ONITIRI REPRESENTATIVE SPEAKS WITH SOKOTI ON HOW THEY SHOULD JOIN HANDS TOGETHER

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 16 жов 2024

КОМЕНТАРІ • 50

  • @BamideleMathew-tg6pe
    @BamideleMathew-tg6pe 4 місяці тому +1

    Oro omugo gbaaaa lo njade lenu okunrin yi.

  • @Ibo22272
    @Ibo22272 4 місяці тому

    Baba mi sokoti you are well done sir,Yoruba people need our own nation not regional, regional can not work in Nigeria awusa and fulani they will still say we are one nation so they can still dey do bad things like killing our people in farm killing our farmers, but our own nation dey can do such of things again because we will have our own rules and regulations to secure our own country

  • @samueldayoenimola
    @samueldayoenimola 4 місяці тому +4

    Oga sir se ile Abuja wa je ile yoruba teni ki won lo. se emo pe gbogbo ohun ija te ri yen duro fun ti orile ede yoruba.

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 4 місяці тому +2

      Ni wọ́n fi di ìhámọ́ra ogun lọ sí ilé ìjọba ni secretariat? Ṣebi ijoba àpapọ̀ ló ń control army?? Ṣé bí wọ́n ṣe ń gba orílẹ̀ èdè nìyẹn.. Wọ́n kàn fẹ́ fi èmi ara wọ̀n ṣòfò dànù.. Oko ìparun nii àwọn Onitirí ńko wọn lọ..

    • @sokotitv1737
      @sokotitv1737  4 місяці тому

      Okayyyyy

    • @sokotitv1737
      @sokotitv1737  4 місяці тому +1

      ​@kehinthanks my brother ejosephkashimawo9410

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 4 місяці тому

      @@sokotitv1737 Baba Ṣokotí, àwọn Awólọ́wọ̀, Azikiwe, Balewa, Ahmodu Bello tí wọ́n gba ominira kúrò lọ́wọ́ Britain kò kó ogun àti òun ìjà jọ now. Baba Awólọ́wọ̀ kó ẹgbẹ́ jọ ní wọ́n sì dúnadura pẹ̀lú ijoba ile Geesi ni.. Àwa ti a jẹ́ Yoòbá yìí gbogbo wa la mọ̀ pé orílẹ̀ èdè ni wá. Kii se Onitirí ló ṣẹ̀ṣẹ̀ má wí ìyẹn fún wa.. Gbogbo wa là mọ̀ pé a lẹtọ sì self-determination lábẹ́ òfin UN. Ṣùgbọ́n kii se ọna ti àwọn Onitirí gbée gba yẹn rárá.. Kódà gan akitiyan àwọn bàbà Akintoye kò fi ìlànà kzn gbogì hàn láti gba ilẹ̀ Yorùbá.. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ kan ń kígbe lórí Social media: "Yorùbá Nation now" ni.. Àgbá òfìfo lásán-làsàn.
      Èmi ná tí wí bẹ́ẹ̀ rí.. Ṣùgbọ́n mo ṣàkíyèsí wípé gbogbo àwọn tí wọn nse asiwaju wá yìí kò ní ìlànà kankan rárá ju pé ká kan máa wípé a fe gba Yoruba Nation lọ.. Báwo là ó ṣe gbaa?? ni ìbéèrè tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ kò ì tíì dáhùn bí ọlọ́pọlọ àti èyí tó yanjú rárá àti rárá. Ẹ má wo ràndánràndán tí irú Abẹli rọra bu òkèlè yẹn ńwí.. Gbogbo agbára tí wọ́n nlò yẹn ìgbésẹ̀ àkókò ni pé kí wọ́n parapọ̀ láti béèrè fún àtúntò lọwọ́ ijoba wa gbogbo àti ti àpapọ̀ pelu awon asoju ni ilé Ìgbimọ̀ Aṣòfin apapo méjèèjì pẹlu Ààrẹ Tinubu pé ká ṣe àtúntò.. Àwọn na si gbodo kó ipa láti ṣe nkan tó ṣe rí sì ilẹ̀ Yorùbá.. Ti wọ́n bá ní aṣepọ̀ pẹ̀lú British government nípa àtúntò na yóò tún ní ìtumọ̀ díẹ̀ láti fi yé wọn pé àwọn ológun ni wọ́n da eto ijoba ti a gbà lọ́wọ́ wọn rú tí wọ́n wà gbé èyí tí a ń lò yìí lé wa lọ́wọ́ tó fi ìran Yoòbá sínú ìgbèkùn.. Iyán wa ti di àtúngún ọbẹ̀ wá sì ti di àtúnsè.. Ọlọ́pọlọ pípé là gba pe ọmọ Oótú Yorùbá jẹ́ kii se ìdojútì àti radaràda tí wọ́n ńṣe yẹn. . Ní pàtàkì awon Onitirí.. Wọ́n ńṣe bí ẹni pé wọ́n ó tiẹ̀ mọ òun tiwọn nṣe rárá.
      Àwa nìkan kọ́ la wà nínú Nigeria now?? Ẹ̀yà orisirisi ló wà níbẹ̀..

