Oyeolohun Tv. Please for the Awenu asina that you divide into 9 places using 3 daily for 3days. Please do we use different sponge daily for the 3days. Please respond. Thanks..
Baba egbeji is very intellectual despite the fact that he didn’t attend a secondary and tertiary institution. What a knowledge? I give big tuale to you sir. Emi yin a gun dale amin🙏
Agba yin adale baba egbeji ogbomosho. Olorun olodumare fun yoruba nimo pupo sugbon esin ti gba laakaye awon opolopo omoluabi. Ki eledumare ko saanu wa.
Ahhhhhhhhhhh I swear adesu n'be atunbotan re ni o da ooooo hmmmm aponipokipo n'be ahko n'be hmmmm I smile arinjinna lairi abuke okere oooo infant anobo n'be I swear
Thanks, àwa náà mọ pe airinjina la o ri abuke Ọ̀kẹ́rẹ́, ti a ba de ìsàlẹ̀ odò a ma ri ẹja to yarọ. Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ inú ilé, a kii sọ nita, ọ̀rọ̀ ìta a kii sọ ninu ile. Contact us on WhatsApp 08069316812 for more enlightenment
I am from Lagos but i know baba Egbeji live and direct❤ you will love to be with him even if you don’t want to do juju😁 very interesting man always❤ he’s very cool and wise man. Very humble man❤️❤️❤️
E gba emi sile o Ekon gba owo ni 150 thousand mi si wa lowo yin, mo pe yin egbe phone mi mo E sise fun mi, e si da owo mi pada, lati 2 years Afo, deni e pe mi e de da owo mi, pada Baba egbeji boya e busy ni boya e gbagbe i don't know Eyin de ni ewa lori social media, e need lati keep image yin, e da Owo mi pada fun mi, mo pe yin ti, e gbe phone mi mo, Oye ki ema ko oruko awon ti won be yin fun ise, ti won ti lowo fun yin sile ati Owo ti won ba son fun yin sile, ti e ba busy, iwe yen loma ran yin leti se ise won, ekon Ki e ma ba image yin je Baba bi mo se like yin to Mafe pe ki e tun arin yen se Eyin ni baba Wa ni ile yoruba, mo binu siyin Sugbon e yin arin yen se Olodunmare awa pelu yin o Eku ise olotu olodunmare a so agbara di otun o
E seun Iyaafin, E dakun bi mio ba si yin gbo, ti moba gbo yin ye, E Sope o tito odun meji abo seyin tie ti fi owo sowo si baba? To tumo si wipe kiise ori ikanni wa yii leti koko ba won pade abi bee ko? O si dabi wipe e ti kan si mi lori oro yii ti moti bayin pe won abi bee ko?
First to watch , first to comment. Pinned my comment. Ese, gan
You got it
Ẹ seun, mo pinned ẹ 😅 Ẹ kú ìfẹ́ Olódùmarè lára wa ✌️
@@OYEOLOHUN_TV Ese pupo fu gbogbo effort
Thank God u visit Baba ooo I respect him so much Nd been to his place bfor
Oyeolohun Tv. Please for the Awenu asina that you divide into 9 places using 3 daily for 3days. Please do we use different sponge daily for the 3days. Please respond. Thanks..
Still coming here to watch baba again ❤😊
Baba Alalubarika, ee ni toju ile mole
I'm from ogbomoso i love this man 😊
Oh really
Baba is full of wisdom 😊😊 May you live long sir
Amin ase Edumare
I'm so glad you interviewed baba egbeji oo. Na strong men you've been interviewing
Thanks sir, Ẹ seun pupọ ✌️
Baba egbeji! Oyeolohun, Ẹ kú iṣẹ́ takuntakun o. A máa jù yin ṣe o.
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ sir
Amen Amen Amen
❤ My Baba Egbeji, tuale sir! Nice seeing you again. E pe fun wa
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Bàbá nki yín ooo
Ipa ota koni kayin Oyeolohun bie sengbe asa atise wa laruge eoni wale sir
Àmín oooo, Ẹ seun pupọ ✌️
Olorun A ma bayin se ooo eku eto sir
I'm proud of you sir. God is your strength
Amen Thanks ✌️
Baba egbeji is very intellectual despite the fact that he didn’t attend a secondary and tertiary institution. What a knowledge? I give big tuale to you sir. Emi yin a gun dale amin🙏
What a good lesson and illustration, baba may God keep you, I wish to know you.
Eku ise ooo Oyeolohun broda mi. Moje ri yin oo👍. Yi o ma ju yin se oooo.
