EJOWO EDARIJIMI OMO YORUBA EYI NIDI TI MOFI JE IDINA SI IGBOHO ATI OMO YORUBA LAPAPO O KONI SELE MO

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 11 січ 2025

КОМЕНТАРІ • 82

  • @AdeyemiOyetunde-dz1vm
    @AdeyemiOyetunde-dz1vm 3 години тому +1

    Gege bi imoran temi, YORUBA lo ma nso pe bi Owo ko ba SE San ama nka sori ni, mo gba Baba WA Oloye Igboho Oosa ATI Baba WA. Akintoye pe a o ni pada lati gba ominira Yoruba NATION.

  • @sikiruoluwasegun6804
    @sikiruoluwasegun6804 16 годин тому +6

    All we won't is totally lndependent freedom for Yoruba Land, Yoruba nation no going back, igboho ooooosa,madawon loun o,won foju jore otani won o

  • @richrich6950
    @richrich6950 7 годин тому +1

    Awon baba ti o ni emi ida rijin , at that age still kept malice 😮baba don't change ooo continue 😮till 200 years

  • @debbieolopade3017
    @debbieolopade3017 19 годин тому +2

    Igboho Orisha Baba Dami continue with your good work that you are doing, the Lord will see you through to the end, and by the power of the Almighty God, you will take us to our promised land (the Yoruba Nation) by the grace of the Almighty God in Jesus mighty Name, Amen. We love you and we appreciate the good work that you are doing for US, the Yoruba people, and by the grace of God, we shall have our Nation by the Grace of the Almighty God in Jesus mighty name, Amen. Thank you for the good work. The Lord will crown all your efforts with success and glory in Jesus mighty name, Amen. We are grateful to you and our Father, Emeritors Steven Adebanji Akintoye for the good work you are both doing to take us to the promised land in Jesus mighty name, Amen. We appreciate you both for the good work. God bless you both and your families in Jesus mighty Name name, Amen.

  • @CharlesKayodeOyelaja
    @CharlesKayodeOyelaja 9 годин тому

    Yoruba Nation Now, no going back.Arekereke ti won fe fi mu Sunday Igboho ni won fe lo, Olorun ko ni fun won se loruko Jesu. Ki o ma pa oro ominira ti o, bi a ba gba ominira wa,lesekese ni awon ajeji ati awon odale maa fi ile wa sile lai janpata.Independence is our primary role now,- a task that must be done, while Security of our land(country) is secondary. Well done.

  • @abosedeoyibokure6767
    @abosedeoyibokure6767 12 годин тому

    Obasanjo kii se omo Yoruba.omo yibo ni kii se baba tiwa.Ole ni ika si ni pelu .Amo sa ko si ohun to le da Yoruba Nation duro tori pe ase Eledumare ni.Ti Obasanjo ba ni ko ni soju out a seyin laipe n̈I paapaa
    Yoruba Nation no going back Yoruba Nation now now

  • @taofikilawal5127
    @taofikilawal5127 4 години тому +1

    Yoruba nation know going back

  • @OmitogunDennis
    @OmitogunDennis 17 годин тому +3

    E ku ishe o 🎉. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.

  • @azeezola6695
    @azeezola6695 2 години тому +1

    Baba obasanjo OLORUN OBA ju e lo lagbara OLORUN OBA ELEDUMARE oju e lase maa pin loteyi waa wa lo pokunso... Igbeyin ooole daa na tele......

    • @massbtv
      @massbtv  2 години тому

      AMIN ASE EDUMARE

  • @TitusOjuade
    @TitusOjuade 16 годин тому +1

    Chief Dr Sunday Igboho Oosa maa ba ise naa lo.No going back.Eyin agbaagba ile Yoruba e seun gan an ni.Sugbon e jowo e duro sinsin Lori ipinnu yin.Yoruba Nation yio gbe gbogbo wa o.Yoruba Nation la fe ni kia kia,no going back.Eto aabo yio duro ti a ba Koko gba ominira orilede Yoruba Nation.Etan lo wa nibe PE ki Chief Sunday Adeyemo Igboho Koko se ti abo saaju ominira orilede Yoruba Nation.Yoruba Nation first then security follows.

  • @CharlesKayodeOyelaja
    @CharlesKayodeOyelaja 9 годин тому

    Lati 1978 ni Obasanjo ti ndale Yoruba, baba Yi mo wipe oun o le lenu rara ti a ba gba ominira baba Yi to se ibi lopolopo si away Yoruba nitori iwa ilara ati igbonara ti o NBA aye baba Yi jagun, e gbo eyi, eniyan ni baba Olusegun Obasanjo kii se Olorun, ki enikeni mase bee rara, o Fe, o ko, Olorun-Oga-ogo funrarare lo ma gba wa ti O so ma fun wa ni ominira to a fe loruko Jesu Kristi.

