Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pè o, Ẹgúngún o Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o (Gbogbo mònríwo) Ẹgúngún a yè, kíì ṣẹ́ bọ ọ̀run Mo júbà rẹ̀ Ẹgúngún mònríwo Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o A kíì dé wa ó, a kíì ẹ́ Ẹgúngún Won gbogbo ará asíwájú awo Won gbogbo aráalé asíwájú mi Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o Mo pẹ̀ gbogbo ẹ̀nyin Si fún mi ààbò àti ìrònlọ́wọ́ Agó, kìì ngbọ́ ekún ọmọ rẹ̀ Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o Ki o ma ta etí wéré Bàbá awa ọmọ rẹ ni a npẹ̀ o Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o Ki o sare wá jẹ́ wa o Ki o gbọ́ ìwùre wá Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o Má jẹ̀ a ríkú èwe Má jẹ̀ a ríjà Èsú Má jẹ̀ a ríjà Ògún Má jẹ̀ a rija omi Má jẹ̀ a rija Soponná Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o Motumbá Bàbá Egungun Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ilẹ̀ mo pẹ̀ o, Ẹgúngún o
Curta o vídeo para ajudar o canal ❤️
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pè o,
Ẹgúngún o
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
(Gbogbo mònríwo)
Ẹgúngún a yè, kíì ṣẹ́ bọ ọ̀run
Mo júbà rẹ̀ Ẹgúngún mònríwo
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
A kíì dé wa ó, a kíì ẹ́ Ẹgúngún
Won gbogbo ará asíwájú awo
Won gbogbo aráalé asíwájú mi
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
Mo pẹ̀ gbogbo ẹ̀nyin
Si fún mi ààbò àti ìrònlọ́wọ́
Agó, kìì ngbọ́ ekún ọmọ rẹ̀
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
Ki o ma ta etí wéré
Bàbá awa ọmọ rẹ ni a npẹ̀ o
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
Ki o sare wá jẹ́ wa o
Ki o gbọ́ ìwùre wá
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
Má jẹ̀ a ríkú èwe
Má jẹ̀ a ríjà Èsú
Má jẹ̀ a ríjà Ògún
Má jẹ̀ a rija omi
Má jẹ̀ a rija Soponná
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
Motumbá Bàbá Egungun
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o
Um excelente vídeo parabéns
👏👏👏👏👏
Essa é resa de invocar baba egun