Розмір відео: 1280 X 720853 X 480640 X 360
Показувати елементи керування програвачем
Автоматичне відтворення
Автоповтор
The Lord Bishop speak like Alaafin Adeyemi and even looks like him
Ẹ kú ìmọyì Bàbá pàtàkì
Wúrà iyebíye ni ogbón, ìmò àti òye ti Olorun jogún fún Bàbá wa, Bishop Àgbà Ayó Ladigbolu. Ki Oluwa túbò bá wa lóra èmí bàbá yi láti se awari àti àfikún opolopo ìtàn ti oti sonu larin àwon omoobo, ijoye àti ará ìlú.
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o
E ku ise o olorun yio maa teyinsiwaju , baba wa adupe pupo o da bii ke maa dake mo, e pe fun wa ni oruko Jesu
Ẹ ṣeun púpọ̀ o. Ẹ kú ifẹ́ wa.
Alaafin Oyíndàsọ́lá Adekatẹ, Adélù Agúnlóyè (1858-1876)