Bẹ́ẹ̀ni, NI KÒ TAKO ÈRÒ, ÌMỌ̀ ÀTI ÀLÀYÉ YÌÍ. Ṣùgbọ́n ìmọ́lẹ̀ ránpẹ́ nípa òye àti ìmọ̀ témi náà ni pé @ ÌRÓ OHÙN (sounds/ tone of the voices) ìró ohùn ni gbígbé sókè sódò tàbí lílọ sókè sódò ohùn nígbà tí a bá ń sọ̀rọ̀, safọ̀, pípè tàbí gbígbé ọ̀rọ̀ jáde láti inú ẹ̀dọ̀ fóró. NÍGBÀ TÍ ÀMÌ OHÙN ( TONE MARKS) jẹ́ ohun tí a má a fi sórí ọ̀rọ̀ nínú èdè Yorùbá tó fí ìyàtọ̀ láàrin èdè Yòókù kí ó lè dùn ún kà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́, òǹkàwé àti gbogbo olùfẹ́ sí èdè Yorùbá. Nítorí pé èdè olóhùn ni èdè Yorùbá jẹ́. Ẹ wo àkíyèsí àti ìtọ́nisọ́nà yìí fún àgbọ́yé.....
Bẹ́ẹ̀ni, NI KÒ TAKO ÈRÒ, ÌMỌ̀ ÀTI ÀLÀYÉ YÌÍ. Ṣùgbọ́n ìmọ́lẹ̀ ránpẹ́ nípa òye àti ìmọ̀ témi náà ni pé @ ÌRÓ OHÙN (sounds/ tone of the voices) ìró ohùn ni gbígbé sókè sódò tàbí lílọ sókè sódò ohùn nígbà tí a bá ń sọ̀rọ̀, safọ̀, pípè tàbí gbígbé ọ̀rọ̀ jáde láti inú ẹ̀dọ̀ fóró. NÍGBÀ TÍ ÀMÌ OHÙN ( TONE MARKS) jẹ́ ohun tí a má a fi sórí ọ̀rọ̀ nínú èdè Yorùbá tó fí ìyàtọ̀ láàrin èdè Yòókù kí ó lè dùn ún kà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́, òǹkàwé àti gbogbo olùfẹ́ sí èdè Yorùbá. Nítorí pé èdè olóhùn ni èdè Yorùbá jẹ́. Ẹ wo àkíyèsí àti ìtọ́nisọ́nà yìí fún àgbọ́yé..... WPS Office: Complete office suite with PDF editor Here's the link to the file: eu.docworkspace.com/d/sIOHP7Ym_AdKnqK4G?sa=00&st=0t Get WPS Office for PC: www.wps.com/d/?from=t
Thank you for sharing ❤️
Mo gbadun eko yii
More grace to continue
Thanks sis
Ẹ ṣe púpò
Eyi dára pupo
Bẹ́ẹ̀ni, NI KÒ TAKO ÈRÒ, ÌMỌ̀ ÀTI ÀLÀYÉ YÌÍ. Ṣùgbọ́n ìmọ́lẹ̀ ránpẹ́ nípa òye àti ìmọ̀ témi náà ni pé @ ÌRÓ OHÙN (sounds/ tone of the voices) ìró ohùn ni gbígbé sókè sódò tàbí lílọ sókè sódò ohùn nígbà tí a bá ń sọ̀rọ̀, safọ̀, pípè tàbí gbígbé ọ̀rọ̀ jáde láti inú ẹ̀dọ̀ fóró. NÍGBÀ TÍ ÀMÌ OHÙN ( TONE MARKS) jẹ́ ohun tí a má a fi sórí ọ̀rọ̀ nínú èdè Yorùbá tó fí ìyàtọ̀ láàrin èdè Yòókù kí ó lè dùn ún kà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́, òǹkàwé àti gbogbo olùfẹ́ sí èdè Yorùbá. Nítorí pé èdè olóhùn ni èdè Yorùbá jẹ́. Ẹ wo àkíyèsí àti ìtọ́nisọ́nà yìí fún àgbọ́yé.....
Bẹ́ẹ̀ni, NI KÒ TAKO ÈRÒ, ÌMỌ̀ ÀTI ÀLÀYÉ YÌÍ. Ṣùgbọ́n ìmọ́lẹ̀ ránpẹ́ nípa òye àti ìmọ̀ témi náà ni pé @ ÌRÓ OHÙN (sounds/ tone of the voices) ìró ohùn ni gbígbé sókè sódò tàbí lílọ sókè sódò ohùn nígbà tí a bá ń sọ̀rọ̀, safọ̀, pípè tàbí gbígbé ọ̀rọ̀ jáde láti inú ẹ̀dọ̀ fóró. NÍGBÀ TÍ ÀMÌ OHÙN ( TONE MARKS) jẹ́ ohun tí a má a fi sórí ọ̀rọ̀ nínú èdè Yorùbá tó fí ìyàtọ̀ láàrin èdè Yòókù kí ó lè dùn ún kà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́, òǹkàwé àti gbogbo olùfẹ́ sí èdè Yorùbá. Nítorí pé èdè olóhùn ni èdè Yorùbá jẹ́. Ẹ wo àkíyèsí àti ìtọ́nisọ́nà yìí fún àgbọ́yé.....
WPS Office: Complete office suite with PDF editor
Here's the link to the file:
eu.docworkspace.com/d/sIOHP7Ym_AdKnqK4G?sa=00&st=0t
Get WPS Office for PC:
www.wps.com/d/?from=t
Oro yin ti ye mi. E se pupo fun akiyesi na a