Aare Opitan, Baamotan, truth will always be bitter. Please don't be discouraged, many of us are really riding on the horse and we're drinking from the ocean of your knowledge. God Almighty will continue to bless you Sir
Aare Opitan, kawo-kaye loro Yoruba. "Eri lanwe enikan kiiwe irira" gegebi oro Yoruba. Kosi eniti o lebase yinje, owu ( Jealous ) londa won lamu. Won gbese ran elomiran ni sugbon "Atari ajanaku kii seru omode". Tani o sope ara orun ko ponmore? Otito loju, aroso koni eleyi "egan kosope koyin o ma dun. Ote nte enia.
Mo ranti igba ti Felix Owolabi ngba corner wole.. Mo wo awon ere boolu yen ri daadaa. Ko s'eni to fara kan boolu yen to fi wole lati corner.. Ooto ni mo ranti daadaa.
January 1966 ni àwọn soja Ibo pa Sardauna, Tafawa Balewa àti Akintọ́la pelu awon eeyan míì pelu nínú ìṣe ológun àti àwọn olóṣèlú. Ti wọ́n ò pa hóró ẹyọ kan nínú àwọn èèyàn tiwọn..
Aare onpitan iku koni pa e fun wa jare. Sauti tio nso itan ti baba baba e kole so .emi mope iro nla nio npa atipe sebi alagbe ni sauti o gbodo gbe alfa ga kiwon le na owo fun .sebi oun naa alfa ni kio losi epe kio sope oun ju elepe tabi olu epe lo.
Aree onpitan ile Yoruba, you are the best keep it 💯 up
Wow I love this aare opitan ,,,he is always saying the truth
You are absolutely 💯 the best historian
This man your are a hero of history
Aare Opitan, Baamotan, truth will always be bitter. Please don't be discouraged, many of us are really riding on the horse and we're drinking from the ocean of your knowledge. God Almighty will continue to bless you Sir
You are the best, thank you sir
Aare Opitan, kawo-kaye loro Yoruba. "Eri lanwe enikan kiiwe irira" gegebi oro Yoruba. Kosi eniti o lebase yinje, owu ( Jealous ) londa won lamu. Won gbese ran elomiran ni sugbon "Atari ajanaku kii seru omode". Tani o sope ara orun ko ponmore? Otito loju, aroso koni eleyi "egan kosope koyin o ma dun. Ote nte enia.
Kudos to you
I respect your courage ❤
Eku etoo sir ❤
Ijo ni wọ́n njó kiri.. Àti ẹbọra Òwu ati Gomina Adéléké..
Mo ranti igba ti Felix Owolabi ngba corner wole.. Mo wo awon ere boolu yen ri daadaa. Ko s'eni to fara kan boolu yen to fi wole lati corner.. Ooto ni mo ranti daadaa.
January 1966 ni àwọn soja Ibo pa Sardauna, Tafawa Balewa àti Akintọ́la pelu awon eeyan míì pelu nínú ìṣe ológun àti àwọn olóṣèlú. Ti wọ́n ò pa hóró ẹyọ kan nínú àwọn èèyàn tiwọn..
Beeni 1966 ni
Saw❤❤❤
Aare onpitan iku koni pa e fun wa jare. Sauti tio nso itan ti baba baba e kole so .emi mope iro nla nio npa atipe sebi alagbe ni sauti o gbodo gbe alfa ga kiwon le na owo fun .sebi oun naa alfa ni kio losi epe kio sope oun ju elepe tabi olu epe lo.
😂
Alfa Baba oba ke? Lati Ibo sibo? Agbedo.
First to comment
Baba you are just genius anyhow 😂❤❤❤
Aare Opitan Otito oro loma leke
Olohun wa pelu ee
😂