Isedale Abinibi Wa
Isedale Abinibi Wa
  • 712
  • 204 568

Відео

ITANDOWE: Omi lo po ju oka lo. #yoruba #proverbs #proverbial #motivation #proverb #culturalhistory
Переглядів 4212 годин тому
ITANDOWE: Omi lo po ju oka lo. #yoruba #proverbs #proverbial #motivation #proverb #culturalhistory
Orisa Sango yato si Alaafin Sango #yoruba #facts #historical #history #oyo #fact #historicalfacts
Переглядів 9216 годин тому
Orisa Sango yato si Alaafin Sango #yoruba #facts #historical #history #oyo #fact #historicalfacts
Oro Idupe lati enu Alaafin tuntun, Oba Abimbola Akeem Owoade. #yoruba #king #viralvideo #gratitude
Переглядів 29319 годин тому
Oro Idupe lati enu Alaafin tuntun, Oba Abimbola Akeem Owoade. #yoruba #king #viralvideo #gratitude
Awon ohun ti o n te Ite Oba nile Yoruba. #history #historian #tradition #kinag
Переглядів 6421 годину тому
Awon ohun ti o n te Ite Oba nile Yoruba. #history #historian #tradition #kinag
Ayeye Ojo Olokine ti odun 2024. ( 2024 Olokine Day Celebration) #highlights #ijebu #celebration #joy
Переглядів 57День тому
Ayeye Ojo Olokine ti odun 2024. ( 2024 Olokine Day Celebration) #highlights #ijebu #celebration #joy
Olori Oluyinka Banjo (Olori Olokine ti Ojowo) #humanity #humanitarian #culture #olori #ijebuigbo
Переглядів 40День тому
Olori Oluyinka Banjo (Olori Olokine ti Ojowo) #humanity #humanitarian #culture #olori #ijebuigbo
Oba Dr. AbdulRasheed Abayomi Banjo Ph.D Orilonise1 (Olokine ti Ojowo) #history #culture #ijebuigbo
Переглядів 3414 днів тому
Oba Dr. AbdulRasheed Abayomi Banjo Ph.D Orilonise1 (Olokine ti Ojowo) #history #culture #ijebuigbo
Alaye nipa Owe:A pe oro yii lowe o ni Aaro ninu #proverb #proverbial #facts #yoruba#proverboftheday
Переглядів 2614 днів тому
Alaye nipa Owe:A pe oro yii lowe o ni Aaro ninu #proverb #proverbial #facts #yoruba#proverboftheday
IDUPE FUN IFOWOSOWOPO ODUN 2024 ATI IMORAN PATAKI FUN ODUN 2025 #yoruba #appreciation #proverbial
Переглядів 3421 день тому
IDUPE FUN IFOWOSOWOPO ODUN 2024 ATI IMORAN PATAKI FUN ODUN 2025 #yoruba #appreciation #proverbial
Ipade Apapo Egbe Omo Yoruba Atata ti Olawale Ajao sagbateru #yoruba #culture #traditional #original
Переглядів 5821 день тому
Ipade Apapo Egbe Omo Yoruba Atata ti Olawale Ajao sagbateru #yoruba #culture #traditional #original
ITANDOWE: Ore afogbon ṣe ni kii réni si koto #proverbs #proverbial #motivation #motivational
Переглядів 28Місяць тому
ITANDOWE: Ore afogbon ṣe ni kii réni si koto #proverbs #proverbial #motivation #motivational
Oriyomi Hamzat: Mekunnu gan-an lota Mekunnu. Iwonwara lo fa ijamba to waye lose yii #ibadan #funfair
Переглядів 36Місяць тому
Oriyomi Hamzat: Mekunnu gan-an lota Mekunnu. Iwonwara lo fa ijamba to waye lose yii #ibadan #funfair
Orun ire fún Alhaja Olatunde Abeni Onabule omo Akeula ni Ijebuode #restinpeace #sleepon #mother
Переглядів 49Місяць тому
Orun ire fún Alhaja Olatunde Abeni Onabule omo Akeula ni Ijebuode #restinpeace #sleepon #mother
Imoran Pataki fun Soun Ogbomoso nípa isakoso ìlú. thanks #message #yoruba
Переглядів 46Місяць тому
Imoran Pataki fun Soun Ogbomoso nípa isakoso ìlú. thanks #message #yoruba
ITANDOWE : Ohun ti eye ba je leye a gbefo #yoruba #wordsofwisdom #newweek #monday #proverbial
Переглядів 38Місяць тому
