Baba Adedotun Ogundeji, ẹ kú àgbà. Inú mi dùn wípé irú yín sì nbẹ. K'ẹpẹ́ fún wa. I like your boldness and confidence. It takes confidence to tell the truth. I love you for telling it boldly that you can never forget or forsake your ancestors. May Eledumare bless you with long live in good health. Àṣẹ.
I love your simplicity and sincerity Baba, God bless you.
Bekear TV, kudos to you sir.
Eseun lopolopo sir
@@BikearTv ❣️
Bikear tv loke loke le o ma re. Super interesting programme, makes me learn new things everyday.
Eseun lopolopo fún Ife ti eni siwa. You are the best sir!
Baba Adedotun Ogundeji, ẹ kú àgbà.
Inú mi dùn wípé irú yín sì nbẹ. K'ẹpẹ́ fún wa.
I like your boldness and confidence. It takes confidence to tell the truth. I love you for telling it boldly that you can never forget or forsake your ancestors. May Eledumare bless you with long live in good health. Àṣẹ.
Ase wá! Àdúrà tiyin nan yo gba
Erin Fam ❤️
Mo n gbadun yin
I laughed through out😂😂😂😂😂😂
Ọlọ́run abawa sanyin lesan rere oo
Ase wá! Irẹ àti Àánú Olódùmarè kọ́ni fiyin sile.
Both of you look alike so much
Great discussion with one of our elders! Thank you!
Olootu, ẹmi yin a gun ninu òwó alafia baba ọrọ. Thanks for keeping us inform about our culture sir
Eledua yo fi ìgbà deyin lọrun. Ojú kọ́ni tiyin.
Great job sir
part 2
Heheene Ę tún ti gbé nti mo mọọ jẹ de 😂😂😂.
E kuuse takuntakun Olootu.
Eledua yo gbo Àdúrà yin Baba mi. Eseun lopolopo sir
Good job!
Thanks for the compliment sir
Walahi mo gbádùn Baba yi sir 😂😂😂
Ibà yín @deep 679
Well done sir 🙏
Adupe sir