ILE IFE NI ORISUN

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 24 січ 2025

КОМЕНТАРІ • 42

  • @Ayanwola1
    @Ayanwola1 Місяць тому

    Aare composer😊😊😊😊😊❤❤❤

  • @oladejimu-oz4kk
    @oladejimu-oz4kk Рік тому

    Beni lahji abas baba ododo oro ❤❤❤❤ oluwo ese pele oo

  • @oladejimu-oz4kk
    @oladejimu-oz4kk Рік тому

    Baba wa oluwo ese pelepele lori itan yoruba tori igbeyin alabosi kiidara

  • @SereabramSetlhako-pu2gk
    @SereabramSetlhako-pu2gk Рік тому +6

    Ewo oro oluwo ki se lasan won fefi mada ile yoruba ru awon ota yoruba ni won nfi oluwo sise lati ma so isokuso gbogbo re ye wa patapata won nfi esin islam boju ni lati da ile yoruba ru ni oju loma tiwon gbehin lagbara olorun oba

  • @yettiefash7425
    @yettiefash7425 Рік тому +2

    Oluwo knows that Tinubu time will run over in 8years if he is lucky then back to square one. Yoruba being on its own is the answer.

  • @ShemLogan
    @ShemLogan 8 місяців тому

    E fi were sile ko s'oku Iya re Bo se wu. TO ba wu ko sun je.

  • @jidejohnson9449
    @jidejohnson9449 11 місяців тому

    You are loud and clear Aree

  • @olamilekanayodele6177
    @olamilekanayodele6177 Рік тому +2

    Kí Ọlọrûñ bâwâ salekun ęmí gigun fun Ôlùkọ Àgbà wâ
    The òñíbôdè îlé Yoruba

  • @ojoyekini6011
    @ojoyekini6011 Рік тому +2

    Aare Laji Abass , opolo re ko ni. doba OLORUN a je ki o ma ju e se.
    I am a student of History and I have learn more from your programs
    I prayed that the Almighty Allah will bless you with more wisdom to continue this program.
    It shall be well with you.

  • @abdulwahab501
    @abdulwahab501 Рік тому +1

    Àrẹẹ Òpìtàn Ẹmi yìn yìò gùn pẹ̀lú idẹra. Àṣẹ Èdùmàrè. Òlùwo Rashidi nwà ojùrèrè àwọn Fùlani àti Àrabò làti màá gbà Òwò lọwọ wọ̀n! Àtipè kò fẹ̀nì ìtẹríba fún Ọ̀nìrìsà Ìle Ìfẹ àti Ilẹ̀ Yorùbá. Pàtàkì jùlọ nípè àwọn àgbàlagbà òlòtitọ kòsì mọ ní Ilẹ̀ Yorùbá àti Òlòsèlù. Àdàà Ìlú rù ni Rashidi Ìlú Ìwò nítorí kí se Ọmọ Òjùlòwò Yorùbá Àtàtà! Ẹyin Ọmọ Ìwò Àtàtà ẹtàjí lójú Orùn Ọba Rashidi nbà nkàn bọ o.

  • @helenadeogun6649
    @helenadeogun6649 Рік тому +1

    Eku ise ati itan ti oni ARE OLODUMARE yio ma ti yin leyin awa na yio si Maa se iPa Tiwa
    Ile Yoruba a gbe wa o

  • @OwolawiDavid-dp1ke
    @OwolawiDavid-dp1ke 11 місяців тому

    Weldon sir

  • @SereabramSetlhako-pu2gk
    @SereabramSetlhako-pu2gk Рік тому +3

    Aree you are too much mo gbe osuba fun yin aree you are God sent to yoruba land pls pls pls leave that guy oluwo alone is a novice in yoruba land so continue your work God will bless you for yoruba land

  • @adewumiifeoluwa1356
    @adewumiifeoluwa1356 11 місяців тому

    Laji Abbas you no go kill person “ k’eya mo asiko t’eyan o bere Ibere lowo kabiesi”😂😂😂

  • @theophilusayantokun5581
    @theophilusayantokun5581 Рік тому +1

    Imukumu ati ifakufa n yo Oluwo lenu.

