Hmmmmm... Awikonko ẹku isẹ ọpọlọ o, Ọlọ́run á dé isẹ yín l'ade Àmín. Báwo ni kò bá ti dùn tó kani àwọn asiwaju wa nílè Yoruba mọ ewu ti o wà nídìí ọ̀rọ̀ yi ni kí wọ́n sì parapọ̀ tako erongba àwọn ọmọ àlè ọmọ Fulani wọ̀nyí ni, kò bá dára pupọ.
Saudi Arabia is the country that is even holding boxing events most now,, those people are moving forward while the Yoruba muslims are going backward.. is that not stupidity?.
They want to implement sharia court, simply because of those Alfas that failed to take care of thier wives and many ELEJAs are now doing hook up and it's paining all those ALFAS ni now.
Brother mi Awikonko i knew the first programme you did was just etan, 😂😂, you yourself have seen it that it will not work,, that's why i said it that if we allow them to implement that court, in future it will brings more trouble to Yoruba race if you remember sir., and i said HA WE ARE NOT AN ARAB NOW. so we Yorubas don't need SHARIA court in the wide whole Yoruba land. Won a pa kisa si omo Yoruba lara..
Ojogbon Awikonko, Ewi re o. Sugbon ma so afikun kan tabi omiran. Gbogbo nkan ti e ka jade ninu Sharia law yi, ni ati ni provision fun ni nu ofin to wa ni orilede wa. Papa Julo ni Ile Yoruba. Gbogbo eleyi ti a nri yi, je ikan ninu awon ona ati mu Ile yoruba leru si abe awon larubawa ni. Lakawe, ko ki se gbogbo eyan ni o ma gba esin Islam tabi gba iwe won Quran pe iwe olohun ni. Iyen tun mo si pe eni to ba ni igbagbo miran to yato si Islam... pipa ni, bibe Lori ni, gige lowo ni. And ti nkan yi o ba sele ni kiakia, a si pa pa sele later ti won ba ti po ninu population area tabi region ti won ba wa. Eyi ti o nfa gbogbo wotowoto to nsele nisin, nipa pe won fe ma po si. Ni pa eyi ni won ma fi gain sentiment ati support fun awon nkan ti won gbe wa sile Yoruba yi. Ona miran ni pe won o fe eni tio je musulumi ko gbe papo pelu won bee won o fe ki eni to ba ti wa pelu win ko kuro boya inu won dun si on ti won se or not. Ofin ti won da sile lati cage, cleanse or wipe out awon eya ti o ba ti gba ti won ni. Ti asoju e a ma dahun si awon ara ita ni. Ti awon eyan won oni je eyan pataki loju won ayafi awon ara won (clerics, teachers, sultan ati bebe lo). Legbe keji, ni wipe won ngbe eleyi wa ni atari pe oju awon eyan ti nsi si otito esin tabi ka so pe aburu ti won fi esin nse fun awa eleya dudu. Olaju si ti ngboro de bi pe Yoruba ti mo ra e ni Yoruba osi ti n gbero bo se ma daduro. Ti awon eyan asi ma fi owo re fun. Ti o ba si daduro, a di wipe ko ma bere fun eto e boya nipa oja ti ta tabi omiran.. lapere, osese ki iye eyan to ma ma losi mecca din ku ti idagba soke ati ilosiwaju bade ba oun ti Ile wa ni atara olaju to nsele yi. Eyi pelu nkan ti o n fa ki awon ara ibi maa gbogbo ipa lati ma gbe nkan orisirisi ti ko ba ilana Yoruba mu wa fun ni ona kona. Bi etise so, awa ti ni ilana ti wa to poju osuwon ki Islam to de. Be naa ni wipe gbogbo ofin Sharia yen ko da Lori nkan mi biko se pe fun fifo eya mo ati mimu leru fun awon larubawa. Ewo, China, America, Japan, Brazil, UK, France are all examples of places ti economy won wa ok. Even though awon die ninu won allow Sharia ni ilu won, they made sure wipe ofin ilu bori Sharia law won. Won o de bi eyan kan re ninu gbogbo awon ti won nsoju Sharia ninu awon ilu to faye gba ko dajo bibe Lori tabi gige lowo... Mo tu tun so pe awon ilu to fi aye gba Sharia ninu awon ilu ti mo daruko like yen, o fi aye gba bibe Lori tabi gige lowo. Nitori pe won ma n da wahala jurisdiction sile ni... in other words confusion, because awon to gba late fi nse oju aye nipa pe won ba awon ilu Musulumi se owo ilu si ilu. Iketa nbe nope, ti awon ba se nkan buruku ni agbegbe kan, ti awon eyan ba koju si won... ibeere mi ni pe ki lo le da awon eni duro lati so pe gbogbo eni ti o accuse eyan lo wa anti-islam or anti-muslim se iyen o tun ni di nkan ti a mas mu ija ati ede aiyede wa larin omo iya si ran won? Ibeere keji, ti Oki tabi iyawo baje elesin kan tabi omiran. Ti oko tabi iyawo mejo losun ti court sharia si dajo ni ilana ti won latari pe won ti ni court. Nje won ni se be pa awon eya mi ran tan tabi sowo da la bo ara. Ti asi ma le awon eyan kuro lagbegbe. Lona mi ki eyan se, ko gbe losi normal court, ko si ma beere pe ko gbe ohun lo si court Sharia nipa pe oun je elesin musulumi, ti eni keji si je elesin omiran? E do eyi kogban eyin omoran Ile Yoruba. Mo wi yi naa o, baba Awikonko.