    • @stephenmichael9148
      @stephenmichael9148 4 місяці тому

      ​@@kehindejosephkashimawo9410Iru Atunto Wo Ni E'nso?

  • @BamideleMathew-tg6pe
    @BamideleMathew-tg6pe 4 місяці тому

    Dupe Onitiri has captured and brain washed them through her power of darkness. They have been possessed and need spiritual deliverance.

  • @dettoldettol586
    @dettoldettol586 4 місяці тому

    Oloriburuku ni Sokoti, alatenuje ni. Gbogbo yin patapata ti e ta wa fún oloselu. E ma sofo tọmọ tọmọ yin ni.

  • @samueldayoenimola
    @samueldayoenimola 4 місяці тому +3

    Nibo lema fi oju si ti Onitiri be wa gba.

    • @sokotitv1737
      @sokotitv1737  4 місяці тому

      I don't answer a fool like you

    • @stephenmichael9148
      @stephenmichael9148 4 місяці тому +3

      Sokoti Koki Nduro Si Onaa Kan. Omo Eyin Tinubu Ni Sokoti. 👌.

    • @kehindejosephkashimawo9410
      @kehindejosephkashimawo9410 4 місяці тому

      @@stephenmichael9148 Tinubu yẹn wá ńkọ́? Ṣé Ibo àbí Hausa a bí Fulani ni? Ṣebi ọmọ Yoòbá ni?? Ẹ̀yin ta wá lo yẹ kí bàbá Ṣokotí dúró sí??Ṣé lẹ̀yin Peter Obi ni? Nigbati 90% to 100% wọn dúró lẹ̀yin ' ọmọ tiwọn.. Wọ́n á wá máa wí fún yín pé ọmọ tiyín ò daa
      . Akudunnu àti dàdàndidín ara yín ẹ ó máa tẹ́tí sì wọn.. Ṣé àwọn ìyẹn fẹ́ nífẹ̀ẹ́ ilẹ̀ Yoòbá ju ọmọ Yoòbá lọ ní..???

  • @oyelamijanet7163
    @oyelamijanet7163 4 місяці тому

    BABA SOKOTO, E TI GO JU. AI NI LAAKAYE PO FUN YIN.

  • @johnaugustus1979
    @johnaugustus1979 4 місяці тому +4

    My brother Sokoti. If you are educated, which i don't think you are 100%. I want you and all Yoruba to understand the main problem withng Yoruba land. The old lying BABAs calling themselves leader doesn't want to allow the youth to rule. Now. Sokoti doesn't understand and many what is called SOVEREINITY . It is the power that you have as a Yoruba to claim and you don't need anybody to give you. Again, more than 5 Million Yorubas signed a refrendum that shows we don't want to be called Nigeria again. Mr Sokoti as a Yoruba, you don't need United Nation to tell you whi you are. There are many countries that are not even up to 2 Million. The mentality of most of you has been program to beleive that only Mr Akintoye and my brother Chief Sunday Igboho that can take Yoruba freedom. Anything you want to do now, you need document. That is where our more than 5 Miklion refrendum that we all signed is with Mrs Modupe Onitiri and she was presenting this document to every Nation that we Yoruba have prove it. It will take time to convince my brother Sokoti and others.