  • @olorunfemifemi3897
    @olorunfemifemi3897 Рік тому +1

    ❤❤👏👏👏👌👊 ọlọrùn àmá tìọ́ lẹ́yì 🙏

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 Рік тому +1

    🤣😂🤣😂🤣🤣 Baba Oluwo joko won fi apoti tise won nju 'pa ju 'se pa alo. Eni ti ko lo ile iwe gan mo wipe Iwo kii se ilu isembaiye bi Oluiwo se wii yen.. Awon kan si joko sibe won ngbo aalo apamo.... Itan ti baba Oluwo n so dabi enipe won fe moomoo da ile Yoruba ru lati maa fa ipinya laarin awa Yoruba titi de Ile-Ife.. Eleyi buru jai

  • @MikhailAwolowo-zm7fr
    @MikhailAwolowo-zm7fr Рік тому +2

    Aare Laaji Abass, mo gba ni adua wipe ki Olohun jeki e ri ile yoruba daabobo ile yoruba ju bi Bashorun Yamba se ri daabobo lo.

  • @afolabioduwole559
    @afolabioduwole559 Рік тому +1

    Omo Ale ni Oluwo ni ile Yoruba

  • @comfortadeleye128
    @comfortadeleye128 Рік тому +2

    Why did this man do much hate ONI by extension ILE IFE we still have the record of all the fake stories he told his Canadian wife he must be stopped
    I thought he first said he’s from Mecca (LAMURUDU or NUMURUSU)

  • @jidejohnson9449
    @jidejohnson9449 11 місяців тому

    love

  • @davisawoniyi2116
    @davisawoniyi2116 11 місяців тому

    Thanks

  • @AdelekeRidwan-g3i
    @AdelekeRidwan-g3i Рік тому

    😂😂😂 baba don high Nii

    • @Topdigitc
      @Topdigitc Рік тому

      Kwarai! His royal HIGHness.

  • @williampowers2109
    @williampowers2109 Рік тому +2

    Awesome 👌 👏 👍 😅😂

  • @Topdigitc
    @Topdigitc Рік тому

    Oluwo Rasheed, his royal HIGHness.

  • @eki1
    @eki1 Рік тому +3

    Ni ABD atijo,A-aja,B-bata etc, sugbon ko si Oro ti o bere pelu U,ni nwon Fi ni U-uku-uku,lol. Okunrin kan ti o we lawani pelu slate ti nwon nlo ni ile-kewu ni nwon pe ni uku-uku.
    One Ijesha man said " o WI e si ede Yoruba ko bere pelu U, ushu,uku,ule siko?lol.( yam, stomach,house).
    E kuu ise opolo Are Opitan.

  • @tiiluolamide4573
    @tiiluolamide4573 Рік тому +1

    Even the name Adekola is not long in d history....... Check the name history.... Is also traceable is less than 700yrs nd if Adekola telu established ìwo how manage of ìwọ?

  • @azeezbabatunde9542
    @azeezbabatunde9542 Рік тому +2

    Fantastics 😂😂😂 The baapitan of Iwo land.

  • @comfortadeleye128
    @comfortadeleye128 Рік тому

    He wants to turn himself to the leader of all Yoruba kings

  • @jimohnasiru819
    @jimohnasiru819 Рік тому +2

    Eku ojumo sir.

  • @BD-nn3fq
    @BD-nn3fq Рік тому +3

    Oluwo should be removed . He his a traitor

  • @davidtumiariyo
    @davidtumiariyo Рік тому +2

    Aare Laji Abass , are you not the one who promoted Oluwo online from the beginning? See the man you promote. He is the same man misbehaving online. However, it's not your fault for promoting and defending Oluwo oooo. Eefin ni iwa. Ida ni yio pe ara re ni eru. A lot of people are saying Oluwo is a disgrace to Yoruba Royal stood. Well, kudos to you , though Aare Laji Abass

  • @kolaolayenju2761
    @kolaolayenju2761 Рік тому

  • @dettoldettol586
    @dettoldettol586 Рік тому +3

    If u want to poison your life spend your time with ignorant people like Rasheed Oluwo Ọba awọn Dindinrin.

  • @AdelekeRidwan-g3i
    @AdelekeRidwan-g3i Рік тому +2

    Oba iwoo don’t like ooni that’s the fact

  • @comfortadeleye128
    @comfortadeleye128 Рік тому +1

    AARE EKU ISEO ESIKU AGBALE AWA OMO KOOTU OJIRE ,KINI WAHALA BABA OLUWO? SE OFE DALE YORUBA RUNI . Anyway it’s not his fault I hope RAUF will be listening to all the rubbish coming out from the mouth of this man who want to sell his race to Fulani

  • @Tm_tino
    @Tm_tino Рік тому +3

    Oluwo is presenting the stupid script of the fulani caliphate to us by trying to destroy and rubbish the Yoruba history

  • @holarlush6452
    @holarlush6452 Рік тому

    I hate to Dey see this man talk
    😡😡😡
    Like is dragging Yoruba go back..