It is very sad that Nigerian govt has to negotiate with the bandits ( criminals ) . God Almighty we cry up to you , Pls arise and fight for us and deliver us from these evil and wicked ones in J N . Amen .
Gegebi e se n ka a yii gan lo se ri ti won fi gba ilu Ilorin mo Yoruba lowo. Afonja naa pe won fun ogun jija ni itan ti a gbo, sugbon ti won ko lati pada si Sokoto mo leyin ti ogun ti wa to ti lo tan.
Ekale sir ooo baba mi GBagedeimo EKU ISEN takun takun sir ooo emiyin yio gun ni agbara gbogbo awon ALA Len Ile Yoruba patapata ooo Yoruba nation no going back
E ku eto Baba Gbagedeimo. Tit for tat lo ye ki o je, ko wu emi pe ka maa negotiate pelu won. Mo nigbagbo pe die ninu agbara igbaani si seku nile Yoruba. Fifunwon lowo a je ki won tun maa ni anfaani lati tun maa fi owo yen ra nnkan ogun sii ni. Olohun Alaaanujulo a segun fun wa nile Yoruba.
Ohun itiju nla loye k'oje fun awon Gomina wa ni'le Yoruba ti aabo kofi si fun awa eniyan won. Anu awon omo ati aya won lonsemi nitori wipe kole si abo fun won leyin igbati oko won bati kuro nipo olori tan. Ati Aare ati Gomina, nigbati awon omo ilu ba nrerin, ekun ni won ma sun nitori wipe enikan koni gbin alubosa ko wa hu epa.
Babagbedeimo.do you know may be there was agreement between Bola Tinubu and the Fulani before he become president that he will use the Yoruba people as sacrifice to Fulani, may that's why he show unconcerned as they are killing our people.
Weldon sir BGI. EDAKUN TORO BARI BAYII TI JOBA NIGERIA KO BA RI TI WA RO, GBOGBO AWON OBA KINI WON NSE. AWON OBA WA GAN LO DABI PE AWON GAN NI ISORO WA BAYIO. OONI OF IFE OBA KENTA IN OGUN STATE AWUJALE TI ILE EGBA OBA EKO OLUBADAN ORANGUN TI ILA EYIN BABA WA KABIYESI E MA TI DAKE JU. SE AARE BOLA HAMMED TINUNBU LO FI GBOGBO YIN JOBA NI ? TE FI NBERU TE FI LE SORO EDAKUN IDOJUTI LE LEYI FAWA OMO YORUBA. ESE WO LASE GAN NA. OMO WA LOLORI OLOGUN ATI OLOPA O MA SE O.
No smoke without fire! Some Yorubas are involving in these dastardly act, we have seeing and hear source act in Ogun state. It's not even normal to determine whose tribe is involved if we have not catch up with anyone.
BGI, e jeki a gbadura ,ki Olorun se anuwa ni ile Yoruba, nigbati Tinubu ati awon gomina wa o leranwalowo. Pelu agbara ti Olorun fun ile Yoruba nipa nkan ibile,ki Yoruba dide pelu nkan ibile,ki won ran wa lowo. Asiko tito ni kiakia. Awon Oba wa o dasi oro na, akori Eni fojujo, toba ribe ejeka koju si Olorun Eleda wa, kowa gbawa,yio si ranwalowo ni oruko Jesu Amin.
E jo sa mo ki yin A be gbogbo Agba Yoruba dide o nkan to nsele yi ti npoju won nfi owo agbara gba yoruba loju Oni ife ati Alafin Oyo awon lo ye kan siwju fun Yoruba ki won ye sa sehin
B G I , Is it possible for you to write a personal letter to Gov Seyi Makinde on Dr Ganiyat and Abdul Mumini , for assistance from Oyo State Government on their release ? May be the Gov ,will take action . May God help us in Yoruba land in J N . Amen .
Ibon ti fulani ngbe dani ti ijoba gba won laye ni won gbe oju le tiwon fi nse eleyi to wun won layi ko si iberu ati eniti o ma biwon nitorina ni won se tunbo nko ara won wo ile nigeria. Fulani ti.ni won ngba owo ati wo ile lowo awon nitori eleyi ni won ko se dasi ati gbeja wa.
Nkan ti onse ijoba nipe nwon ti believe wipe awon ni ondibo fun awon so awa yoruba ko je nkankan loju nwon.gbogbo nwon pata ni Olorun man kolu ni agbara Olorun.
