OMO YORUBA GBA'BODE PELU FULANI LATI PA JAGUN IGBAJA NI KWARA N KAN SE ILE YORUBA

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 1 жов 2024
  • OMO YORUBA GBA'BODE PELU FULANI LATI PA JAGUN IGBAJA NI KWARA N KAN SE ILE YORUBA

КОМЕНТАРІ • 79

  • @isaacstrongtower-ws9qm
    @isaacstrongtower-ws9qm День тому +3

    YOUR GOVERNORS ARE SLEEPING .WAKE THEM UP.

  • @mygodisgood-os7ux
    @mygodisgood-os7ux День тому +3

    Àwọn olóṣèlú ati àwọn ọba olóṣèlú tí bá ilẹ̀ Yorùbá jẹ. Olódùmarè ló kún kó ràn wa lọwọ́ báyìí oo😢😢😢

  • @mrscpower6200
    @mrscpower6200 День тому +5

    See now, this is what Sunday Igboho is saying, Fulani is killing Yoruba one by one. May his soul rest in peace, o ma se o. Yoruba need to join hands together now before it is too late for all Yoruba’s

    • @leyoola-xz4ld
      @leyoola-xz4ld 22 години тому

      It is already late my brother,kolori di orie mu loku, many Yoruba are too stupid to be free

  • @ganioloyede9333
    @ganioloyede9333 20 годин тому +2

    Look at those childrens,they have no life.that’s what our Yoruba leaders want for us too in Yoruba land

  • @oe6526
    @oe6526 День тому +5

    These people will conquer yorubaland by 2044 if we continue to cry foul.
    When is areonakakanfo going to stop them?
    Their kabiyesis have all relocated to ilorin; two years ago, I saw some prominent obas fleeing for their lives in knickerbockers and cattles occupying their palaces.
    Maybe that is what's happening now. Very sad!

  • @olaajibola1097
    @olaajibola1097 День тому +2

    It's a pity there are many traitors among the Yorubas when are we going to stop this in Yoruba land?

  • @kintonjosh
    @kintonjosh 13 годин тому +1

    Ariwo sa ni Yoruba mo Pa, so predictable. No action. What a weak tribe we are.
    May your soul rest in peace Jagun

  • @okikiolaokiki5557
    @okikiolaokiki5557 День тому +2

    RIP brother we love you ❤

  • @Praise3-yx9eg
    @Praise3-yx9eg День тому +1

    May the gentle soul of our hero, Chief Akinrogun rest in perfect peace.
    And May the Lord almighty grant his immediate family the fortitude to bear the irreparable loss.

  • @bigmummykofo8447
    @bigmummykofo8447 День тому +3

    It's so sad. May his soul rest in perfect peace. 🙏

    • @handsome-hs5fu
      @handsome-hs5fu 22 години тому

      yoruba you people talks too much. why complaining you gave the man over 10 titles still fulani can kill him. all those beads and crowns are all fakes. RUBISH

  • @isaacstrongtower-ws9qm
    @isaacstrongtower-ws9qm День тому +1

    ARE YOUR GOVERNORS STILL ALIVE ? PRAY FOR LIVING GOVERNORS.

  • @rasaqraji5640
    @rasaqraji5640 10 годин тому

    Yoruba must be ready to fight for their freedom

  • @oluwafemifasusi4518
    @oluwafemifasusi4518 День тому +1

    Awon oba lo n gbabode fun ile Yoruba, they are working against their people because of their selfish interests and most of our people join because of religion and cow business they are doing together it’s a shame that we forget ourselves because of our selfish interests

  • @michealawe4883
    @michealawe4883 День тому +1

    NOTHING PLEASE!

  • @bamideleigbamole8844
    @bamideleigbamole8844 8 годин тому +1

    But what police and other law enforcement are doing to all this fulani cattles reareers killing farmers in Yoruba land, is this country call Nigeria working so ??