ITANDOWE : Ohun ti eye ba je leye a gbefo #yoruba #wordsofwisdom #newweek #monday #proverbial
Idupe odun marun-un idasile Ile-ise M.Ayomide Golden Heritage Ventures, Ijebuode ati oye Baba Adinni
Переглядів 44Місяць тому
Idupe odun marun-un idasile Ile-ise M.Ayomide Golden Heritage Ventures, Ijebuode ati oye Baba Adinni
ITANDOWE : Iwa lebun ta a kore ka #proverbial #proverbs #yoruba #wordsofwisdom #mondaymotivation
Переглядів 48Місяць тому
ITANDOWE : Iwa lebun ta a kore ka #proverbial #proverbs #yoruba #wordsofwisdom #mondaymotivation
Afe ola ma fe egbin (There is need to endure before attaining success) #motivation #newweek #yoruba
Переглядів 49Місяць тому
Afe ola ma fe egbin (There is need to endure before attaining success) #motivation #newweek #yoruba
ITANDOWE : Agbojukan kii rebi kan.(Staying on a spot will limit you to that spot)#yoruba #motivated
Переглядів 532 місяці тому
ITANDOWE : Agbojukan kii rebi kan.(Staying on a spot will limit you to that spot)#yoruba #motivated
ITANDOWE:Beeyan o ba fara ni isinmi,ara o fipa gba a.(Always create time to rest) #proverbs #yoruba
Переглядів 412 місяці тому
ITANDOWE:Beeyan o ba fara ni isinmi,ara o fipa gba a.(Always create time to rest) #proverbs #yoruba
Isafihan afesona fun ebi ninu eto momi-n-moo ni ile Yoruba. (Introducing Groom to be to the family)
Переглядів 1022 місяці тому
Isafihan afesona fun ebi ninu eto momi-n-moo ni ile Yoruba. (Introducing Groom to be to the family)
Orin ibile Ijebu-jesa ni Ipinle Osun(Osun Cultural Song in Osun State)#cultural #song #dialet #songs
Переглядів 2052 місяці тому
Orin ibile Ijebu-jesa ni Ipinle Osun(Osun Cultural Song in Osun State)#cultural #song #dialet #songs
ITANDOWE : Ifojudi maa n tilekun oore ni. #proverb #proverbial #yoruba #motivated #wordsofwisdom
Переглядів 202 місяці тому
ITANDOWE : Ifojudi maa n tilekun oore ni. #proverb #proverbial #yoruba #motivated #wordsofwisdom
ITANDOWE: Ohun ti a ba naani, laa jere #proverbs #proverbial #yoruba #wordsofwisdom #words #word
Переглядів 632 місяці тому
ITANDOWE: Ohun ti a ba naani, laa jere #proverbs #proverbial #yoruba #wordsofwisdom #words #word
Iriri Alagba Aderemi Adegbola JP @80 #autobiography #lifeexperience #80years #lifeexperiencequotes
Переглядів 462 місяці тому
Iriri Alagba Aderemi Adegbola JP @80 #autobiography #lifeexperience #80years #lifeexperiencequotes
Yeye Akilimali Funua Olade (Iya Agba)@80 #culturalheritage #africa #blackskin #africanamerican
Переглядів 4732 місяці тому
Yeye Akilimali Funua Olade (Iya Agba)@80 #culturalheritage #africa #blackskin #africanamerican
ITANDOWE: Inunibini ko kan imowa hu (You Can not be appreciated by everyone👌) #mondaymotivation
Переглядів 652 місяці тому
ITANDOWE: Inunibini ko kan imowa hu (You Can not be appreciated by everyone👌) #mondaymotivation
Agba Onkowe Oladejo Okediji(Happy 95 years posthumous birthday) #author #creative #writer #throwback
Переглядів 162 місяці тому
Agba Onkowe Oladejo Okediji(Happy 95 years posthumous birthday) #author #creative #writer #throwback
Omowe Bayo Adebowale @80 @author #writer #lonelydance #impact #lecture #80thbirthday #life
Переглядів 352 місяці тому
Omowe Bayo Adebowale @80 @author #writer #lonelydance #impact #lecture #80thbirthday #life