  • @TaofeeqQuadri-k7f
    @TaofeeqQuadri-k7f 19 годин тому +2

    UP YORUBA NATIONS NO GO BACK

  • @FunmilayoElugbaju-lu3dy
    @FunmilayoElugbaju-lu3dy 17 годин тому +1

    Ki oloye sunday lgboho ma ti wa sile omo araye ko ni ri won mu ooo amin

  • @TaofeeqQuadri-k7f
    @TaofeeqQuadri-k7f 19 годин тому +2

    God bless Yoruba Nation

  • @olunladeidowubabatunde5881
    @olunladeidowubabatunde5881 20 годин тому +2

    Yoruba nation is all we want no going back

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 10 годин тому

    MBaba Ọbasanjo kilode, kini awa ọmọ Yoruba gba lọwọ yin, ę fi wa lọrun silę. Ę ti darugbo, Ki ę maa ranti ọjọ ati sun yin

  • @debbyakinleye5024
    @debbyakinleye5024 20 годин тому +2

    Agbaiya ni Obasanjo, oloriburuku omo ibo

    • @olusolaadesina4623
      @olusolaadesina4623 13 годин тому

      Both young and old will curses to baba osi yen wicked and unconscionable man

  • @oluwaseyiamupitan8640
    @oluwaseyiamupitan8640 17 годин тому +1

    No going back on yoruba nation, yoruba nation first before any other things..

  • @charlesprince5993
    @charlesprince5993 20 годин тому +1

    Oluwa seun lopolopo nitori owo Oluwa ni eyi ti asiri fi ntu ki ona tete la fun irin ajo ominira wa Olorun ju eniyan o baba Obassanjo e lo ronu o se efe ko awon ebi yin lo si odo Fulani

  • @ceciliaolaleye2184
    @ceciliaolaleye2184 6 годин тому

    Mass B thank you for your program, Yoruba Nation NO GOING BACK. We want Yoruba Nation first before we drive Fulani away. After we secure our Nation then we can be bold enough, and the power to drive our enemy away. No I dont think this man is a real Yoruba.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 11 годин тому

    Gbogbo eyin governors ile Yoruba e ko gbogbo owo security vote ti e gba lowo federal government fun sunday Adeyemo lgboho kuo fi protect ile Yoruba fun wa oooo

  • @TijaniShuaib-ci7gt
    @TijaniShuaib-ci7gt 18 годин тому +1

    Yoruba nation not going back ❤❤❤

  • @charlesprince5993
    @charlesprince5993 20 годин тому +1

    Laelae oro wipe ki Oloye Sunday Igboho pa yoruba nation ti ko le sese o.asepo ni o

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 11 годин тому

    Ti Ganiyu lge Abiodun Adamu ko ba le jade lati ja fun wa ni ile Yoruba ki o fi oye Areonakankafo sile ooooooo

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 8 годин тому

    Dr Chief Sunday Igboho Ooşa should not leave Yoruba Nation aside bcos he has been on the race of Yoruba Nation for a long period, he should continue on the Yoruba Nation. YORUBA NATION NO GOING BACK

  • @olusolaayindefakeye4426
    @olusolaayindefakeye4426 20 годин тому +1

    Eni ti ko fe ominira fun ile Yoruba ki o fori sole to ba nbinu. Bi won fe bi won ko, Eleda ti da wa lowun.Yoruba Nation, no going back.

  • @oladeleabiodun8059
    @oladeleabiodun8059 20 годин тому +1

    Obasanjo kise asoju awa omo Yoruba Prof.BanjiAkintoye pelu chief Sunday Adeyemo ooosha ni asoju awa omo yoruba.yoruba Nation no going back ijn

  • @TitusOjuade
    @TitusOjuade 17 годин тому +3

    Baba Obasanjo, jowo nitori Olorun fi awa omo Yoruba sile lati bo lowo Nigeria ati Fulani.Awon ti o le asoju wa,ni Baba Professor Banji Akintoye ati Chief Dr Sunday Adeyemo Igboho Oosa.Baba Obasanjo ko le da wa duro lati gba ominira orilede Yoruba Nation nitoripe baba Obasanjo je eyo enikan nigbati gbogbo awon omo Yoruba je 60 millions.Ko ye ki eni kan ju gbogbo awa omo Yoruba lo.Ko le seese o.Yoruba Nation la fe ni kia kia.Ko si ipadasehin rara.

