WON TISE JAMBA FUN GOV SEYI MAKINDE O NI WAHALA BA BESILE O OMO YORUBA EMA SUN O

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 11 січ 2025

КОМЕНТАРІ •

  • @massbtv
    @massbtv  18 днів тому

    YOU ARE WECOME TO MSS B TV WHERE WE SPEAK TRUTH TO POWER
    DONT FORGET TO SUBSCRIBE LIKE COMMENT TURN ON YOUR NOTIFICATIONS BELL
    TO SUPORT MSS B TV MEDIA STUDIO EQUIPMENTS 0214168704 GTBANK WILLIAMS OUWATOSIN Z
    TO CONTACT US FOR GENUINE INFORMATION OR ADVERT +22957747970 WHATSAPP ONLY
    WE SET THE PACE FOR OTHERS TO FOLLOW
    THANK YOU VERY MUCH MA & SIR ILE YORUBA AGBEWA KONI GBE ODALE OOO

  • @olusolaadesina4623
    @olusolaadesina4623 18 днів тому +2

    Gbogbo fulanis ma ku si ona be eefi ni IJMN Amen

  • @ArabinrinOyindamola
    @ArabinrinOyindamola 18 днів тому

    Elewoni ninu awon omoale arinwa tiwon gbe ofin buruku Wasi ilewa,, awako fe ofin olori buruku ni ile yoruba
    Yoruba nation no going back ❤️ ❤️ ❤️

  • @daudadebeodero5280
    @daudadebeodero5280 18 днів тому +2

    My concern is, the state practices sheria are not better off, no benefit but, all their leader are very corrupt,still not cut with sheria to cut there hand's.

  • @kayodebamideleshittu4374
    @kayodebamideleshittu4374 18 днів тому +2

    Yoruba nation we want

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 18 днів тому +2

    God bless you Mass B.maybe these people that wanted to bring Sheria into OYO,is likely they're going to use it to bring Fulani as Alaafin OYO. May the good Lord almighty let us Omo-Oko yoruba tooto prevail over all our enemies in our mist in yoruba land. Yoruba Nation will stop all these nonsense that is happening to us from the people we accommodated in yoruba land in Jesus mighty name!

  • @akinladeoluwafunmilola9218
    @akinladeoluwafunmilola9218 18 днів тому +2

    Good evening my dear brother Yoruba nation no going back ❤❤🎉🎉

  • @AjibolaMajiyagbe
    @AjibolaMajiyagbe 18 днів тому +1

    Tinubu ati Ooni gedemu lo fa Gbogbo arinfin ti awon Fulani eranko ati baba nwon asitani of Sokoto ti nwon fi nlo wa.

  • @OnifadeDeborahOmolara
    @OnifadeDeborahOmolara 18 днів тому

    Olorun ko ni gba fun won,awa ko fe saria. Yoruba Nation lanfe

  • @alaotijani6769
    @alaotijani6769 18 днів тому +2

    Yoruba nation no going back

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 18 днів тому

    MASS B, ao gbọ nkan ti ęni yęn sọ daada ooo. Tun sọ fun wa ki a gbọ ooo

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 18 днів тому

    Awọn Fulani Alimajeri yi fę sọ ilę Yoruba di Babianla adura agba Babianla, iya kudi babianla. Ọlọrun maa di ọna mọ gbogbo ęyin Fulani na loruko Jesu

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 18 днів тому +3

    Our politicians know that the only solution for Yorubas is Yoruba nation, but because they are benefiting from one Nigeria, that Is why they go against it now

  • @sikiruoluwasegun6804
    @sikiruoluwasegun6804 18 днів тому +4

    Saria law,ko gbodo sele ile Yoruba Land,ni won unpebi o,eni tobafe se saria ko gba Saudi tabi ile Fulani lo Yoruba nation no going back

  • @kayodebamideleshittu4374
    @kayodebamideleshittu4374 18 днів тому

    Seyi makinde I want to go for president
    So he want to favour the Northern

  • @christianaadedeji8900
    @christianaadedeji8900 18 днів тому

    Gbagbe e, ko le seese nile yoruba.

  • @AbiodunSakiru-c3j
    @AbiodunSakiru-c3j 18 днів тому

    Seriya kise ede Yoruba afeseriya ooooo

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 18 днів тому

    Ki Gomina Ṣeyi Makinde lọ ba awọn agbaagba ilę Yoruba ki wọn ro gbogbo abawọle ilę Yoruba, bi awọn Alimajeri Fulani yi ba ṣe nbọ ki wọn maa parę soju ona pęlu aṣę Edumare

  • @jacoboss8038
    @jacoboss8038 18 днів тому +3

    Yoruba nation no going back.

  • @henryidonije
    @henryidonije 18 днів тому +1

    Won kii somo nigeria oo,fulani ni won.

