amazing eye Kannakanna ti o ye eyin sugbon to ba ba le eyin eye ti eye to ye eying ba pamo, okan ninu awon eyin won yi ajo. Oluwa mo fi ori bale fun oh
Kare Laji Abbas Itan yi kamama Olodumare Oba NLA itan na agboye gidi Owa ku si Owo gbogbo wa walai Itan nii Otobi pupo mais aditu loro Eledumare ibere po ki se nisiyin pesepese InShaAllah Eshun Oba mi amafun yin se ASE 🙏🙏🙏
Dan Mazani wa lati okè-ọya, o wá ńpìtan wa fún wa, láti fi tẹ́ ara rẹ̀ lọ́rùn. Abájọ naa tó fi ní àwọn làwọ́n sọ wá ní "Yorùbá".. Mọ́là, lásán-làsàn.. 🤣🤣😂😂. Ẹjọ́ rẹ̀ wa ni... N'gbà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwa ọmọ Yorùbá 'ò ní ṣe ìwádì orírun, ìtàn àti àṣà àti ìṣe wa.
E jo, awon wo ni Ugbo ti awon Alaiyemoore pa idi apo pelu?? Se awon Ibo ti apa ila orun Nigeria ni? Abi awon wo? Toripe awon Ibo kan dabi enipe won so wipe awon eeyan awon ni awon Ugbo yii

Olorun a fun yin se. Laji Abass ese mo dupe o. A o ma rii yin ba.
Baba eseee eku isetakuntakun.ibere mi lobayi wipe se beeni pe Sango ati Ogun ja fun obinrin
Ijebu-ife ni ilu temi. Inumidun lati gbo itan de ilu mi.....❤❤❤🇳🇬🇳🇬🇳🇬🇺🇸🇺🇸🇺🇸🇳🇬🇳🇬🇳🇬
Kare Laji Abbas Itan yi kamama Olodumare Oba NLA itan na agboye gidi Owa ku si Owo gbogbo wa walai Itan nii Otobi pupo mais aditu loro Eledumare ibere po ki se nisiyin pesepese InShaAllah Eshun Oba mi amafun yin se ASE 🙏🙏🙏
Alao biliaminu from Germany
Ago-Oko ni Abeokuta je olu ilu Egba Oke-Ona. Ibe ni aafin Osile Oke-Ona wa.
Dan Mazani wa lati okè-ọya, o wá ńpìtan wa fún wa, láti fi tẹ́ ara rẹ̀ lọ́rùn. Abájọ naa tó fi ní àwọn làwọ́n sọ wá ní "Yorùbá".. Mọ́là, lásán-làsàn.. 🤣🤣😂😂. Ẹjọ́ rẹ̀ wa ni... N'gbà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwa ọmọ Yorùbá 'ò ní ṣe ìwádì orírun, ìtàn àti àṣà àti ìṣe wa.
Can you do the story of iseyin?
How tall was orunmiyan from ile ife ???
We need story of saki
E ku ise sir, e ejowo se e le shalaye nipa DNA ti o dagba ju laye?
Iran lafodido ni emi je ni Ile-Ife.
E jo, awon wo ni Ugbo ti awon Alaiyemoore pa idi apo pelu?? Se awon Ibo ti apa ila orun Nigeria ni? Abi awon wo? Toripe awon Ibo kan dabi enipe won so wipe awon eeyan awon ni awon Ugbo yii
OLUKO AGBA EKUN ISE OO EJO NIBO NI AJERO TI JE OBA
Ekiti
My love for this Man is great for letting me know alot of Yoruba history thank you