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ brọda mi láti Osogbo, adora wa a gba✌️
Baba Egbeji Eku eto
E SEUN
Agba yin adale baba egbeji ogbomosho. Olorun olodumare fun yoruba nimo pupo sugbon esin ti gba laakaye awon opolopo omoluabi. Ki eledumare ko saanu wa.
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Olódùmarè Á bá wa dá iyì àti apọnle ilẹ̀ Yorùbá padà ✌️
Eku ise ooo e dakun mofe noba ero alagbeka yin ati ti Baba egbeji Ogbomosho sir
Ẹ seun, Ẹ bá wa sọ̀rọ̀ lórí WhatsApp 08069316812 ✌️
Baba too busy beyond to carry ur number
Humm very deep sir weldone
Thanks ✌️
Have been to this baba house before na confirm
Keep up the good work baba 👏🏻👏🏻❤️🙂
Very educative program, keep it up sir 👏
Thank you, I will
Nice one aburo mi 👍👍👍
Ẹ seun sir, mo dúpẹ́ ooo
Baba mi Egbeji ❤️ God bless you !
Baba Egbeji I love you Sir
Thanks for the love for him
OYEOLOHUN moki yin sir eku igbiyanju oba oke o ni jeki a se lasan
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Àmín ooo, Ẹ seun ìyá mi ✌️
Ahhhhhhhhhhh I swear adesu n'be atunbotan re ni o da ooooo hmmmm aponipokipo n'be ahko n'be hmmmm I smile arinjinna lairi abuke okere oooo infant anobo n'be I swear
Thanks, àwa náà mọ pe airinjina la o ri abuke Ọ̀kẹ́rẹ́, ti a ba de ìsàlẹ̀ odò a ma ri ẹja to yarọ. Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ inú ilé, a kii sọ nita, ọ̀rọ̀ ìta a kii sọ ninu ile. Contact us on WhatsApp 08069316812 for more enlightenment
Baba egbeji olorun oba a ma fun yin se baba
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ✌️
Well done! Please show us the "ori anjoonu".
E Ku ise baba mi. Oodua a gbe wa.
Amin ase Edumare, E seun
Thank you for this wonderful program of yours Mr Agoro. Your program is inspiring and life saving and giving hopeless hope. Thanks 🙏
Thanks sir ❤️💯✌️
Eku eto sir olorun yoo ma ranyin lowo sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀, Àánú Ọlọhun koni fi ẹyin naa silẹ ✌️
Olorun o ni kuru lakaye yin sir
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ✌️
This is what I'm saying, you always kill it Oyeolohun please keep it up ❤️
Thanks sir my brother ✌️
It time to kick it up a niche’s, it time to start demonstrating their skills.
Hummm! Thanks sir
Yes Baba, God bless Us with the entire knowledge and wisdom.
I am from Lagos but i know baba Egbeji live and direct❤ you will love to be with him even if you don’t want to do juju😁 very interesting man always❤ he’s very cool and wise man. Very humble man❤️❤️❤️
Hummm! Thanks sir✌️
Be careful owo mi wa lowo baba yi
Baba kon gba owo mi ni, lati 2 years ago baba o gbe phone mi mo
You should have let Baba take us To his power house Egbe fun fun ode orun
Okay
I trust you sir, May God bless you more
Àrà òtò , respect
Thanks sir ❤️
Wow 👌 long time sir
Yes, thanks
Nice one
Thanks ✌
Amen
Ewe ati egbo a maa je o baba.
You are the Best ❤🎉 More Way Forward sir
Thank you so much 😀
Àmín àṣẹ Èdùmàrè
Oyeolohun eku ise ooo
Ẹ seun sir
I always enjoy your program sir may God bless you
Amen, Thanks my brother ✌️
It's what we called discerning spirit, in the Bible. Very important to know.
I always watch ur program. Keep it up
Thanks sir for your encouragement word ✌️
So bawo lase leri awon baba wa Alhaji fun ajoo
Contact us on Whatsapp 08069316812 to collect his phone number. THANKS
Koni suyin se ooo adupe ooo
Merci beaucoup
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ Ẹ̀gbọ́n mi, A kú ọjọ́ gbọọrọ bí ọwọ́ aṣọ ✌️
Baba Egbeji Ogbomoso ❤ I love you so much ❤
Hummm! Omo agoro Eku ise o olorun ama funyin se
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun èmi nù-un✌️
Keep up the good work baba 👏🏻👏🏻👏🏻❤️
Thanks ✌
I just found out about this channel and I love what you do my brother.... Much 🖤
Oduduwa o gbe wa o 🙏🏼
Respect baba mi
Thanks My Soul
Nice one my brother please we need to talk sir
Thanks sir, no problem my brother ✌️
Wow
How can i know this man
I love your program sir ❤️
Thanks Madam, We love you too ✌️
Good job
Thanks ✌
Well done sir
Ẹ seun A dúpẹ́ sir ✌️
Amin ase
Weldone sir may God bless you
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun mo dúpẹ́ púpọ̀ ✌️
Baba egbeji Ogbomosho i love you so much thank you sir
🎉❤
Nice ❤ advice
Glad you think so!
