A bi o. Awon ti esin to ko si lagbari. Ikan alrwon so pe muslim le fe Chtistiani obinrin sugbo obinrin ye ko leto si ogun oko re ti o ba ku nitoripe ki se musulumi. Awon larubawa gan to ni esin Isilamu, won gba kankankan bi it awon istjabah, al shariah.
i love❤ that statement >> ariwo ko ni music
Peace be upon you Sheikh.
Amiin 🙏
Alfa e bawa soro Lori ki okunrin Abi obinrin ma bo Ara pelu chemical
Se o too sunnah
Awa yooku nko alfa taikise omo iya inu Islam sugbon ti a je omo iya ninu iran yoruba. Ko yo kiki funwa?
A bi o. Awon ti esin to ko si lagbari. Ikan alrwon so pe muslim le fe Chtistiani obinrin sugbo obinrin ye ko leto si ogun oko re ti o ba ku nitoripe ki se musulumi. Awon larubawa gan to ni esin Isilamu, won gba kankankan bi it awon istjabah, al shariah.
Gbogbo yin ni won ki Sir, ike ati ola Olohun ki o ma ba gbogbo wa
Good morning sir
JazakumuLLAHU khairan sheikh, may Almighty ALLAHU bless you more 🙏