ODAJU PEOPLE IN EVERYWHERE

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 11 вер 2024

КОМЕНТАРІ • 12

  • @adenikefajuke5994
    @adenikefajuke5994 23 дні тому

    Baba Ekiti e ku ise ile Yoruba, Olorun a ma dabo re boyin tomotomo tayataya loruko Jesu Amen. Wahala yin koni jasi asan, Yoruba nation ti di dandan

  • @Dare-d7h
    @Dare-d7h 24 дні тому

    Kudo's to you baba lekiti 👍

  • @janetborisanmi9235
    @janetborisanmi9235 24 дні тому

    Baba Ekiti ominiile Yorubaland yoo gbaa fun e o Amin ❤

  • @estherewetuga8245
    @estherewetuga8245 23 дні тому

    E ku ise takuntakun baba Ekiti ❤❤❤
    Yoruba Nation no going back
    Yoruba Nation is the only Solution
    God bless Yorubaland
    Ibukun ni fun Orile EdevYoruba

  • @janetborisanmi9235
    @janetborisanmi9235 24 дні тому

    Baba Ekiti you're blessed 👍

  • @kabirballey3428
    @kabirballey3428 24 дні тому

    Ibere mi lori president Nigeria ni npe se president Nigeria ni pashę ni ilu Nigeria tabi awon ijo kan wani ikonko toję awon ni won pashę ni .
    Kilode ti tinubu kole se bi omo oko kio fariga nitori bi koba se ishę dada Oruko rę ni mbaję lo .

  • @saheedsolely1407
    @saheedsolely1407 24 дні тому

    Baba ekiti kete emure ekiti e ku eto o ekaro oo

  • @janetborisanmi9235
    @janetborisanmi9235 24 дні тому

    Awon omo Yoruba njiiriya nii 😢

  • @Abb-r8d
    @Abb-r8d 23 дні тому

    Se inu igbo lo ngbe ni baba onito letu

  • @olaidealao8174
    @olaidealao8174 23 дні тому

    Yoruba nation no going back

  • @JosephAjewole-s4w
    @JosephAjewole-s4w 24 дні тому

    YORUBA YOUTH E DIDE AWON AGBA YI TI TA YIN GBOGBO OMO WON KO SI NI ILE NIGERIA IGI DA EIYE FO NI WON. ( E GBO TI FULANI SO PE WON TI GBOWO LOWO WON KINI A TUN FE GBO.).

  • @JosephAjewole-s4w
    @JosephAjewole-s4w 24 дні тому

    BABA EKITI E KU ISE TAKUNTAKUN OLORUN YIO RAN YIN LOWO, AJAYE NI TI YIN LORUKO JESU.