Yoruba’s iṣẹ̀ṣe courts alone, governor Seyi Makinde will not have enough space in his Oyo state to accommodate them. Apáa Ṣèyí ò níí ká yọ́npọnyọ́nrin. They think Yoruba brain works the same way as the one-way Hausa-Fulani does ni? Wọn ò ní léè kóo tán. Àwọn dìndìnrìn gómìnà tó fẹ́ ta ilẹ̀ Yoruba gba ipò ààrẹ ní PDP!
They drink more Alcohol in the North than in the south, it's not a hearsay I lived there and went to the school there for almost 13 yrs. I laugh all the time when they come out to denounce alcohol, I liked Tinubu with the new distribution of Taxes that is going on now with that move the North will sell Alcohol at the end with a big store that the south will probably travel over there to buy whole sales cause their border is open for various alcohol to flow in from neighboring country which is not available in the South. The truth is they are hippocrates, they also drink at the clubs and drunk like fish that swallow too much water. We shall see how this ends, I don't know why they are threatening the President over their bad behaviors.
If they want shariah, traditionalists will alao setup there courts and enforcement and Christians will also do same. This is not homogeneous religious tribe
THIS IS A GAMEPLAN BY FULANI TO CONQUER AND ENSLAVE YORUBA. ASETANI SOKOTO IS BEHIND THIS PLOT HAVING FAILED TO INSTALL HIS PREFERRED CANDIDATE AS ALAAFIN OF OYO.
This man you are a double mouth human being your first program you said you can not go against the sharia that is normal for them to implement it but now you have changed your mouth again Mr jomijoke
Nothing like double mouth what he is trying to pass across is in the Nigeria 1999 constitution which recognized the Sharia court in Nigeria. Anyway he received a lot of messages about that and still came back and explained but still yet you are not satisfied. Oga ooo
Thank you Awikonko. I like ur boldness on this issue
Well said,Awikoko
Baba awikonko this program make me laugh too much oh god in heaven.
Love ur program
Hmmmmm... Awikonko ẹku isẹ ọpọlọ o, Ọlọ́run á dé isẹ yín l'ade Àmín. Báwo ni kò bá ti dùn tó kani àwọn asiwaju wa nílè Yoruba mọ ewu ti o wà nídìí ọ̀rọ̀ yi ni kí wọ́n sì parapọ̀ tako erongba àwọn ọmọ àlè ọmọ Fulani wọ̀nyí ni, kò bá dára pupọ.
Awikonko you make me laugh.
Okare omo oko yoruba...Eso fun won ,kokoko laranfa aditii...
Baba awikonko this lrogtamake laugh too much oh god in heaven
NO ISLAMIC SHARIA LAW IN YORUBALAND
Awon Oloriburuku apaayan. Emi eniyan o jo won loju paa.
Saudi Arabia is the country that is even holding boxing events most now,, those people are moving forward while the Yoruba muslims are going backward.. is that not stupidity?.
They want to implement sharia court, simply because of those Alfas that failed to take care of thier wives and many ELEJAs are now doing hook up and it's paining all those ALFAS ni now.
Brother mi Awikonko i knew the first programme you did was just etan, 😂😂, you yourself have seen it that it will not work,, that's why i said it that if we allow them to implement that court, in future it will brings more trouble to Yoruba race if you remember sir., and i said HA WE ARE NOT AN ARAB NOW. so we Yorubas don't need SHARIA court in the wide whole Yoruba land. Won a pa kisa si omo Yoruba lara..
Se won fe force awa Christian lati se tipatipa se Muslim ni Abu force isese se Muslim ni
Ojogbon Awikonko, Ewi re o. Sugbon ma so afikun kan tabi omiran.
Gbogbo nkan ti e ka jade ninu Sharia law yi, ni ati ni provision fun ni nu ofin to wa ni orilede wa. Papa Julo ni Ile Yoruba. Gbogbo eleyi ti a nri yi, je ikan ninu awon ona ati mu Ile yoruba leru si abe awon larubawa ni. Lakawe, ko ki se gbogbo eyan ni o ma gba esin Islam tabi gba iwe won Quran pe iwe olohun ni. Iyen tun mo si pe eni to ba ni igbagbo miran to yato si Islam... pipa ni, bibe Lori ni, gige lowo ni. And ti nkan yi o ba sele ni kiakia, a si pa pa sele later ti won ba ti po ninu population area tabi region ti won ba wa. Eyi ti o nfa gbogbo wotowoto to nsele nisin, nipa pe won fe ma po si. Ni pa eyi ni won ma fi gain sentiment ati support fun awon nkan ti won gbe wa sile Yoruba yi. Ona miran ni pe won o fe eni tio je musulumi ko gbe papo pelu won bee won o fe ki eni to ba ti wa pelu win ko kuro boya inu won dun si on ti won se or not.