  • @omowayefolorunso7555
    @omowayefolorunso7555 День тому +1

    Yeye Dara you are right

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 14 годин тому

    Nkan ti se wa o iya mi mo ki yin ku ise o ohun ti won fe so wa da ni yen ka ma woju oko ka to jeun yoruba ti sonu nitori ijekuje Ole ni gbogbo agba yoruba tan ba ti fun ni egunje ti enu nikan na mo won o ja fun ilu won ti ba ogo yoruba je ohun la se nni ifasehin

  • @abebianike4049
    @abebianike4049 День тому +1

    Awon Fulani ti npa awon olori wa diedie oooo Haa Ogun ti deee

  • @aminatakande9385
    @aminatakande9385 18 годин тому

    They're all ARUNGUN OMO. The western governors

  • @aminatakande9385
    @aminatakande9385 18 годин тому

    They killed the it all

  • @adeolawahab
    @adeolawahab 11 годин тому

    Won gbabode fun akogun ni, awon omo ale yoruba

  • @bolanlekemi6903
    @bolanlekemi6903 17 годин тому

    Eleyi mawa lagbara ooo
    Olorun wa sanu wa

  • @babalolakutedo5592
    @babalolakutedo5592 День тому +1

    🙏🏻🙏🏻🙏🏻🙏🏻🙏🏻🙏🏻🙏🏻🙏🏻

  • @timothywale8055
    @timothywale8055 6 годин тому

    Ibi ti esorosi Yi na loma , ariwo lasan, ojo wo leri ti awon Fulani ki won ma pariwo bayi , titi won mafi se ohun ti won nse , Eyin elo si odo awon Fulani pa eyokan ninu won,ki ewa rii itu tiwon ma fiyin pa

  • @YeboahJob-ok8xm
    @YeboahJob-ok8xm 2 години тому

    Amin Àse waa

  • @ganioloyede9333
    @ganioloyede9333 20 годин тому

    Look those childrens they have no life,that’s want our leaders is Yoruba land want in Yoruba ppls

  • @bunmiodusina-idollor3479
    @bunmiodusina-idollor3479 День тому

    It's so very sad! May his gentle soul rest in perfect peace . Condolences to his family.

  • @bolanlekemi6903
    @bolanlekemi6903 17 годин тому

    Iku aitojo npa awon eyan Awon Oba kosoro kankan Gbogbo won marojo ni iwaju Olorun oba

  • @labakes1917
    @labakes1917 День тому

    We like it …it’s a great enlightenment… great job as always omo oko Yoruba .

  • @JosephAjewole-s4w
    @JosephAjewole-s4w 18 годин тому

    ASIKO OMO LUWABI TI KOJA.

  • @aminatakande9385
    @aminatakande9385 18 годин тому

    AKINROGU OMO OKO OODUA rest in power

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 День тому

    Let all of us Yorubas stop shouting about the Fulanis killing our people on timely everyday , let us beginning to go after them and do the needful. We can see what Iganga people do through Igboho Oosha and themselves, now Igangan is at peace. Yorubas let us wake up and fight our battles ourselves and stop waiting for the government, enough is enough

  • @user-sk4jf1mw4i
    @user-sk4jf1mw4i День тому

    Nothing , they are just self centered

  • @olubunmiukhueleigbe3897
    @olubunmiukhueleigbe3897 День тому

    They are not there because of us,is just for there selfishness

  • @bolanlekemi6903
    @bolanlekemi6903 17 годин тому

    Ko si nkankan rere ti gbogbo won ri gbe se Won kan kowo je ni

  • @aderibigbematthias8646
    @aderibigbematthias8646 День тому

    Gov. Adebayo of Ekiti State

  • @yankeeebony5149
    @yankeeebony5149 День тому

    Sister Daara, Àjẹ ké láàná, ọmọ kú léni, tani kómọ wipé àjẹ àná lópa ọmọ jẹ. Sister mi, Lagbaji is responsible. All this stubborn and heartless religious fanatics. See, these people knows the secret to all the areas, he can be very dangerous and act like a green snake under the green grass..

  • @ArabinrinOyindamola
    @ArabinrinOyindamola День тому

    Rip brother 😭😭 bi ikule opani tode ole pani, gbogbo enikeni togba fun egbon wayi ni agbara edumare koni kije laiye asegun
    Yoruba nation no going back ❤
    Ekuise takun takun ma

  • @Adeotimiyemiye
    @Adeotimiyemiye День тому

    Yeye dara eseun gan koni baje fun yin amiase seri kosi gbogbo Awusa Fulani Bororo atijo ota awa omo Yoruba ni wan oo apariwo kema munwan ni ore rara ki atete da oju ija kowan pada ti awan OBA wa koba gba abode funwa yes kilode eyipo kee i

  • @abebianike4049
    @abebianike4049 День тому

    Awa Yoruba ti n pe lara awon atoro je ewe Yoruba ti pe lara ose Yoruba ti di OSE oo ma se oo