    • @sokotitv1737
      @sokotitv1737  4 місяці тому +2

      Thanks, you don't need to convince me, I am not part of what you believe, you can stay in your own line, all we want is Yoruba independent, so follow up your way and let be be on my own way, thanks and God bless

    • @AKANDE.Kolawole
      @AKANDE.Kolawole 4 місяці тому +2

      But why did united nations didn't talk when Nigeria soldier arrested some of your men in Ibadan

    • @elizabethodelola4121
      @elizabethodelola4121 4 місяці тому

      All Yoruba Nation people signed the petition. Not only Ominira people. I and my people are part of it. No point.

  • @modupesonubi2350
    @modupesonubi2350 4 місяці тому +1

    I knew Mr. Abel working from Walmart in America

  • @samueldayoenimola
    @samueldayoenimola 4 місяці тому +2

    Ati da duro gege bi orile ede. Se erope ti eba se referendum Fulani ma jeki elo.

  • @OyeyemiSalau
    @OyeyemiSalau 4 місяці тому

    Eku eto baba sokoti
    Awon eleyi o mo nka ti won nse
    Igberaga lonse dupe Onitiri
    Kofe gba fun oga e
    Okan fi wahala si aye awon eniyan ni
    Awon to wa ni nu iti mole nko kini won se si
    Awon eletan ,Kosi opolo Lori okunrin yi rara

  • @allstars6443
    @allstars6443 4 місяці тому +1

    IROLABI IROTIRI MODUPEIRO

  • @Mary-tz9fz
    @Mary-tz9fz 4 місяці тому +2

    TALO NI IYA WERE DUPE ONIDIRI ONIRO APANIYAN ATI MUMU ABEL ERU FULANI ODE LASAN LASAN WON FI ETAN AGABANGEBE PA SAIDI OMO BUTTER WON PARO PE OJE MOJELE WON KAN JEKI OMO OLOMO JEYA YORUBA NATION LASAN ORI RE MA SE IDAJO TI KO LANU FUN GBOGBO YIN NI AGBARA OLORUN OBA AMIN 🙏

  • @IsaacSangodele
    @IsaacSangodele 4 місяці тому

    Hi my God that guy has no sense at all. He doesn’t have a clue to what he is saying. I love you so much sir. You’re very intelligent far, far , more than that guy. They’re very, very stupid people. I like your comments to the guy.

  • @modupesonubi2350
    @modupesonubi2350 4 місяці тому

    Baba sokoto tell them to go and face Fulani not Ibadan secretariat God bless you abundantly and your family we love you Baba Sokoti❤

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 4 місяці тому +1

    🤣😂🤣😂😅 Ń ọ̀ mọ̀mọ̀ lè rẹ̀rín oooo!!!

  • @ayenim.a1657
    @ayenim.a1657 4 місяці тому +1

    Oloselu ni man yi. Odale ati oniro. Eyin gan le fe ta eje awon to ti gbaa sile.
    O ti gba owo eje. Aga ati aye ti o wa si ti fi han. O yato pupo si bi a ti se mo e tele nigba ti o bere.
    Olohun a da oo..

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 4 місяці тому

    Abẹli rọra bu òkèlè ìyàn ń tán lọ làwo, Abẹllì rọra bù òkèlè.. 😅😅 Orin tí ẹ fi parí rẹ̀ yẹn gan tún dùn. Ara oun tí mo fi like eyin ọmọ Ìbàdàn nùu.. Sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ ni gbogbo yín. No dull moment. Mo bá ẹnìkan náà gbé ilé ni London to jẹ́ ọmọ Ìbàdàn ni ọdún mẹ́wà sì méjìlá sẹ̀yin... Ó lè sọ̀rọ̀ fún wákàtí méjì lai dànù dúró, nípa orisirisi nkan. Tí máa máa rẹ̀rín títí.. Òun na a tún rẹ́rìn.. Wọ́n dàgbà díẹ̀ ju mi lọ.. Nígbà tó yá ni wọ́n ni àwọn n padà sí Ibadan.. Nígbà tó jẹ́ wípé ìyàwó wọn ò fẹ́ wá join wọn.. Ti ọmọ nà sì wá ní Nigeria.. Mo sìn wọn dé Airport nígbà náà.. A kàn nsọ̀rọ̀ a nrẹ̀rín lọ ní títì.. Driver cab to gbé wa jẹ́ bi Indian tàbí àwọn Asian apá ọ̀dọ̀ wọn yẹn ń wò wá láti inú mirror.. Nígbà to jẹ́ Yoòbá là nsọ, t'òun ó sì gbọ́ un tá ńwí.