THANK you
Olódùmarè lọpẹ́ tọ́sí✌️
Mr Agoro o to ojo meta , ka si n kan Olorun yio ma fi iso re so wa.
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, kò kúkú sí láburú, àsá wa kò pẹ́ ko bẹ́ẹ̀ rí ọ̀nà ló ji❤️💯✌️
Weldone sir hope all is well? May God bless you for this
Yes, thank you
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun pupọ ✌️
@OYEOLOHUN_TV how can I get his number sir
@@goldinahouseofbeauty Contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his phone number. Thanks
I know Baba well well-confirmed
Okay sir, Thanks
Hello
Excellent interview
Eku eto sir koni suyin koni reyin lagbara olorun
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Ẹ seun púpọ̀ ma✌️
Great job
Ẹ seun púpọ̀ ✌️
thank you so much sir ❣️
Most welcome
Baba mi ,happy to see you here...
Baba mi Egbeji Ogbomosho, my mentor..
O dára bẹ́ẹ̀, Olódùmarè kòní padà lẹ́yìn gbogbo wa
I too dey gbadun as baba dey explain stuff. Opolo yon oni joba lase Edumare🙏
Amin ase, Mo ba won se Amin witiwiti
E jowo e fun wa ni telephone Alhaji
Ẹ seun, Ẹ kàn sí wa lórí WhatsApp 08069316812 láti gba òùnkà ẹ̀rọ ìbáni sọ̀rọ̀ wọn ✌️
Nice one sir
Thanks ✌️
Sir i love ur videos
How can i get to him
YOUR BACKGROUND IS TOO NOISY SIR.
Eku eto olorun ama ran yin lowo oo
Pls how can I get baba egbeji numbers
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, just contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his phone number
Well done Mr agoro. How can we get in touch with this man
Contact us on WhatsApp 08069316812 to collect his phone number. Thanks
43:30
Welcome back
Ẹ seun Ẹ̀gbọ́n mi, Ẹ kú ọjọ́ mẹ́ta sir✌️
45:00
9:10
I messaged you a few days ago but you ignored me.
Please resend your message, not intentionally but there's lots of message in our DM, Sorry for that
Alh. Sulaiman's voice is not audible.
E seun
Baba efun wa ni number
E jowo e fun wa ni number Baba
Arẹwà Bukky, O dà bí wípé èmi àti ìjọ yín ti jọ sọ̀rọ̀ lórí WhatsApp 08069316812? Àbí ẹ̀yin kọ ní? Ẹ seun ✌️
Confirm ni baba
Pls too much preamble go to the show
E dakun e bawa tu oyinbo ti e so hun, E seun
Please remember to ask for Egbeji phone number.
E gba emi sile o
Ekon gba owo ni 150 thousand mi si wa lowo yin, mo pe yin egbe phone mi mo
E sise fun mi, e si da owo mi pada, lati 2 years Afo, deni e pe mi e de da owo mi, pada
Baba egbeji boya e busy ni boya e gbagbe i don't know
Eyin de ni ewa lori social media, e need lati keep image yin, e da Owo mi pada fun mi, mo pe yin ti, e gbe phone mi mo,
Oye ki ema ko oruko awon ti won be yin fun ise, ti won ti lowo fun yin sile ati Owo ti won ba son fun yin sile, ti e ba busy, iwe yen loma ran yin leti se ise won, ekon
Ki e ma ba image yin je
Baba bi mo se like yin to
Mafe pe ki e tun arin yen se
Eyin ni baba Wa ni ile yoruba, mo binu siyin Sugbon e yin arin yen se
Olodunmare awa pelu yin o
Eku ise olotu olodunmare a so agbara di otun o
E seun Iyaafin, E dakun bi mio ba si yin gbo, ti moba gbo yin ye, E Sope o tito odun meji abo seyin tie ti fi owo sowo si baba? To tumo si wipe kiise ori ikanni wa yii leti koko ba won pade abi bee ko? O si dabi wipe e ti kan si mi lori oro yii ti moti bayin pe won abi bee ko?
Oyelohun abeg I need this man contact ..number
Please contact us on WhatsApp 08069316812 Thanks
Well done sir