  • @olayinkawilliams5865
    @olayinkawilliams5865 16 годин тому +1

    OBASANJO IS NOT A FULL YORUBA MAN,HIS FATHER IS FROM ANAMBRA STATE

  • @amosomotunde9341
    @amosomotunde9341 20 годин тому +1

    Baba Obasanjo ati Aare Tinubu Enyin Mejeji O Leda Gbigba Ile Yoruba Gbogbo Omo Yoruba Ju Yin Lo Ki E Lo Joko Sibi Kan Jare Yoruba Nation Mawaiye o Lase Olorun Oba

  • @margaretosiname4580
    @margaretosiname4580 4 години тому +1

    I disagree, Oloye shouldn' step aside to drop Yoruba Nation to face the security of all Yoruba land. No way, it's another way of tricks to stop Yoruba Nation. Let the Govt. fight for the total security of the Country. Enough of this SLAVERY MENTALITY. OLOYE IGBOHO and Professor Banji Akintoye can be trusted as our leader.

  • @Tunde-y1g
    @Tunde-y1g 19 годин тому +1

    Sebi eyin le n pewon ni baba, won o kin se baba, ota wa niwon, won korira wa, won tun gbabode funwa.

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 8 годин тому

    Dr Chief Sunday Igboho Ooşa should face the Yoruba Nation to lead us over the red sea of Nigeria. I for one too, i'm not putting hand on that opinion that Sunday Igboho Ooşa should leave Yoruba Nation and face the security of Yorubas, The security of Yoruba land is the duty of the government

  • @oladipupojimoh2985
    @oladipupojimoh2985 14 годин тому

    Yoruba nation no going back

  • @JadesanmiOgbonmuwagun
    @JadesanmiOgbonmuwagun 16 годин тому +1

    The moment is totally wrong, Sunday should not listen to that .

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 11 годин тому

    Kini ise awon uniform men ni ile Yoruba ti won ko le pese abo fun wa ni ile Yoruba kini won ngba salary fun.se sunday Adeyemo lgboho je osise ijoba nigeria ni....

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 10 годин тому

    Prof. Banji Akintoye Stephen Emeritess Merituss is our father, leader and Chief Sunday Igboho Ooşa is our Representatives, our mouth speaker in Yoruba Nation. Ọbasanjo is not a Yoruba man, his came from Anambra his an obstacle to Yoruba Nation. Almighty God will clear him away from the Yoruba Nation's road by the power of the Almighty God. Amen Amen Amen

  • @TitusOjuade
    @TitusOjuade 17 годин тому

    Yoruba Nation ni Koko.Ti a ba gba Yoruba Nation tan oro abo kekere ni o maa je nitoripe a o ni agbara ofin lati fi de awon Fulani buruku to npa awon eniyan kaakiri.Ti awon Fulani ba le ri baba Obasanjo gbe tabi awon omo re ohun ti a nso yii ki ba ti ye baba Obasanjo.Ki Chief Dr Sunday Adeyemo Igboho Oosa mase pa ise to lori oro ti rara.Nitoripe ti o ba gbe segbe kan,ti ko sise to o mo bi nwon se maa se aida fun Oloye Igboho ni won maa ma wa.Ki ijijagbara yii maa te siwaju lo dara o.Yoruba Nation la fe ni kia kia,ko si ipadasehin para.

  • @josephoguntade4483
    @josephoguntade4483 5 годин тому

    O ku die ka to fun eni to n soro yi. Se Oloye Sunday Ighoho je Soja ni tabi Olopa Nigeria. Ki ni ise àwon eso alabo ti ijoba n sanwo fun un! Babanla isokuso ni eniyen n so. Oro amukunmeko gba ni. Ki nwon pin Nigeria ki onikaluku peto aabo fun Orileede won. Yoruba gbodo kuro ninu Nigeria lagbara Eledumare ati isowopo gbogbo àwon Alale ile Yoruba.

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 20 годин тому +1

    Kosi Omo oko Yoruba kan tiko ni nife si ominira Yoruba sugbon iya cassette tifi Ori gbale, omo ale, omo fulani

  • @aderibigbematthias8646
    @aderibigbematthias8646 19 годин тому

    Chief Sunday Adeyemo Igboho , emi o faramo o ki e fi agitation sile fun igbogun to awon Fulani o, awon araabi lo nsoro yen o, awon elete alarekereke awon firi nidi oke ni awon to gbimoran yen o

  • @debbyakinleye5024
    @debbyakinleye5024 20 годин тому +1

    Obasanjo you can’t stop us Yorubas, you’re not our Representative, whether you like it or not Yorubas are out of Nigeria. Break Nigeria now

  • @olusolaayindefakeye4426
    @olusolaayindefakeye4426 20 годин тому +1

    Leyin ti e ta gbogbo owun ini Nigeria,fun ara yin, sibe e ko ni itelorun. Olorun ni Alabama. Bi e fe, bi e ko Yoruba a gba ominira..

