WASIU AYINDE DA EPE PADA FUN AWON ALFA LORI ORO GANUSI

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 9 лют 2025

КОМЕНТАРІ • 129

  • @PatriciaIbidunniAdebayo
    @PatriciaIbidunniAdebayo 11 днів тому +9

    Abo Olorun ma ba Wasiu, Oni jabo ki ojo meje to pe loruko Olorun Alaye
    Wa gun lemi Wasiu , o ni se aisan, oni ku lewe, gbogbo won lo ma ma ku loju re Wasiu. Amin

  • @beatriceajayi4970
    @beatriceajayi4970 7 днів тому +2

    Babagida is on wheel chair today...(All the money,he embezzled, he cannot buy his health to be walking.. (Wasiu please 🙏 listen,apologise sometime does not mean u are wrong,u just want peace to reign , we love u ,u are one of our African star that do make some people happy with your song.. Do it for the sake of ur late mum .

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +6

    Kosi aburu kankan ti o maa sele si Wasiu Ayinde K1 lagbara Olorun Eledumare. Wasiu Ayinde ki yio ku iku kiku kan, sugbon bikose yiye lagbara Olorun. Nitoripe omo eniyan ko lo se Eda Wasiu Ayinde, therefore, gbogbo abiyamo aye yio duro ti Wasiu Ayinde, won koni jeki o jabo lagbara Olorun.

  • @ahlajagramma5282
    @ahlajagramma5282 11 днів тому +2

    Wasiu koni ku lagbara Olorun, gbogbo eyin ejebure ooo, omo yin Wasiu Ayinde, ebawa dariji ooo, esanu abiyamo ooo

  • @PatriciaIbidunniAdebayo
    @PatriciaIbidunniAdebayo 11 днів тому +3

    Thank you,for sending it back to them. See the way he is cursing. It shall be so for their family. Awon elepe Alfa. ELEPES

  • @adetountalabi6823
    @adetountalabi6823 12 днів тому +2

    You are a good leader ,Agba yin a di ale sir.

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 12 днів тому +3

    K 1. Omo-Oko yoruba tooto, thank you for replying your enemies, No weapon fashion against u shall prosper in Jesus mighty name!

  • @olusaemmanuel7634
    @olusaemmanuel7634 6 днів тому

    The pride in the alfas is even more than what they accused Wasiu of. They talk as if they're are God....

  • @abiodunogunlana2979
    @abiodunogunlana2979 8 днів тому +1

    K 1 GOD will be with you.

  • @nelsonadenola9754
    @nelsonadenola9754 12 днів тому +5

    May all their curses be unto them and their generation.
    This Alfa is wise than all of them put together..
    Wasiu is more knowledgeable and brilliant than all the alfa cursing him... He fears God more than all of you...
    He is the Olori omo Oba of Ijebu land..you Alatenuje guys thought na moimoi abi?..
    May orunmila and Sango kpae you all...

  • @OluwagbengaOlawande
    @OluwagbengaOlawande 12 днів тому +3

    Nothing go do wasiu ayinde by God's grace ❤

  • @balogunomosesan532
    @balogunomosesan532 4 дні тому

    Amen 🙏 oo k1 the ultimate... Black to sender to Alfa that is swear to k1

  • @chukwuemeka1202
    @chukwuemeka1202 12 днів тому +5

    Kowokowo Araba o Wo Mo Oju Tiroko,Nkan Kan o nii Se Wasiu Ayinde

  • @hadjiyaro881
    @hadjiyaro881 12 днів тому +5

    OLORIBU ELENUN RIRUN EYIN ALFA OHUN NAADA ONIDOTI NI GBOGBO YIN E LEENI LARI TO WASIU AYINDE EKANPARIWO LASAN NI,,,,,,ARABIC LEVEL LASAN 😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂

  • @ezekielagbeje227
    @ezekielagbeje227 11 днів тому +3

    Wasiu ni agbara Olorun wasiu onijabo

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +3

    Eleyi ma wa ga o. Olorun Eledumare jowo bawa le esin ajoji ti o fe ba ile Yoruba je jina siwa.

