Ìbàràpá náà wà ní Abẹ́òkúta.. Ọjà Ìbàràpá aarọ̀ wa, Ìbàràpá alẹ́ wà.. Wọ́n ti ràn mi lọ ra ǹkan ní àwọn ọjà wọ̀nyìí rí, nigbà tí à ngbé ni Ìsàlè-Aké ní ìgbà tí a wà ní kékeré.
Weldone sir, The present Yoruba land transcends the old Oyo empire, therefore the inhabitants of Old Oyo empire were not the only Yoruba. Do you agree with this.
😂❤❤
Ìbàràpá náà wà ní Abẹ́òkúta.. Ọjà Ìbàràpá aarọ̀ wa, Ìbàràpá alẹ́ wà.. Wọ́n ti ràn mi lọ ra ǹkan ní àwọn ọjà wọ̀nyìí rí, nigbà tí à ngbé ni Ìsàlè-Aké ní ìgbà tí a wà ní kékeré.
I’m watching again 💃💃💃💃
Nice one boss
Ìlú àwọn wérí-wénu.
👏Laji Abbas Eshun Itan Are Afonja Amafarabale gbo dada nitori owa important pupo fun Omo kotu ojire lopolopo Oba mi amafun yin se ASE
Baba Laji Abbas, you deserve a professorial title. I love your diligence and objectivity.
aku isetakun takun
Amazing job. Esee ti e lawa ni iye ati imo.
May Almighty Allah bless you and your generation
E ku ise opolo oluko agba,konireyin oo,aisan konigbeyinde oo amariyinba oo ajuuwaseeeooo Amin
Mo ki yin ati omo meji, e ku ise, ajinde ara yio make yin o. E daruko awon ill to wa leku Ibolo sugbon e ko daruko Erin ile, se ko wa lara Ibolo ni?
Oluko agba a gbadun eto yin oooo more wisdom and keep it up sir
Eku ise oluko agba
Eku ise opolo
Eku ise baba mi
💯💯💯💯💯💯💯
Shaki pa la pelu sabe.
Weldone sir, The present Yoruba land transcends the old Oyo empire, therefore the inhabitants of Old Oyo empire were not the only Yoruba. Do you agree with this.