  • @FunsoAdeniyi-cr8pl
    @FunsoAdeniyi-cr8pl 18 днів тому

    AWA OMO YORUBA,AWA KO FE OFIN SARIA NI ILE YORUBA RARA O,EMA GBAGBE KI I SE ESIN KAN SOSO LO WA NI ILE YORUBA, ALAFIA LO-JEWA-LOGUN O.ADANIWAYE A GBA WA . YORUBA EJE-KAJI-KAMA-SUN

  • @fatimahabubakar3458
    @fatimahabubakar3458 18 днів тому

    Brother mass B, yio dara fun yin. Sharia is not done in yoruba land. OLUWA koni gbaaaa, IRO LORO WON BADE.. OODUA NATION NO GOING BACK INSHA ALLAHU ROBY 🙏🙏🙏

  • @temidayodennisomitogun1038
    @temidayodennisomitogun1038 18 днів тому

    E ku ishe o! Up Yoruba Nation! No going back!

  • @adeolajoshua371
    @adeolajoshua371 18 днів тому

    U are very correct,state of emergency is looming and don't forget one of the PDP states in West.

  • @victoriamodupe7896
    @victoriamodupe7896 18 днів тому

    AWON IJAPA OLOGBON EWE..WON FI ENU DIDUN ATI IRO.....FI GBA GOLD NI OWO WON ..GBE PANDA TI WON MA REGRET. TILL THE ENTIRED OF THERE LIVE AND UMBORN.GENERATIONS WON LE WON LOWO
    KI SHARIA..TUNSE NILU NORTHERN STATE

  • @mamaiya6633
    @mamaiya6633 18 днів тому +1

    Omo-Oko yoruba tooto, let us wake up, because the insult passing to us from the people we accommodated in yoruba land to us is too much, enough is enough.Yoruba Nation is our solution!

  • @KayodeJacob-qb2gt
    @KayodeJacob-qb2gt 18 днів тому

    Awon oloriburuku. Ko ni Dara fun won se pelu ebi ilu yi

  • @AbiodunSakiru-c3j
    @AbiodunSakiru-c3j 18 днів тому

    Ododo Oro bi isokuso

  • @FunmilayoElugbaju-lu3dy
    @FunmilayoElugbaju-lu3dy 18 днів тому

    Gbogbo won ma sofo danu pelu ofin saria won se ko si ohun ti awon ara ilu iwo lese fun oba won ni

  • @fakayodesanjo5226
    @fakayodesanjo5226 18 днів тому +1

    Their thought was that western law 'tax reform bill'was impose on them so they also want to impose northern law unto southern too. We don't know who is ruling in this Tinubu regime

  • @tanimowookusaga4856
    @tanimowookusaga4856 18 днів тому

    Won le fi iwosi lo yin, o wa ku si yin l'owo ti eyin ba fi ara gba lo ku.

  • @MagaretAbiodun
    @MagaretAbiodun 18 днів тому

    That is the more reason we should get our yoruba nation Nigeria is a muslim country.

  • @KayodeAjibade-ep7tn
    @KayodeAjibade-ep7tn 18 днів тому

    Thanks so much mass b it won't happen no matter it cost us and God will support us. Awon alale koni gba fun won

  • @KayodeAjibade-ep7tn
    @KayodeAjibade-ep7tn 18 днів тому

    Koni si amotekun naa mo pelu O P C

  • @AbdullahifasasiAlao
    @AbdullahifasasiAlao 18 днів тому

    Hmmm 🤔

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 18 днів тому

    SHARIA LAW KI IṢE OFIN ILĘ YORUBA
    ĘYIN FULANI ALIMAJERI TI Ę KO BA FĘ PARĘ LOJIII, KI Ę MA A ṢE SHARIA YIN NI AREWA YIN LỌHUN, KI IṢE ILĘ YORUBA TI WA NIBI. OFIN NORTH YATỌ SI OFIN ILĘ YORUBA OK

  • @OyeronkeAjadi-w1j
    @OyeronkeAjadi-w1j 18 днів тому

    Too to le so kosi iro nibe won fe pa agbara mo Gov Lara ni Gov na koni le soro mo won aso ara won di oga mo ijoba lowo

  • @AyodeleVictor5133
    @AyodeleVictor5133 18 днів тому

    Irinajo oba ojaja ti Ile Ife lo bi Sharia ni ile Yoruba

  • @tanimowookusaga4856
    @tanimowookusaga4856 18 днів тому

    Aba ni ikan nda, ikan ko le je okuta. Yorubas ki se eran riro fun Fulanis lati gbe mi. Eni ko ni orisirisi iwosi ti wa mba yoruba lati owo awon ota re, ewo lo wa si imuse ninu gbogbo won. Sebi ni on the 12th osu December yi ni awon Igbo l'ori l'aya wipe awon ngbe egungun/ orisa won mbo lati wa jo ni ile Yoruba. Ti awon oloriburuku oloselu/ alakatakiti esin jagidijagan musulumi tun ni eleyi. Inhale ati imura sile wonyi ni lati ma je ki o sese fun iran Yoruba lati da duro fun orile-ede Yoruba ni. O soro fun won lati gbe ogun ko ile Yorubas nitori awon Yorubas ko se ohun kankan to l'odi si ofin. Nitori idi eyi ni won se fe fi ogun atehin ja won. A ki ni ki Ajana ma gun Efon, ko gbiyanju ati guun, iran re ni a ma wo.

