Tani Yoruba? 9

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 2 лют 2025

КОМЕНТАРІ • 18

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu9017 5 років тому +4

    Awon ti Egba ati Awon ti losi Port Novo? Donc Awon Ti OWU ti won wa ni Abeokuta tiwon nko? Kabiyesi Eledumare Laji Abbas Eku Ise opolo Amaju yinse Amin

  • @Ayodeleist
    @Ayodeleist 5 років тому +2

    Adupe o Oluko agba laji Abass! Eku ise naa.

  • @KKandu4040
    @KKandu4040 5 років тому +4

    E ku ise o.
    Ire ati anu Olorun yio ma ba e gbe o

  • @empresskofoworolatv
    @empresskofoworolatv 3 роки тому +1

    wao 😮 you just make mention of Yagba and Egbemekun 🙌 mo ro pe emon ni pa Yagba ati Egbe ni oh

  • @yusufsaheedadewale7751
    @yusufsaheedadewale7751 4 роки тому +1

    E seun oluko agba itan womi Lara gidi gan ni, olorun a maa fun yin se

  • @OpesanFunsho-kk7ih
    @OpesanFunsho-kk7ih 16 днів тому

    Houn ti emi mo nipe Omo bibi Yoruba kan naa ni gbogbo wa ema so pe aki se omoyakan atan kakiki agbaye ni stipe eyin gan oleri gbogbo ako si le Yoruba taan ematu da yan pan yan ri sile Yoruba rara isokan Yoruba lafe oduduwa agbewa o as

  • @olaotanshegun8637
    @olaotanshegun8637 5 років тому +2

    Oluko Agba otojo meta moti retireti

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 3 роки тому

    È kabo Oluko agba

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 3 роки тому

    Gegebi brasil

  • @dahakrimadja1863
    @dahakrimadja1863 4 роки тому

    Eru aye bami

  • @shituadebayo3846
    @shituadebayo3846 5 років тому +2

    ESE OLOTU AGBA OTUMO SIPE AROMODOMO NAMURUSU NI YORUBA TISE BABA WA OODUDUWA

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu9017 5 років тому +1

    👍💯

  • @officialsliconetv8287
    @officialsliconetv8287 5 років тому

    Please can you translate the numbers in Yoruba to English please! Thank you sir

  • @janeeeyoshinowo9864
    @janeeeyoshinowo9864 4 роки тому +2

    O dabi enipe e ko ranti pe igba Oyo Empire, awon Oyo dabo bo gbogbo Ekiti, Ife, Igbomina,Ijesa, Ondo ati beebe lo. Nwon si ran awon Ilari lo si ibe lati gba isakole. Gege bi apeere, e o ri awon Omo omo Omo etc awon wonyi ni Ikere Ekiti, Ikoro Ekiti ati beebe lo.

  • @olumakinwaisingbadebo706
    @olumakinwaisingbadebo706 3 роки тому

    BRAZIL

  • @shituadebayo3846
    @shituadebayo3846 5 років тому +1

    ESE OLOTU IJEBU IJESA OHUNDO ATI EGBA ATI BEBE LO KOSI BI WON SEMASO EDE OYO NI SUGBON OLOO LENU WON YATO SI AWON IBINI NIKAN ADE LODAWAPO

  • @shituadebayo3846
    @shituadebayo3846 5 років тому +1

    ESE OLOTU IRAN OYO TI WON BAFE KO IWE WON MA KO NI YORUBA GEGE BI EDE WON OLOTU IJEBU IJESA OHUNDO ATI EGBA SE AWON YII NI OHUNKO TIWON YATO SI TITI OYO