  • @mathewajayi63
    @mathewajayi63 20 годин тому

    Yoruba Nation la n fe

  • @shekinahgloriousvoices8103
    @shekinahgloriousvoices8103 17 годин тому +1

    Obasango is not our representative only professor banji akintoye and chief Sunday igboho are our representatives Yoruba Nation lanfe ooo no going back, what has yoruba people done to you Obasango and tinumbu

  • @estheroluseun6188
    @estheroluseun6188 9 годин тому

    Ko si oro nibe. E ma je ki won gberu wa lati ehin. Iwakusa to nlo nko. Oloye CSI can not change his mind on Yoruba Nation agitation. We are talking about those that want to take over the whole of Yorubaland. Ko si oro ni be o. Oju a foo fo tan IJA lon da sile. Won fe de panpe sile ni o. Olorun a segun gbogbo awon ota Ile Yoruba lai ku enikan ninu won. Aamin

  • @adebayoishadipe5582
    @adebayoishadipe5582 20 годин тому

    Yoruba nation lafe no going back

  • @mohamedbombata739
    @mohamedbombata739 10 годин тому

    No. Oloye Igboho must not stop Yoruba nation's work. Let Makinde and other governors do their jobs. The governors' jobs are to protect the people of their states. What are they doing with the security money?

  • @olusolaadesina4623
    @olusolaadesina4623 13 годин тому

    Ti fulanis bawa gbe baba osi yen lo pa danu dat will be better for us

  • @bisolawe1996
    @bisolawe1996 10 годин тому

    EYIOWUAWI TOLUWA OBA LASE

  • @M.S.Ademola
    @M.S.Ademola 17 годин тому +1

    Obasanjo is not our leader and he cannot stop us from getting a Yoruba Nation. Our leaders and representatives are Prof Banji Akintoye and Chief Sunday Adeyemo Igboho. Yoruba Nation no going back. Yoruba Nation now now now.

  • @deesadotun3864
    @deesadotun3864 19 годин тому +1

    Ki wean odo bere si ju Oko fun baba Yeye yi

  • @abosedeoyibokure6767
    @abosedeoyibokure6767 12 годин тому

    Isokuso gbaa nio n so.Se Sunday Igboho nba won gba security vote ni abi kilo kan pelu security Nigeria. Panpe nla ni won fe de sile yi.Ti a ba ti gba Yoruba Nation wa security ma de automatically tori awon oloriburuku fula 13:34 ni wonder ko ni ni anfani lati wo orile ede wa mo

  • @bisolawe1996
    @bisolawe1996 10 годин тому

    Imo Ota koni jo NO PEACE FOR WICKED PEOPLE. JESUS CHRIST OF NAZARETH IS THE ONLY FINAL SAY AMEN

  • @olufunmitijani3783
    @olufunmitijani3783 14 годин тому

    lgboho madawon

  • @ceciliaolaleye2184
    @ceciliaolaleye2184 6 годин тому

    Please Mass B, don't play that guys video anymore. You do not want to confuse people.

  • @cosmasadebowale5877
    @cosmasadebowale5877 20 годин тому

    This audio makes no sense rather than kill Yoruba nation mission.

  • @AkindioseFrancis
    @AkindioseFrancis 13 годин тому

    As for me I can never and will never trust OBASANJO for any reason if you really wants to know who is OBASANJO please call on GEN , OLUKOYE GEN ALANI AKINRINADE PROF WOLE SOYINKA , OKUNROUNMU E T C and if FELA ANIKULAPO ,is alive today he will tell you more about him hmmmmmm IGBOHO should be extra careful about YORUBA elders and leaders because most of them are more patriotic to the fulanis than their subjects and region because of money but history will tell on them and their children IGBOHO must be careful very very careful as I don't trust them because all means of getting Igboho is all what they are running after

  • @cosmasadebowale5877
    @cosmasadebowale5877 20 годин тому +1

    Obasanjo is a man with low integrity he so much believe only surface dressing while someone like Francis Adekunle Fajuyi believed in founder mentalist approaches

  • @MarculayOladeleayenibisi
    @MarculayOladeleayenibisi 5 годин тому

    Baba obasanjo it's not a good daddy Yoruba land

  • @allenade3618
    @allenade3618 39 хвилин тому

    Show your facts before you preach you are just burning our data. Leave your fans to comments

  • @EwaaunEwaaun
    @EwaaunEwaaun 19 годин тому

    Yoruba nation no going back

  • @deesadotun3864
    @deesadotun3864 19 годин тому +1

    Ki wean odo bere si ju Oko fun baba Yeye yi

  • @deesadotun3864
    @deesadotun3864 19 годин тому +1

    Ki wean odo bere si ju Oko fun baba Yeye yi