  • @taiwotinuoye329
    @taiwotinuoye329 11 днів тому +1

    ALHAJI WASIU Ayinde ma da awon radarada Alufa

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +5

    Alabosi ni gbogbo yin patapata. Kilode ti eyin musulumi buru. I thank God pe emi o si ninu ilana esin buruku bayi. Esin ti ko se fi yangan.😮 Jagidijagan esin, wahala saa ni all over the world.

  • @BlessedMother1
    @BlessedMother1 8 днів тому

    Iya Lagbara lara omo huuun, I Am 70yrs , OLORUN OBA Ti Koniku KABI-OSI, Jowo Ni oju aiye Mi ati lehin iku Mi OLORUN OBA Jowo Majeki ogun ja Awon Omo Mi AMIN.

  • @fatimaahmed7249
    @fatimaahmed7249 12 днів тому +5

    Eyin Alfas, e beru Olorun ooo, As a practicing Muslima, i think any "AlAfa" cursing instead of praying for God to forgive an errant Muslim,is raining curses, walahi, those "Alfas" will all reap the same curses that they rain instead of praying for him/her...This is so shameful. Little wonder that The Arab Muslims look down at African (especially Nigerian Muslims)!

  • @taiwotinuoye329
    @taiwotinuoye329 11 днів тому +2

    Alufa radarada ewo ni ti epe. Se eni olorun ama sepe. Eyin Alufa ile Yoruba ati Alufa ilorin e ki se eni olorun

  • @Muasak-x3c
    @Muasak-x3c 11 днів тому +3

    Aseju awon Alfa ti Fe poju Lori Oro Wasiu Ayinde yi, ewo ni epe. Olorun lo da Alhaji Wasiu Ayinde, SE eyin le da ni. Won MBE yin e si nse bi Olorun. Eyin ko we Wasiu si Islam, islam ni won bi si. Kinwa ni epe. E lo SE suuru

  • @oluwoleshekoni8140
    @oluwoleshekoni8140 11 днів тому +1

    Fantastic message to K1 by Baba Akewugba Gold.❤

  • @SolomonAdegbenle
    @SolomonAdegbenle 12 днів тому +3

    Oro Wasiu tidi FEPE SI 😂😂😂😂.

  • @RealVoice-p8t
    @RealVoice-p8t 7 днів тому

    Ofo ati àdánù ko mọ ba Allah ati Muhammad ati awon ẹgbẹrun kan omo eru fulani.

  • @akindelegiwa5874
    @akindelegiwa5874 12 днів тому +4

    Awon afa wonyi hun se bi olorun olodumare, igberaga awon afa wonyi ti poju

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +2

    E wo gbogbo won, ha! Gbogbo yin de un se amin nibiti won ti un sepe fun omo olomo. Eleyi ko dara o. E beru Olorun o. E ranti wipe oju Olorun un wo gbogbo yin pelu awon epe ti e un se😮.

  • @ganiyuabdul7008
    @ganiyuabdul7008 11 днів тому +2

    Iro ni gbogbo e. Kini itan yi nise pelu oro Wasiu ati awon Alfa. E lo tun aarin yin se. Olorun ko lo ran yin lo si ile Wasiu lati lo gba N8000000 nibi adua oku Iya re. E lo yi iwa yin pada.

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +2

    Eyin afaa yi e de beru Olorun. Sebi eyin na bimo tiyin. Sugbon Olorun koni fi Wasiu Ayinde sile

  • @johndada3500
    @johndada3500 12 днів тому +3

    Story Akewugbagold tima unpoju Irolode maun muwa, come on paap.

  • @halfnigeriaandhalfghana6447
    @halfnigeriaandhalfghana6447 11 днів тому +3

    Alhaji Akeugbagold pelu awon itan ofo. Iro lasan 😅😅😅😅😅😅😅😅 Arab level 😅😅😅😅😅

  • @johndada3500
    @johndada3500 12 днів тому +5

    Irò lomò Eyin Alfa Yoruba.

  • @BlessedMother1
    @BlessedMother1 8 днів тому

    Iya osi Baba o si fun Wasiu , e jowo Alfas e dariji omo oku orun .

