AWUJO OMO ALADE ISELE OAU ILE IFE

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 29 лис 2024

КОМЕНТАРІ • 27

  • @princeakeemadebolaadedapo2668
    @princeakeemadebolaadedapo2668 Місяць тому

    Eku ise takun takun, amo oye ki ese afikun re pe ti Alaafin na ba pa ipoda won ma ranse si Ile Ife na koda ti Alaafin miran ba gun ori apere o ma wa gba opa ase ni Ile Ife, ise si yi bere lati ori Alaafin Sango

  • @isikalusunday4223
    @isikalusunday4223 Місяць тому +1

    Are Opitan eku ise takun takun, Oluwa yoo fun yin lokun ,agbars

  • @babatundekadejoh6964
    @babatundekadejoh6964 2 місяці тому +2

    Oloye Aare Opitan, asise tabi asiko ni Legba to nje o, Loyo gangan loruko e 😂😂. Tobaje Legba ni kolesi nigboro Aro loma fise ibugbe. E le pe ni LEWON abi LOGBA. Thanks

  • @suadahitv1684
    @suadahitv1684 2 місяці тому

    Amin yah rob 🙏💯❤

  • @BD-nn3fq
    @BD-nn3fq 2 місяці тому +1

    This is the reason we are calling for Yoruba nation. This kind of insult will continue if we still remain in Nigeria

  • @user-iu3dq3ot4k
    @user-iu3dq3ot4k 2 місяці тому +2

    Tani Ọlọhun ti ṣe ètò lórí ẹ.

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 2 місяці тому +3

    Yoruba e je ki a fura o,se eri bi awon Fulani se ni awa Omo-Oko yoruba tooto ko le n'ka won ni inu ile won,especially Obafemi Awolowo University ti Baba Awolowo fi owo ti nwo ko jo ninu owo cocoa ko ni Western Regional,Yoruba it's high time we come out of Nigeria, Because we Yorubas are the largest in the whole Africa.The insult that the Fulani who are foreigners passing upon us it's too much,Yoruba Nation no going back.

  • @irominimisrat7854
    @irominimisrat7854 Місяць тому

    Baba wa Areopitan lagbara olohun emi yoo gun pelu Alafia ara, pelu itan ti e nso fun wa yi ,Adupe .

  • @OluwatoyinPeter-q8e
    @OluwatoyinPeter-q8e 2 місяці тому

    Ilu eko nko se won o si nibi ogun ni

  • @ibiyimikaige4814
    @ibiyimikaige4814 2 місяці тому +3

    We can hear a fresh case of rubbishing the Yoruba by the VC, Senate and leadership of OAU. The organizers of the event should use this case to send a strong message. Sir, you and your team have been discriminated against. Get a brilliant lawyer to fight this case. Don’t appear weak. Yoruba, be strong on your own ancestral land. Forget the Omoluabi stuff. Yoruba are being mistreated all the time in the failed Nigeria.

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 2 місяці тому

    Pelu itan ododo, awon ota Ile Yoruba ngbogun tiyin ki itan yin ,oro yin, komaata leti gbogbo omo Yoruba mo

  • @suadahitv1684
    @suadahitv1684 2 місяці тому +1

    Mansa allah 🙏..am proud of ila orangun. Omo ogboye❤

  • @brightligan519
    @brightligan519 2 місяці тому

    Gbogbo inkan ti yoruba ni, Awon Fulani Fi ogbon magomago gbaa lowo yoruba,o ma seeo

  • @KREMADUKEOyelake
    @KREMADUKEOyelake 2 місяці тому

    Biku ile o pa ni, tode o le pani ni oro Iran Yoruba. Ara ita ko le wole, ti ko ba si ara ile! Bibeli wipe,ile kile to ba yapa si ara re ma n ……… ni. A o ki gbo buburu lenu abore ni Yoruba wi.

  • @carolinefowosire8188
    @carolinefowosire8188 2 місяці тому +2

    E jo sir,mo daba pe, ki Kiriji day, ki a je ki awon Oloselu wa ATI awon Oba, pon ayajo ojo yi laruge,ki won si fise holiday fun gbogbo Yoruba,

  • @comfortadeleye128
    @comfortadeleye128 2 місяці тому

    EKU ETO ALHAJI SEKOSI AGBALAGBA LADUGBO LEGBA TOLE KILOFUNNI WAHALA EYI TIWANPOJUO

  • @akeemadedayo9626
    @akeemadedayo9626 Місяць тому

    Kiriji is supposed to be Yoruba's unity or national day.

  • @brightligan519
    @brightligan519 2 місяці тому +1

    Everythings yoruba built with their forefathers sweats were conninly taken from them by the fulanis , what a shame,

  • @rufusaduibijola1897
    @rufusaduibijola1897 2 місяці тому

    E ku ise Oloye Aare Opitan

  • @suadahitv1684
    @suadahitv1684 2 місяці тому

    Biznllah 💖

  • @SundayAbayomi-pf8xr
    @SundayAbayomi-pf8xr 2 місяці тому

    Eku ise opolo

    • @KazeemBabatunde-my7ps
      @KazeemBabatunde-my7ps 2 місяці тому

      From example. Falana

    • @KazeemBabatunde-my7ps
      @KazeemBabatunde-my7ps 2 місяці тому

      Gani fawehinmi

    • @maryogunkuade2560
      @maryogunkuade2560 2 місяці тому

      E kú ogbón bàbá wa ààrẹ òpìtàn. Ọgbọn kò ní kú mọ ọ yín nínú. Ọlọrun a bá wa pa ina ote ní ilẹ̀ Yorùbá.

  • @ThomasAdisa-g5p
    @ThomasAdisa-g5p Місяць тому

    Please speak louder! You sounds fearful unlike you! Please no one can kill you or bring down your brain. Thank you by omoibadan gangan!

  • @yogunyemi
    @yogunyemi 2 місяці тому

    I won't blame the authorities of OAU Ile Ife. All kinds of people and organizations claim to represent Yoruba interest. We all saw how some tried to take over a radio station, storm Oyo Governor's office. Not only that, some of these groups openly support and call for the release of Nnamdi Kanu - someone facing criminal charges from FG, someone rabidly anti-yoruba. It's understandable if the OAU authorities don't want any of that wahala on their campus.