Boya won ko fe gbe ija yoruba nitori a so wipe a fe kuro ni Nigeria. Oye ki awa na wa ona ati ja. Ki Yoruba ye s'ojo mo. Ki won ye miliki gbaladun osi titi ti won afi pa won tan. Ojo buruku ni Yorubadice,. ki won ja fun ile won.
Nigeria is a carcas but we failed to accept it. Nigeria is finished. We don’t have a country. Yet, we think we have a country. I cannot say why publicly, I am beginning to have a negative view about our people.
So also the Governors in each State.....are they helpless? Can't they use all Government apparatus at t h eir disposal to put a permanent STOP unto all these mess?.....SHAME to all of t h em if they sit down in office and allow these handful of criminals to continue terrorizing innocent citizens in NIGERIA.
Kini de ti.tinubu olori.ilu ko se dasi gbogbo owun iparun awon fulani ti won ngbeni.pa? Ti tinubu ko eyin siwa? Ati pe awon eya buhari, ti won nrimu ti tinubu ko se gbe won losi ile ejo? Sebi a ti se ma ma balo ni ati odun yi niyi,? Pelu ki awon fulani yi ma se ife inu won lati ma pa awon enia bi eranko.
Great Babagbagede Imo you are right with
great advice but the entire Yoruba nation needs to wake up.
E se jare!
O ga o baba gbdgede imo yoruba nation is the way forward thanks sir
How? When? 😮
Head line yin e sope owo ti te oga zwon bandit amonsa iyato wa ninu iroyin ti enso fun wa ko yewa mo ooo
Baawa? E ku ishe o 🎉. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.
Amin loruko olorun gbogbo adura wa a gba.
It is very sad that Nigerian govt has to negotiate with the bandits ( criminals ) . God Almighty we cry up to you , Pls arise and fight for us and deliver us from these evil and wicked ones in J N . Amen .
Olori won yen jo buhari Ope ni fun Olorun, gbogbo awon to ku Olorun amu won., Yoruba nation no going back.
Eku eto baba gbagede imo
Olorun eledunmare atubo tu asiri won
Owo ate turuji ni agbara olorun
Yoruba nation ni ona abayo
Yoruba nation no going back
Let the delegates sent go to the Obas of Oke Ogun and Ibarapa to solve the problems.
Yoruba nation no goin back
Yoruba nation lafe
Ki won lo wa nkan ti ko fi ni boridele fun koni luyo lagbara Olorun Oba Yoruba Nation no going back IJMN 🙏❤️
Yes ooooo a okinse nigeria 🇳🇬 ki win finally sile ka ma losi ile baba waa
Omo ale oloriburuku ni gbogbo awon gominan ile Yoruba patapata ooo
BABA GBAGE IMO EKU ISE TAKUNTAKUN SIR
Awa Omo Yoruba okinse omo Nigeria
Ki olorun muwa pada si inu Ile yoruba
Toje Ile Baba wa
Yoruba nation no going back
Gegebi e se n ka a yii gan lo se ri ti won fi gba ilu Ilorin mo Yoruba lowo. Afonja naa pe won fun ogun jija ni itan ti a gbo, sugbon ti won ko lati pada si Sokoto mo leyin ti ogun ti wa to ti lo tan.
Hallelujah repete Lori ika to Subu lule yen o.
Ekale sir ooo baba mi GBagedeimo EKU ISEN takun takun sir ooo emiyin yio gun ni agbara gbogbo awon ALA Len Ile Yoruba patapata ooo Yoruba nation no going back
Ransom yen na ni won fi nra ibon ti won ma fi pa wa tan
This Nigeria government's actions on this negotiations with bandits shows that they knew their hideouts. Who is fooling who?
This is so, so SAD 😭😭😭. YORUBA NATION THE ONLY SOLUTION!!!.
Good evening sir EKU ETO Sir
E ku eto Baba Gbagedeimo. Tit for tat lo ye ki o je, ko wu emi pe ka maa negotiate pelu won. Mo nigbagbo pe die ninu agbara igbaani si seku nile Yoruba. Fifunwon lowo a je ki won tun maa ni anfaani lati tun maa fi owo yen ra nnkan ogun sii ni. Olohun Alaaanujulo a segun fun wa nile Yoruba.
Won ti fi esin lu wa ni jibiti ti awa naa si ti go o fun won. Sugbon mo nigbagbo pe die ninu awon agbara igbaani si seku.