  • @BabalolaOluwole-o3n
    @BabalolaOluwole-o3n 11 днів тому +2

    Olopa ewo lepe

  • @akinladeoluwafemi3599
    @akinladeoluwafemi3599 10 днів тому

    Gegebi Abiyamo aye yin tamajise oun gbogbo tase laye fun olorun toda gbogbo enia atokunri atobirin Edarii jiii Ewo ti olorun orun Oluwa yio dariji gbogbo wa amiiiiin Eseun pupooo Sir

  • @OlalekanOlatoye-xo7hh
    @OlalekanOlatoye-xo7hh 11 днів тому

    Iro lasan ni story akeugba gold arabu level

  • @adesuaolanrewaju752
    @adesuaolanrewaju752 8 днів тому +1

    This one na mumu,when did America said that there is no God. They wrote inside their money that in God we trust. Tell this goat that America belief in God,natural disaster can Happen anywhere in the world

  • @YushoofSulaiman
    @YushoofSulaiman 11 днів тому +1

    Won ti sepe sugbon oro ti osoyi ofe Wala sinu ayere

  • @walesal7906
    @walesal7906 12 днів тому +1

    Akeugbagold oni itan iro, IRO PO BABA😂😂😂

  • @bolaelegbede7843
    @bolaelegbede7843 11 днів тому +2

    Awon alfa isonu

  • @BelloKabiru-m9l
    @BelloKabiru-m9l 5 днів тому

    Awon Alfa na alagbe ni yin

  • @AkanjiJamiuGbemisola
    @AkanjiJamiuGbemisola 11 днів тому +2

    Back to sender

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +1

    Sebi eyin musulumi wonyi bu awon Oba ile Yoruba. Sebi oro buruku gbogbo ni eyin musulumi so si baba wa Ooni of ife ati awon Oba miran ni ile Yoruba. Afaa melo ni o wa sita lati wa se show kilo fun Mufti iwo.

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +1

    Iru Awokose wo ni o wa ni ara awon eru wonyi tori Olorun 😮

  • @comfortadeoye5748
    @comfortadeoye5748 12 днів тому +4

    Kosi ohun ti yoo se wasiu

  • @rajiadeyinkaoyenihun1115
    @rajiadeyinkaoyenihun1115 12 днів тому +3

    Eleyi ti po ju Alfa e jowo e se pelepele

  • @taiwoloye4877
    @taiwoloye4877 11 днів тому +1

    Eeni emi Idariji kankan. Wahala yin ti poju. O ga o

  • @enochekundayo5078
    @enochekundayo5078 11 днів тому

    Good response 👍.

  • @comfortadeoye5748
    @comfortadeoye5748 12 днів тому +2

    Nkan ti oro awon. Alfa maa dumi,eyin si ni esi alafia lesi yin

  • @balogunomosesan532
    @balogunomosesan532 4 дні тому

    Ride on k1

  • @BabalolaOluwole-o3n
    @BabalolaOluwole-o3n 11 днів тому

    Alfa gold hmm , alfa dada

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 12 днів тому +1

    Awon fulani Ile Ilorin kosi oba Ile Yoruba Kankan tojo eyin alfa Ilorin yii loju,

  • @johndada3500
    @johndada3500 12 днів тому +2

    Ose ose eyin ni kilode .Emaba Nigeria je ,Eti fun Nigeria loruko buruku.

  • @AdewaleEmmanuel-vx5ve
    @AdewaleEmmanuel-vx5ve 12 днів тому +2

    Ko si ohun tio se wasiu, Alfa etu ganu

  • @LawalShitu-p2o
    @LawalShitu-p2o 11 днів тому

    ejowo nitori ti olorun oba toni emin gbogbo wa edarijin wasiu ayinde edakun tori anonbi monmmed ejowo

  • @yemisi5812
    @yemisi5812 11 днів тому

    Inu mi dun wipe Akehu gba gold so otito. Emi na gbo nigbati Wasiu nso oro fun Akewu gba gold. Olorun ko ni kuru Lakaye nyin.

  • @abdulrasaqyusuf4884
    @abdulrasaqyusuf4884 11 днів тому

    This batters left and right has further exposed the rot both ways. If he had refused to apologize, the way and utterances of some clerics on the issue does not show there is a soft landing.