  • @owoniyiogundipe4999
    @owoniyiogundipe4999 4 місяці тому

    Haaaa...Ile yoruba...Emir abi Obaaa😂😂😂😂

  • @joyceolusola8549
    @joyceolusola8549 4 місяці тому

    Akindanidani NI AWON ti ba tun BERE fun Regional govt.because we have practice Regional and it was destabilized. We need total Yoruba Nation.
    E LO so fun Baba yin ko lo GBA OKU ADOGAN ALFA ADEORIOKIN LOWO BABA Tinubu govt

  • @Bjponda1
    @Bjponda1 4 місяці тому

    Sebi dupe dagboru ti GBA orile ede DRY, ki lo tun ku, awon oniyeye ale Amuda, kini onitiro mo nipa Country? Gbogbo awon omo n onitiro afoju ati aditi ni won.

  • @lexycool
    @lexycool 4 місяці тому

    Mr Sokoti I don't think you need to stay so long to speak with this person . He know nothing about what he is saying.

  • @OyeyemiSalau
    @OyeyemiSalau 4 місяці тому

    Eyi to ye ki won ma be ijoba
    Won tun npa iro
    Kati Kati ni won nso

  • @AysteveAworetan
    @AysteveAworetan 4 місяці тому +1

    Orisirisi were lowa labe orun

  • @oyelamijanet7163
    @oyelamijanet7163 4 місяці тому

    AIKAWE YI MA JEYIN NUYA O.

  • @olufelabarber7795
    @olufelabarber7795 4 місяці тому

    Dangerous proposal

  • @OlarenwajuMosesAderonmu
    @OlarenwajuMosesAderonmu 4 місяці тому +2

    ABEL TO NGBE USA, TI NSE ỌMỌ LEHIN DÚPẸ́ ONITIRI, GBA 2.5% PELU IGBIYANJU É LATI TA ÈGBÉ FUN AIYE. ỌPỌLỌ KU DI KATO.

  • @adebayoadesola9408
    @adebayoadesola9408 4 місяці тому

    You will canvas till kingdom come. Olote ni iwo Sokoto you are not working for Yoruba nation at all.

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 4 місяці тому

    Ṣé àgbàlagbà náà ni ẹni tó pè yín yìí ṣá??

  • @banjiadebayo-tz7km
    @banjiadebayo-tz7km 4 місяці тому

    NOWAY TO JOYIN BABA AKINTOYE AGAIN ONITIRI IS VERY STUPID WOMAN THEY SHOULD NOT ALLOW PLESA

  • @GraceKuteyi
    @GraceKuteyi 4 місяці тому

    Hmmmmmm really?

  • @titilayodina1943
    @titilayodina1943 4 місяці тому +1

    Omo go won ni ko ma ku, awon won yi ma go o. This man is very foolish o, it's a pity Onitiri doesn't have wise followers o.

  • @modupesonubi2350
    @modupesonubi2350 4 місяці тому

    Babasokoti this man is sick he is doing security job in America has him to come back home Nigeria with his family Were People Babasokoti don’t listen to baba were egbon Dupe Oniro Omo were Onitiri Itire surulere

  • @safetydomain6861
    @safetydomain6861 4 місяці тому

    Awon omugo eranko ni awon ti won ro wipe awon le tan omo Yoruba. How many of the know Onitiri apart from seeing her on social media? They think if they can convince people to join them, it may be possible to convert their lies and cover up to a reality. Awon Onitiri, Black Lion, Ijinle, Ajakaiye and Wale Ali ti gbo Yoruba nation! What an insult

  • @jamesitaronbi3889
    @jamesitaronbi3889 4 місяці тому

    OYE KI ONITIRI PELU ARE MA BO SILE BABA WON.AWON OLOFO

  • @jamesitaronbi3889
    @jamesitaronbi3889 4 місяці тому

    Shokoti kosi Oro OLOGBON LARA ohun baba YI nso ki onidoti jade dits