Agbara atijo da ooooo.
Apepa, Eedi, Asasi, egbe, Ara Sango, Bibe Esu Lowe, abbl.
EKU ETO SIR ❤❤❤❤❤❤❤❤
Yoruba nation nikan na ni ONA Abayo fun gbogbo Ile Yoruba patapata ooo ilu ofo ni ilu Nigeria ooo ilu adanu ilu ibanujen ilu wahla
Ohun itiju nla loye k'oje fun awon Gomina wa ni'le Yoruba ti aabo kofi si fun awa eniyan won.
Anu awon omo ati aya won lonsemi nitori wipe kole si abo fun won leyin igbati oko won bati kuro nipo olori tan.
Ati Aare ati Gomina, nigbati awon omo ilu ba nrerin, ekun ni won ma sun nitori wipe enikan koni gbin alubosa ko wa hu epa.
Yorubo nation nikan lona abayo.
Yoruba Nation no going back.
Dey play 😂
E ku eto❤
Ope ooo. The sad note is that He will soon be released or replaced by another one. Such news doesn't last long in Nigeria.
E ku ise takuntakun baba Gbagede
Yoruba nation no going back
Babagbedeimo.do you know may be there was agreement between Bola Tinubu and the Fulani before he become president that he will use the Yoruba people as sacrifice to Fulani, may that's why he show unconcerned as they are killing our people.
Ogun esin la won yoruba nja o. Ogun fulani o ma esin kankan rara, ile yoruba ni won fe gba. Olorun o ni gba fun awon omo erankeran wonyi
Ti omo yoruba basi nreti iranlowo ijoba ajewipe afiki oluwa kogbawa o àmin
😮😢
Weldon sir BGI.
EDAKUN TORO BARI BAYII TI JOBA NIGERIA KO BA RI TI WA RO, GBOGBO AWON OBA KINI WON NSE.
AWON OBA WA GAN LO DABI PE AWON GAN NI ISORO WA BAYIO.
OONI OF IFE
OBA KENTA IN OGUN STATE
AWUJALE TI ILE EGBA
OBA EKO
OLUBADAN
ORANGUN TI ILA
EYIN BABA WA KABIYESI E MA TI DAKE JU.
SE AARE BOLA HAMMED TINUNBU LO FI GBOGBO YIN JOBA NI ?
TE FI NBERU TE FI LE SORO EDAKUN IDOJUTI LE LEYI FAWA OMO YORUBA.
ESE WO LASE GAN NA.
OMO WA LOLORI OLOGUN ATI OLOPA O MA SE O.
Baba gbagede o ti dara fun yin e ma base yin lo, Olorun wa pelu yin
Kosi oruko yoruba gan ninu yoruba ninu iwe kzn ti a ka ni igbakan wipe fulani lo ni nigeria olorun a yo wa ninu e ooo
TA lo so pe ko si Olorun. Gbogbo ibiti ti awon ika ba wa, Olorun yio kawon mo, yio si pawon run.
No smoke without fire! Some Yorubas are involving in these dastardly act, we have seeing and hear source act in Ogun state. It's not even normal to determine whose tribe is involved if we have not catch up with anyone.
Lati aye Shagari ni Yoruba ti nse eru northern
BGI, e jeki a gbadura ,ki Olorun se anuwa ni ile Yoruba, nigbati Tinubu ati awon gomina wa o leranwalowo. Pelu agbara ti Olorun fun ile Yoruba nipa nkan ibile,ki Yoruba dide pelu nkan ibile,ki won ran wa lowo. Asiko tito ni kiakia. Awon Oba wa o dasi oro na, akori Eni fojujo, toba ribe ejeka koju si Olorun Eleda wa, kowa gbawa,yio si ranwalowo ni oruko Jesu Amin.
Good evening sir se be ri seyi makinde to ni ile wiwo loun fi ma san jo fu won ni ibadun
Gov seyi makinde n ta Ile Kiri ni ooo
Yoruba e dira o .Awon governors yin o ni time fun yin o.
Bi won ba si dira, ti won ba si dide lati gbe'ja ara won, won a so wipe won teju ofin mo'le tabi fun treason 😮
Yoruba nation is the solution for ur
E jo sa mo ki yin A be gbogbo Agba Yoruba dide o nkan to nsele yi ti npoju won nfi owo agbara gba yoruba loju Oni ife ati Alafin Oyo awon lo ye kan siwju fun Yoruba ki won ye sa sehin
GBA Ile Onile ni seyi GBA kiri
O ma se o, Ile Yoruba lo wa da idakuda bayi ha, kilo wa de, eyin adari Omo Yoruba eranti atunbotan o.