  • @FataiAdeshina-j3o
    @FataiAdeshina-j3o 12 днів тому +1

    All what Alfa Akeugbagold saying simply a story teller. All the references tabled by Alfa Akeugbagold just shenanigan.

  • @pitanKayode
    @pitanKayode 12 днів тому +1

    Alfa should take things easy when something like this is happening among urself . He will has reason why he said that to the Alfas .

  • @toyinorry4659
    @toyinorry4659 11 днів тому +1

    EYIN ALFA YII TI JARE TELE BUT ASHEJU YIN TI JE KI E WA GUILTY

  • @ademuyiwa3898
    @ademuyiwa3898 11 днів тому +1

    Awon were oloshuka oshi

  • @adefemiojokanke5222
    @adefemiojokanke5222 12 днів тому +4

    Epe kopada sori elepe

  • @BabalolaOluwole-o3n
    @BabalolaOluwole-o3n 11 днів тому

    Alfa gold soro dada awon alfa elepe yen nio da

  • @bukolaosun4471
    @bukolaosun4471 12 днів тому +1

    Se eniyan Olorun ni awon afaa wonyi bayi? Ha! O mase o.

  • @olabodeolajuwon4318
    @olabodeolajuwon4318 11 днів тому +1

    Werey nse gbogbo yin eyin alaseju alainise yi atomode atagba yin

  • @TawaRufai
    @TawaRufai 11 днів тому

    Eyin afa yi alabuku niyin eran ti olorun eyin naloma tiyin

  • @FolorunshoSulaimaan
    @FolorunshoSulaimaan 11 днів тому

    This K1 song is an old song na.

  • @adesuaolanrewaju752
    @adesuaolanrewaju752 8 днів тому

    He said he didn't make any mistake because he didn't said it to anyone directly but they got his recorded voice. That's why he refused to apologise

  • @loladeyetunde5536
    @loladeyetunde5536 11 днів тому +1

    Am disappointed in the so called Alfas what a disgrace

  • @SanyaoluDavidSunday
    @SanyaoluDavidSunday 12 днів тому +2

    Quran is a story book of arab also allah and God are not the same with olorun.

  • @IsmailaAyuba-h8v
    @IsmailaAyuba-h8v 12 днів тому

    O ye ki awon Alfa se suruu , Wasiu lo peyin, kilode ti e le se suruu lasiko yi. Eranti pe eyin loro to ba ti jabo ki I se ko mo n. Ki ebi ahun ko ma di ti ana re.e se suruu

  • @Adebayo-b4z
    @Adebayo-b4z 8 днів тому

    Olorun ma duro tie o

  • @morirearike
    @morirearike 8 днів тому

    As much as I don't support the ganusi talk
    Buburu ko gbodo sele si Wasiu o

  • @adewaleadeniran2534
    @adewaleadeniran2534 8 днів тому

    Old music nii

  • @comfortadeoye5748
    @comfortadeoye5748 12 днів тому +2

    Eyin naa ni gbogbo igba

  • @YusulOlatude
    @YusulOlatude 12 днів тому +1

    To enu batin kun eyan ju....Koda rara ati rara..

  • @maryamlawal908
    @maryamlawal908 12 днів тому

    Ganucios ganu😅😅

  • @bolaabifarin9638
    @bolaabifarin9638 11 днів тому

    Ayuba ofi igba kan se muslumi o se se gbe han iyawo re Christian ni on se labele ni.

  • @temitopebusari9407
    @temitopebusari9407 12 днів тому +2

    Haaaaaa

  • @bolanlebakare-nf1xm
    @bolanlebakare-nf1xm 12 днів тому

    Eyin Alfa Yi se Hun Se bi tout bayi, oloopa ewo ni tepe

  • @johndada3500
    @johndada3500 12 днів тому +2

    Unje eyin mo olorun lokan tifi lo ti Tani Olohun mole abi kilode ti efiunrope esin Muslim nikan ni esin, Oniro niyin eyin Alfa Yoruba yi.

  • @2b4d
    @2b4d 8 днів тому +1

    These so called set of hypocris, Imagine!! Alfa has the audacity to insult the Number 1st king of the whole Yoruba race worldwide.

