ITAN IJINLE

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 19 вер 2024
  • Fún alaye àti ibere nípa Itan Yoruba ẹ kan si wa +2348023687432

КОМЕНТАРІ • 18

  • @yoruban8374
    @yoruban8374 4 місяці тому +9

    Laji abass eku eto, yio yẹn yín o, a dẹ ku igbaradi silẹ fun "Itan Àwa Yorùbá" ti yio w'aiye lai'pẹ. Ọjọ ayọ ni yio jẹ l'aṣẹ Olódùmarè

  • @yunusobashola9595
    @yunusobashola9595 4 місяці тому +5

    Aare God bless you so much sir. you're doing a great work for our tribe 👏

  • @RasheedatAkinloye
    @RasheedatAkinloye 4 місяці тому +1

    A ku imura.
    Ibi ko ni sele si enikeni siwaju ati ojo ati leyin ojo naa .
    Ile ise itan ile yoruba ko pare ,yoo ma lo soke si ni lase eledumare.
    Olorun ko ni fi iku ojiji pa yin lase eledumare.
    Emi yin yoo gun ,E ko ni saisan lase eledumare

  • @oladimejimichael-w1o
    @oladimejimichael-w1o 4 місяці тому +6

    Eku eto sir

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 4 місяці тому +3

    Bẹ́ẹ̀ni... Èdè Gẹ̀ẹ́sì tí ń sá wọ inú èdè wa.. Nigbati mo nsọ nígbà kan pé mo máa ngbe rechargeable lantern lé ná,,, ẹnikan tó ńgbọ́ mi bú sẹ̀rin nítorí bí mo ṣe lo èdè Yorùbá yẹn.. Nitoripe mi ò wípé mo ń "charge"....Lara bí èdè oyinbo ṣe ń sá wọ inú èdè wa nìyẹn..

  • @apalarababatunde7491
    @apalarababatunde7491 4 місяці тому +3

    Sir, the igodomigodo is from the lineage of oranfe not obatala sir. And olowo arere is not a son to oduduwa but orunmila. Sir you are missing the generation together sir. Please do the corrections God bless

  • @OlajideAjigo
    @OlajideAjigo 3 місяці тому

    Your historical analyses take into cognizance of aborigines which in my opinion is the best account. Ori yin a ma kanke.

    • @OlajideAjigo
      @OlajideAjigo 3 місяці тому

      Yemen is actually the aborigines of Arab and history has justified that 👍

  • @ShemLogan
    @ShemLogan 4 місяці тому +3

    Ekun oko Aaŕe kakaofo Gani Adamu Logun ojo o.

  • @raimiomoh7599
    @raimiomoh7599 4 місяці тому +2

    Una for just tell us say na Ile ife na world started from 😅😅

  • @adebayobambe4885
    @adebayobambe4885 4 місяці тому +1

    You are God sent. The evidence proves it all

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 4 місяці тому +2

    E ku ise takuntakun

  • @raimiomoh7599
    @raimiomoh7599 4 місяці тому +1

    Sir please who born oduduwa? Person wey born for ife no dey exist?

  • @crownedking2567
    @crownedking2567 4 місяці тому

    Aare, please Ondo,Ugbo,Ekiti,Ilaje 1:13:00 do not have a similar language with Beni, nothing similar to our language with the Bini,I live and I have friends with some Binis and we cannot slightly hear or understand each other except Pele which they always say to greet us the Yoruba who they meet and they say it to themselves too

  • @apalarababatunde7491
    @apalarababatunde7491 4 місяці тому +1

    Sir. Oduduwa ateworan is really. The Oduduwa olofin is different from Oduduwa atewonran sir. Point of correction. The same way we have sango two versions, obatala two versions and obalufon as well please 🙏 do much of research sir. Oduduwa ateworan is of ufe odaye , Oduduwa olofin is of ufe akanlubebe. Please sir correct your narrative in that aspects . There is two versions of Oduduwa sir.