B G I , Is it possible for you to write a personal letter to Gov Seyi Makinde on Dr Ganiyat and Abdul Mumini , for assistance from Oyo State Government on their release ? May be the Gov ,will take action . May God help us in Yoruba land in J N . Amen .
Sebi e sope owo ti te oga banditi
Ibon ti fulani ngbe dani ti ijoba gba won laye ni won gbe oju le tiwon fi nse eleyi to wun won layi ko si iberu ati eniti o ma biwon nitorina ni won se tunbo nko ara won wo ile nigeria. Fulani ti.ni won ngba owo ati wo ile lowo awon nitori eleyi ni won ko se dasi ati gbeja wa.
Huuuunnnn ojo woo bi won pawon ? Lori irooo
Nkan ti onse ijoba nipe nwon ti believe wipe awon ni ondibo fun awon so awa yoruba ko je nkankan loju nwon.gbogbo nwon pata ni Olorun man kolu ni agbara Olorun.
Babagbagede'tieba'unsoro'ijoba'omaundun'min'se'awa'laomaja'funrawa'ni'abi'aomadurodejoba'sewon'rayeiwani'baba'were'koraye'tiwàbiwon'ose'jogun'aye'lobawon
The Ibadan case is even in YBN news yesterday.
29:49 😊
Yoruba lives do not count to both the State and Federal Governments. We the YORUBA RACE has to STAND UP for OURSELVES!!!. 😭😭😭😭
Boya won ko fe gbe ija yoruba nitori a so wipe a fe kuro ni Nigeria. Oye ki awa na wa ona ati ja. Ki Yoruba ye s'ojo mo. Ki won ye miliki gbaladun osi titi ti won afi pa won tan. Ojo buruku ni Yorubadice,. ki won ja fun ile won.
13 thousand naira ni emi no fi ranse si iya Joshua.
Ibukun nifun orile ede yoruba.
Olorun a sanu wa ni ile yoruba,Awon agba agba yoruba ti je dodo enu won ti ko Ododo
Oluwa ni oma nyan olori, sugbon ilu ti won bati nyan olori funrara won bi ti ilu wa yi, nse ni Olorun ma npada leyin iru ilu be.
E joo sa, mo fe bere ibere, kani pe moni ero ibanisoro yin mo ba ti pe yin. Ogbeni to pera re ni pastor Felix nigba yen, a gburo e mo, nibo lo wa
Your topic says Iwo ti ba iga Fulani
You said owo ti ba Awon Oga Fulani? Where is owo to ba Awon oga Fulani
Nigeria is a carcas but we failed to accept it. Nigeria is finished. We don’t have a country. Yet, we think we have a country. I cannot say why publicly, I am beginning to have a negative view about our people.
TINUBU KO FERAN YORUBA RARA, KANRANJANGBON EDA NI TINUBA, IKA!!!
Oba to ni ojo oni a mu won
E ku weekend e si kuse na
E ti mo ibi ti e nlo ti o si je Omo Nigeria ni e si ndaruko ki o wa gba yin
This was revealed almost 4 years ago. Nothing has been done.
What is president Tinubu doing to curtail all these mess ?Is he going to sit down looking until they come to kidnap him in Aso rock ?
So also the Governors in each State.....are they helpless? Can't they use all Government apparatus at t h eir disposal to put a permanent STOP unto all these mess?.....SHAME to all of t h em if they sit down in office and allow these handful of criminals to continue terrorizing innocent citizens in NIGERIA.
But you wrote dat Owo ti ba Oga Fulani pe wahala de bawon. How?? Where is him, Don't fake us with your Headlines please
THIS IS EVEN TERRIBLE AND EMBARRASSING AND SAMEFUL TO THE.😂 FGN. IT IS A RIDICULE BEFORE INTERNATIONAL COMMUNITY.
Tinubu le se ofin gegebi olori.sugbon ko fe gbeja wa nibiti o ni ikorira ile yoruba de.kosi ni jeki a pin ya, o si duro lori oro re.
But yoruba always boost of Africa power why are they not using the juju to fight the fulani's. The thing tired me
Omo ibo ni e ,gbajumo nkan to nse eyin ibo ni ile yin.