  • @Adebayo-b4z
    @Adebayo-b4z 8 днів тому

    Alfa indeed, he doesn't have children abi

  • @omolewabello3467
    @omolewabello3467 12 днів тому

    Ayah kini epe wa ninu Quran eyin alfa elepe wonyi
    Gbogbo eyin ti e o ni anfani lati de ibi oku yi ni ara nta yi

  • @idowuolasoju4968
    @idowuolasoju4968 11 днів тому

    Alfa e wo ni tepe bayi o?

  • @kathrinaoloyede4660
    @kathrinaoloyede4660 12 днів тому

    "Ẹyin afaa ẹ wa ganu" Ha! Irọ́ n la ni eleyi Wasiu never said this! He never spoke to the Alfas.. Inu Ile rẹ lo ti n ba ẹni kan sọ̀rọ̀.. He did not speak rudely to any afaa. Kin lo de ti ẹ fẹ́ fi ọmọ owú pa eera?
    Igba ti àwọn afaa jade ti wọn n bu odindi Ọba Alade, ta lo mu yin si? Nigbati agba afaa jade ti o pe Ọ̀ọ̀ni nii ẹranko,, Minnie àwọn agbagba AFA ṣe si? Kinni de ti ẹ o fi apẹrẹ ẹ̀sìn alafia han wa nipa iṣe ati iwa yin?

  • @AdewaleAwall
    @AdewaleAwall 11 днів тому

    Emo oun ti esooo

  • @comfortadeoye5748
    @comfortadeoye5748 12 днів тому +1

    E lee fesi ko bawa nile yoruba

  • @MrkevinSmith-nu3yu
    @MrkevinSmith-nu3yu 12 днів тому

    Elese kankan eni kankan iro ni yin

  • @Wicked12-u2e
    @Wicked12-u2e 12 днів тому +1

    Alfa oma shofo tomotomo.iku to gbona loma ku.
    Eyin Oloriburuku gbogbo.Islam ofo

  • @morirearike
    @morirearike 8 днів тому

    Alfa kilo de
    Olopa ewo ni tepe
    E fi ija folorun ja

  • @OgunleyeBola-v3e
    @OgunleyeBola-v3e 5 днів тому

    Kilode? Epe yi ti po ju.

  • @olabodeolajuwon4318
    @olabodeolajuwon4318 11 днів тому

    Talo ran e nise Ko ma sun e ti siere

  • @FestusOlanrewaju-t7b
    @FestusOlanrewaju-t7b 7 днів тому

    Why alfa dey curse like dis, shebi u be alfa

  • @AdewaleAwall
    @AdewaleAwall 11 днів тому

    Let's talk with sense and knowledge

  • @CoachOlusegunIbitoye
    @CoachOlusegunIbitoye 12 днів тому +2

    Awon ganusi united😂

  • @kazeemolaniyi5667
    @kazeemolaniyi5667 11 днів тому

    Is a lie this live is old not new song with ganu si

  • @adebayoyunus2610
    @adebayoyunus2610 11 днів тому

    If you want to accept, accept Islam with sincerity and for ALLAH sake, if you accept Islam because of human being, you go out of Islam because of human being.
    If you want to do good , do good because of ALLAH, it is only ALLAH can reward you, but if you do good because of human beings , your goodness would not last long and you will not have any reward from ALLAH. Baba please go outside Nigeria, see how people are accepting Islam with sincerity. This is the consequences of awon Alfa onibidiah. Do pure Islam. Follow ALLAH and his prophet's teachings.
    If you want to do the right thing. You should have gone to his mother's ritual burial not Wasiu house's . Going to Wasiu house's is going there to collect money which is not allowed in Islam.
    Fidau is not allowed in Islam, in pure Islam, apart from undiluted Islam.
    All the prophets of ALLAH have work as source of their income.

  • @BabalolaOluwole-o3n
    @BabalolaOluwole-o3n 11 днів тому

    And you said esin alafia is religion

  • @omolewabello3467
    @omolewabello3467 12 днів тому

    Ara lo nta yin eyin ti won o pe