السلام عليكم ، eku ise Ustaz, sugbon e maa je ko je wipe awon musulimi nikan ni e maa se atunse Oro won, nitori wipe Olohun fun yin ni ebun agbekaale pupo,
Alhaji Adegunwa! Ninu laakaye yin, se ki won o pe Anobi pe ko gba awon ni won npe ni hype? Dajudaju, kii se hype, ebo ponbele ni, e o si le ri ahalu sunnah kan ni gbogbo agbanla aiye ki won o so bee ayaafi eni ti o ba fee se ofo ni aiye ati alukiyamon. Alhaji Adegunwa, o daa yin loju pe nkan otooto ni enso kii se nkan e npe ni hype niyen. Ati Adegunwa ati iwo alfa shia yi, WaLlahi agbako ni eyin mejeeji. Adegunwa so pe alfa salafi ni onse adura yen. Alfa shia si ndaa lohun. Eyin mejeeji wanda gbogbo nkan ru mon ra yin lowo. Alfa shia ni awon le pe awon eni oloun bii Ali, iya wa fatimon, awon mon pe won o ni agbara lati se nkankan fun awon pelu agbara won sugbon pelu iyonda oloun ni, e joo tori oloun iyato da laarin awon alagbako yi pelu awon ti npe jeesu ati awon nkaan min? Eyin musulumi ee si fi ejo awon eeyan yi sun ijoba, abi iru iruju wo ni eyi bay
Ustaz Jamiu Adegunwa, you can't compete with Alfa Tolha in Islamic knowledge of presentation and analysis, just focus on your comparative analysis or presentation.
Wallahi otitoni ustaz jamiu so
Jazakumullahu Khaira Al Ushtadh Tolha....long life to you.
Aamina ya rabil-alamiina my honourable sheikh and wishing you the same InshaAllah. My regards Sir
Thank you Ustaz for making your point without insulting anyone
You're highly welcome Sir and may Allah accept it as an act of ibaadah from us together INSHAALLAH
As a muslim, you only call GOD(Allah) for help and not human being, never…
Ustaz jamiu lo wa loju ona
Ko to fun Muslim ko pe enikankan lehin olorun to dawn.
السلام عليكم ، eku ise Ustaz, sugbon e maa je ko je wipe awon musulimi nikan ni e maa se atunse Oro won, nitori wipe Olohun fun yin ni ebun agbekaale pupo,
وعليكم السلام ورحمة الله وبركاته شيخنا الفاضل
Okay, Ọlọhun a ṣe ni irọrun fún wa ínshaAllah
E tun se igbiyanju Lori kika nipa ESIN Isese, ki e si maa proof re fun wa ninu iwe won, Koda ki e tun maa Fi ran wa bi e se maa n Fi eleyii ran wa .
Noted InshaAllah
Alhaji Adegunwa! Ninu laakaye yin, se ki won o pe Anobi pe ko gba awon ni won npe ni hype? Dajudaju, kii se hype, ebo ponbele ni, e o si le ri ahalu sunnah kan ni gbogbo agbanla aiye ki won o so bee ayaafi eni ti o ba fee se ofo ni aiye ati alukiyamon. Alhaji Adegunwa, o daa yin loju pe nkan otooto ni enso kii se nkan e npe ni hype niyen. Ati Adegunwa ati iwo alfa shia yi, WaLlahi agbako ni eyin mejeeji. Adegunwa so pe alfa salafi ni onse adura yen.
Alfa shia si ndaa lohun. Eyin mejeeji wanda gbogbo nkan ru mon ra yin lowo. Alfa shia ni awon le pe awon eni oloun bii Ali, iya wa fatimon, awon mon pe won o ni agbara lati se nkankan fun awon pelu agbara won sugbon pelu iyonda oloun ni, e joo tori oloun iyato da laarin awon alagbako yi pelu awon ti npe jeesu ati awon nkaan min? Eyin musulumi ee si fi ejo awon eeyan yi sun ijoba, abi iru iruju wo ni eyi bay
eran ni e Iwo man yi
Ustaz Jamiu Adegunwa, you can't compete with Alfa Tolha in Islamic knowledge of presentation and analysis, just focus on your comparative analysis or presentation.
Adegunwa does not supposed to interfere in the affairs of knowledge bcs you don't understand anything about Islamic knowledge.
Keep deceiving yourself