Hymn 237 - "Emi Mimo Olutunu Sokale Sarin Wa" - 46th Adult Harvest 2022

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 14 січ 2025

КОМЕНТАРІ • 5

  • @adetayodavid-u2f
    @adetayodavid-u2f 3 місяці тому +1

    HYMN 237
    Emi Mimo Olutunu
    Sokale sarin wa
    Ire Oba Olubukun
    Awa nse reti Re
    Nitoripe Ire ni Oba
    NIa Oba Olore
    Oba Emi sokale wa
    Awa nse 'retiRe
    Oba anu sokale wa
    Si ju anu wo wa
    Awa omo Re nwo 'ju Re
    Silekun anu Re
    Oba Mimo, Oba Olore
    Baba 'jo bukun wa
    Nitoripe Ire loba
    T'o bukun omo Re
    Oba mimo, Oba lye Tan 'mole Re fun wa Ire Oba kiki mole Awa nse reti Re
    Oba Mimo Oba lye Jowo wa bukun wa Nitoripe 'Re 'Oba anu Awa nse reti Re
    Emi Mimo Emi Olore
    Awa nse reti Re
    Oba Mimo sokale wa Wa gunwa sarin wa
    Amin🙏🙏

  • @tobilobashadrack6598
    @tobilobashadrack6598 2 роки тому +1

    I'd like to visit this church this year... An amazing choir

    • @niyijohn867
      @niyijohn867 Рік тому

      Me too oooo... USA here I come .. God help me 😢

  • @TaiwoFemi-ob1hx
    @TaiwoFemi-ob1hx 8 місяців тому

    FMF