Ofin ti won da sile lati cage, cleanse or wipe out awon eya ti o ba ti gba ti won ni. Ti asoju e a ma dahun si awon ara ita ni. Ti awon eyan won oni je eyan pataki loju won ayafi awon ara won (clerics, teachers, sultan ati bebe lo).
Legbe keji, ni wipe won ngbe eleyi wa ni atari pe oju awon eyan ti nsi si otito esin tabi ka so pe aburu ti won fi esin nse fun awa eleya dudu. Olaju si ti ngboro de bi pe Yoruba ti mo ra e ni Yoruba osi ti n gbero bo se ma daduro. Ti awon eyan asi ma fi owo re fun. Ti o ba si daduro, a di wipe ko ma bere fun eto e boya nipa oja ti ta tabi omiran.. lapere, osese ki iye eyan to ma ma losi mecca din ku ti idagba soke ati ilosiwaju bade ba oun ti Ile wa ni atara olaju to nsele yi. Eyi pelu nkan ti o n fa ki awon ara ibi maa gbogbo ipa lati ma gbe nkan orisirisi ti ko ba ilana Yoruba mu wa fun ni ona kona. Bi etise so, awa ti ni ilana ti wa to poju osuwon ki Islam to de. Be naa ni wipe gbogbo ofin Sharia yen ko da Lori nkan mi biko se pe fun fifo eya mo ati mimu leru fun awon larubawa. Ewo, China, America, Japan, Brazil, UK, France are all examples of places ti economy won wa ok. Even though awon die ninu won allow Sharia ni ilu won, they made sure wipe ofin ilu bori Sharia law won. Won o de bi eyan kan re ninu gbogbo awon ti won nsoju Sharia ninu awon ilu to faye gba ko dajo bibe Lori tabi gige lowo... Mo tu tun so pe awon ilu to fi aye gba Sharia ninu awon ilu ti mo daruko like yen, o fi aye gba bibe Lori tabi gige lowo. Nitori pe won ma n da wahala jurisdiction sile ni... in other words confusion, because awon to gba late fi nse oju aye nipa pe won ba awon ilu Musulumi se owo ilu si ilu.
Iketa nbe nope, ti awon ba se nkan buruku ni agbegbe kan, ti awon eyan ba koju si won... ibeere mi ni pe ki lo le da awon eni duro lati so pe gbogbo eni ti o accuse eyan lo wa anti-islam or anti-muslim se iyen o tun ni di nkan ti a mas mu ija ati ede aiyede wa larin omo iya si ran won?
Ibeere keji, ti Oki tabi iyawo baje elesin kan tabi omiran. Ti oko tabi iyawo mejo losun ti court sharia si dajo ni ilana ti won latari pe won ti ni court. Nje won ni se be pa awon eya mi ran tan tabi sowo da la bo ara. Ti asi ma le awon eyan kuro lagbegbe. Lona mi ki eyan se, ko gbe losi normal court, ko si ma beere pe ko gbe ohun lo si court Sharia nipa pe oun je elesin musulumi, ti eni keji si je elesin omiran?
E do eyi kogban eyin omoran Ile Yoruba.
Mo wi yi naa o, baba Awikonko.
😂😂😂😂😂😂
baba you dont get it...
Yoruba’s iṣẹ̀ṣe courts alone, governor Seyi Makinde will not have enough space in his Oyo state to accommodate them. Apáa Ṣèyí ò níí ká yọ́npọnyọ́nrin. They think Yoruba brain works the same way as the one-way Hausa-Fulani does ni? Wọn ò ní léè kóo tán. Àwọn dìndìnrìn gómìnà tó fẹ́ ta ilẹ̀ Yoruba gba ipò ààrẹ ní PDP!
Kare omo oko yoruba.
They drink more Alcohol in the North than in the south, it's not a hearsay I lived there and went to the school there for almost 13 yrs. I laugh all the time when they come out to denounce alcohol, I liked Tinubu with the new distribution of Taxes that is going on now with that move the North will sell Alcohol at the end with a big store that the south will probably travel over there to buy whole sales cause their border is open for various alcohol to flow in from neighboring country which is not available in the South. The truth is they are hippocrates, they also drink at the clubs and drunk like fish that swallow too much water. We shall see how this ends, I don't know why they are threatening the President over their bad behaviors.
WHERE IS AARE OPITAN LAJI ABASS? I AM WAITING FOR HIS COMMENT ON THIS ISSUE.
Yoruba kise jagidija ogun ni won fidale si le Yoruba ka saye
Oloriburuku omo ale ni awon alfa Imam sehik mufti Ile yoruba won fe fa wa soko esin jagidijagan
If they want shariah, traditionalists will alao setup there courts and enforcement and Christians will also do same. This is not homogeneous religious tribe
@Damilare_40s. Are you for backwardness? Do you really follow these programs? What exactly do you want? Please explain.