Розмір відео: 1280 X 720853 X 480640 X 360
Показувати елементи керування програвачем
Автоматичне відтворення
Автоповтор
Esin yin na ni e fi ba Ile yoruba je.
i love old laji abbass song than this one.
Hmmm ❤ Amin ati gbogbowa
"Ẹ má fi Ìbàdàn ṣeré o. Mí ò ní fi Ibadan ṣeré o. Ẹ̀dá tó fi Ibadan ṣeré ìyẹn nwa 'yọnu.. "- Chief Commander Ebenezer Obey.. Evergreen songs.
Chief laji Mr check and balance well said sir
Gbogbo Ile Yoruba Kole sere oooo Huuuuuum Ibadan Anu Omo yen semiooooo
Portable. Omo aijoberi to njapo si aya.
Eni tori e ba ti daru o, lolefomo Ibadan sere o.
Kole sere ni gbogbo Ile Yoruba ni ema ba Bebe ooooo
True talk aarẹ opitan. God bless you 🙏
Aarẹ said "fine boy malato"😂
Oloshi ni Bobo Portable yen, just forget about the mumu man Aare Opitan.
True talk. ❤❤❤❤❤❤❤
Pls what is title of the songs
Àwa na lo ilé ìgbọ̀nsẹ pokítì nigbati a wà ní kékeré.. Àwọn agbépóò má nlọ gbé póò yẹn lẹ̀yìn ìgànna, pelu garawa ẹbọ́tọ lórí lọwọ́ alẹ́...
Aarẹ,Portable lẹ n dalohun😂😂😂iyẹn ti igbo ti yi lori
I am as surprised as u re, honor portable with nearly 3hrs response,
E ti e ri show se. Answering portable?
Oloru Aron.yin lowo emaje.ki oro awon olode korewesibayi
Laji Abbas...ekun ogbon ati imo...
E ku ipalemo odun o, Aare opintan
Eku etoo sir eku Ohun
Not only àṣà even ẹṣin, but been a muslim it will be hard for you to say.
❤❤❤❤😂😂
Alimokan leunda loun
Portable tún ń wípé kí ló dé tí àwọn ọmọ Ọba ó ṣe ṣú Dami l'opó... Ṣé bó ṣe nrí nílẹ̀ Yoòbá niyen? Kí ọmọ máa ṣúpo bàbá rẹ̀.. Èmi ò gbọ́ yẹn rí o..
Esin yin na ni e fi ba Ile yoruba je.
i love old laji abbass song than this one.
Hmmm ❤ Amin ati gbogbowa
"Ẹ má fi Ìbàdàn ṣeré o. Mí ò ní fi Ibadan ṣeré o. Ẹ̀dá tó fi Ibadan ṣeré ìyẹn nwa 'yọnu.. "
- Chief Commander Ebenezer Obey.. Evergreen songs.