  • @FaugahAbolaji-b1f
    @FaugahAbolaji-b1f 18 днів тому

    Yoruba natiion now going back

  • @AyodeleVictor5133
    @AyodeleVictor5133 18 днів тому

    Wonfe islamize ile Yoruba ni o

  • @olufunmilayooniyo2469
    @olufunmilayooniyo2469 18 днів тому

    Won mapa kisa sara awon ELEWE OMO awon ti won hun ta ori eku ori eja,won dema wa bi won se mama rope won seriya mamu won

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 18 днів тому

    E ku ise takuntakun

  • @AyodeleVictor5133
    @AyodeleVictor5133 18 днів тому

    Awon oba Yoruba to lo ki Buhari lo gbabode shariah

  • @victoriamodupe7896
    @victoriamodupe7896 18 днів тому

    WON O LE SUCCEED. RE RARA NILE YORUBAS LAND
    WON FE FI DA..WAR BORROWED BUSINESS CENTER..WAR.. SILE NI
    SE AWON EASTWEST NA MA GBA ..SHARUA LAW NI IKE WON NI NO
    SE E GBO NINU ITAN RI WIPE..THE WHOLE ..COUNTRY..NSE MUSLIMS ONLY NI ...
    AWON ..ELEDUMARE WORSHIPER...ATI..CHRISTIANS NKON..WON MA DI ..ISLAMIST COUNTRY NI

  • @victoriamodupe7896
    @victoriamodupe7896 18 днів тому +1

    SE BI GBOGBO WON PATAPATA. O KU NI ORI FO NI OJU
    EJOWO ..KINI ..ACHIEVEMENT...TI SHARIA LAW OR COURT..MU BA ILOSIWAJU. WON NILE ..NORTHERN STATE OF NIGERIA CITIZENS. NILE NORTHERN STATE
    JU ..MEKUNTURU. ..MEKAFO....BABI..ALUMONGERI...GBE PANU IMOMI ATI OPA LE OMO OKUNRIN WON. OMO ODUN MARUN. LOWO LE KURO NINU ILENWON..O TUN BERE IGBESI AYIE TI RE NI YEN
    OMO OBIRIN..WON NI OJO TI WON TI BI..NI O TI NI ..OKO TI O MA FE...IBAJE. BABA 50 60 80 YEARS OLD MAN ..AWON OBI RE KO GBODO NI NO...NITORI SHARIA LAW..MA GBE
    TI O BA TI DI ..7 YEARS OLD ..OKO RE A WANSAN OWO ORI RE ..A MU LO SINU ILE RE LO MA GBE PELU RE...NITORI. SHARIA LAW. GBA BE FUN WON
    EYINTI E NRIN IYOYO LO SI PARTY. WON MA ..STONE GBOGBO YIN PATAPATA TO ..DEATH NI...
    SE ERI BI AWON ..OMO WON OKUNRIN. SE ...USELESS NILU NORTHERN STATE. WON KO NI ISE LOWO..WON KO LO SI SCHOOL NIBE. ...OKUNRIN KAN LE FE..IYAWO TWENTY...NIBE BI OMO 130 CHILDRENS NO WORK NO SCHOOLS
    SE E FE KI WON FI ..SHARIA LAW..DA. LIABILITIES...SILE SOUTHWEST OF NIGERIA CITIZENS PLEASE
    A YATO SI WON NI GBOGBO ONA..KI AWON OMO OKUNRIN YIN MA KAWE MO..KI WON MA SE ALUMONGERI. TABI KI WON MA..SIN CATTLES REARING WITH AK47 GUNS. BITI WON BA
    PLEASE LET US.DIVIDE ONE NO WORKING NIGERIA COUNTRY IN PEACEFUL WAY
    SAY NO TO ..SHARIA LAW OR COURT
    SAY NO TO ..LIABILITY...POVERTY IN YORUBAS LAND PLEASE.

  • @victoriamodupe7896
    @victoriamodupe7896 18 днів тому +1

    ILE YORUBAS LAND. KI SE ILE..MUSLIMS ONLY NOR QURAN BORROWED RELIGION COUNTRY PLEASE