  • @busayoabass6165
    @busayoabass6165 День тому

    Benin iya mi awon oloselu ati awon oba oloselu ti ta ile yoruba fun awon fulani

  • @olubunmiukhueleigbe3897
    @olubunmiukhueleigbe3897 День тому

    Rip our warrior, A fi kolorun gbawa Nile yoruba

  • @babalolakutedo5592
    @babalolakutedo5592 День тому

    Ejeki ajo fowo sowopo pelu Dr Sunday omo adeyemo igboho osaa lowo kale joo kuro ni orlide Nigeria yii kale joo lee awon bororo fulani nile yoruba

  • @babalolakutedo5592
    @babalolakutedo5592 День тому

    Haaaaaa igbayi laro ti arugbo nsuku oge see Dr Sunday omo adeyemo igboho osaa pariwo fun won wipe ki won fi owo soo wopo pelu yoruba nation sugbon won koo won tele won

  • @ganioloyede9333
    @ganioloyede9333 20 годин тому

    Yeye to Dara,morning ma

  • @sijiomoniyi5823
    @sijiomoniyi5823 День тому

    Kini wọn fẹ achieve, a fi ki wọn pọn awọn eniyan wọn lójú.

  • @adenikeadeyemo2133
    @adenikeadeyemo2133 День тому

    Ogun to jani fun ogun odun ati eyi to jani fun ogbo Osu ti ko ba pani a pada Lenin eni, ni agbara Olorun a ma Bo lojo kan loruko Jesu. Tori eleyi su wa oo

  • @seunrahman4828
    @seunrahman4828 23 години тому

    Good talk ❤❤❤

  • @MaryOdunuyi
    @MaryOdunuyi День тому

    Aku ara fera ku, Oluwa a gbe emi e lo si orun rere, ki Oluwa pa gbogbo asise re re, alaale agbe gbogbo awon to ku

  • @MaryOdunuyi
    @MaryOdunuyi День тому

    Education systems ti ku ni ilu eko, awon aladani ni won po si ninu ile pako, iyara kan ati ile panu, gbogbo e no ni ile iwe, eyi to je ti ijoba ti wo patapata, ile iwe mi ti di nkan mi, nigbati won gba tisa mo

  • @PaulinePauline-n4w
    @PaulinePauline-n4w День тому

    Hummmmm, Omo Yoruba e funra o lori awon akikaju ti won pa ejo lowo nun

  • @babalolakutedo5592
    @babalolakutedo5592 День тому

    Kosi nkaka ti awon oloselu ille yoruba ati awon totilo ati awon towa ni ibe lowo lowo kosi nkaka tii won see fun waa rara

  • @busayoabass6165
    @busayoabass6165 День тому

    Rip ki olorun ko fi original bother wa ti won ti lo

  • @busayoabass6165
    @busayoabass6165 День тому

    Ase wa mokan n

  • @Esther-f6y2e
    @Esther-f6y2e День тому

    RIP

  • @Esther-f6y2e
    @Esther-f6y2e День тому

    RIP

  • @OmotoshoBabatuda
    @OmotoshoBabatuda День тому

    Yes

  • @busayoabass6165
    @busayoabass6165 День тому

    Ase

  • @busayoabass6165
    @busayoabass6165 День тому

    Obasojo

  • @ronkejamolaya2630
    @ronkejamolaya2630 День тому

    Oye ki won lo fi ina sile oba ni ki won suu ni ina

  • @busayoabass6165
    @busayoabass6165 День тому

    Yeyedara kowe ko ko ko

  • @leyoola-xz4ld
    @leyoola-xz4ld 22 години тому

    Eefe bororo Sugbon E dibo fun Thiefnubu, efe fulani Sugbon esife Nigeria nitoripe atenuje owo awon oloselu,otumo si wipe Eefe ibeji Sugbon efe Taiwo

  • @gbemisolalawal5758
    @gbemisolalawal5758 12 годин тому

    ❤❤❤❤

  • @abebianike4049
    @abebianike4049 День тому

    Oo lagbaraa ooo

  • @ganioloyede9333
    @ganioloyede9333 20 годин тому

    Rest In Peace baba jagun

  • @bolanlekemi6903
    @bolanlekemi6903 17 годин тому

    May his soul rest in peace

  • @seunrahman4828
    @seunrahman4828 23 години тому

    ❤❤❤

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp 4 години тому

    HNNNNNNNNNN