КОМЕНТАРІ

  • @taiwofolorunsho5899
    @taiwofolorunsho5899 День тому

    Beautiful❤

  • @AbeeyAziz
    @AbeeyAziz 4 дні тому

    Ki lo de ti o je pe aremo ni Oye maa to si.nigba ti,oba Toku ni omo ya,ati baa

  • @shiitanremi5879
    @shiitanremi5879 5 днів тому

    Greetings from Mexico, excuse me, could you put the information in English, I would be very grateful, infinite blessings and immense possibilities Always

  • @walesal7906
    @walesal7906 7 днів тому

    Thank you my dear sister for enlighting our people because our people dont really understand the differences. Thank you ma.

  • @abayomiabi
    @abayomiabi 8 днів тому

    Beautiful tradition, we must uphold our tradition and culture in Yoruba land.

  • @estheromo6003
    @estheromo6003 8 днів тому

    Kabiyesi is really readymeh

  • @kolawoleayilara9714
    @kolawoleayilara9714 10 днів тому

    59:08

  • @olatunbosunoladapo
    @olatunbosunoladapo 10 днів тому

    Olatunbosun oladapo Akéwì ÀYÀN AKÉWÌ AFÌLÙSỌ̀RỌ̀ Ẹ̀YIN ÈNÌYÀN Ń LAṢỌ TÈMI Ẹ̀YIN ÈNÌYÀN Ń LAṢỌ TÈMI BÍ MO BÁ BOJÚ WẸ̀YÌN TÍ MO RÁWỌN TÈMI INÚ ÈMI A DÙN ARA ẸMI A YÁ GÁGÁ Ẹ̀YIN ÈNÌYÀN Ń LAṢỌ TÈMI OOO ỌPẸ́ ỌPẸ́Ẹ́ ỌPẸ́Ẹ́Ẹ̀ IRE OOO IRE KÀBÌTÌÌÌ

  • @SadeAdemefun
    @SadeAdemefun 17 днів тому

    All those who knew this man, Mr Olatunbosun Oladapo at Akobo where he lived from 1979 to 2002 when he sold it to a Mosque, will agree that he is a very irresponsible man. He chased out his wife and children in 1995 but before then, he was never a responsible man. Rather than investing in their education, he wanted to force them to learn signwriting, hairdressing or tailoring. Now he is doing fine barra everywhere. Now he is a frustrated man that desires to drag everyone down with his miserable life. May he live long to reap the wild fruits that he had sown.

    • @SadeAdemefun
      @SadeAdemefun 17 днів тому

      True

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 16 днів тому

      Who really are you please? I will like to hear this story of your verbally. @SadeAdemefun Here is my number 07037357317. Thanks in anticipation of reaching out to me.

  • @adelekemicheal8520
    @adelekemicheal8520 18 днів тому

    Amin Oluwa

  • @adelekemicheal8520
    @adelekemicheal8520 18 днів тому

    Eku eto

  • @AderonkeOnikepo
    @AderonkeOnikepo 18 днів тому

    😂😂😂😂

  • @AderonkeOnikepo
    @AderonkeOnikepo 18 днів тому

    Ase Edumare

  • @Bamispecial
    @Bamispecial 22 дні тому

    𝕀𝕟𝕒𝕝𝕚𝕝𝕒𝕙𝕚 𝕨𝕒𝕝𝕚𝕟𝕒𝕝𝕚𝕝𝕙𝕒 𝕣𝕒𝕛𝕚𝕞

  • @ayodejimolaniyan5332
    @ayodejimolaniyan5332 24 дні тому

    Great job 👍 What about Basorun Ogunmola, also there was particular narrative that at one point the Laguna of Oyo was promoted to the position of Basorun Oyo. Thanks and more enlightenment would be appreciated.

  • @KolapoMusibau
    @KolapoMusibau Місяць тому

    Rip

  • @OLADIMEJISODIQAbidemi
    @OLADIMEJISODIQAbidemi Місяць тому

    Hmmm leyi ti o tumosipe ,,Iwo lo sinje olubadan lati igba iwase oga oo

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx Місяць тому

    E seun pupo iya wà.olorun a bunkun funwa Ka le maa jeun to wu wa.ose yi a dara funwa Ohun gbogbo a rorun funwa.a se Odun ayo ni oruko Jesu

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 Місяць тому

      @@rachaelokediji-hv2bx Àmí o, ẹ ṣeun púpọ̀ o, ìyá wa

  • @JamesMallard-i8f
    @JamesMallard-i8f Місяць тому

    😢😢😢

  • @ogunmefunabdulraheem2297
    @ogunmefunabdulraheem2297 Місяць тому

    Allah makes his abode, Aljanati firdaous

  • @fatimatitilade8332
    @fatimatitilade8332 Місяць тому

    YA ALLAH PLEASE, for the sake of Muhammad (s.a.w) grant him your jannat without any question😭😭😰😢

  • @leadtechabuja
    @leadtechabuja Місяць тому

    Very devastating for all Muslims

  • @tutuadewale6521
    @tutuadewale6521 Місяць тому

    Am speechless 😢😮😢😮 This is soooo devastating

  • @alhassanshehu1561
    @alhassanshehu1561 Місяць тому

    ALLAHUMMA RAHAMOHUM WAGAFIRHUM

  • @abdulgafarmuhammed4542
    @abdulgafarmuhammed4542 2 місяці тому

    This your akewi

  • @abdulgafarmuhammed4542
    @abdulgafarmuhammed4542 2 місяці тому

    I love this mummy

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 2 місяці тому

      Mo dúpẹ́ púpọ̀, Akéwì pàtàkì @@abdulgafarmuhammed4542

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 2 місяці тому

    E seun pupo iya wà fun imoran te fun yi.olodumare a te wa si waju.ose yi a Dara funwa.anu olorun koni fiwasile ni oruko Jesu ❤️

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 2 місяці тому

      Àmí o, ẹ kú ìmọyì rẹ̀ o, ìyá wa @@rachaelokediji-hv2bx

  • @OLUTOYINOLATUNBOSUN
    @OLUTOYINOLATUNBOSUN 2 місяці тому

    E ku Agba, E ti dagba. E o dogbo ni ogo Olorun.

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 2 місяці тому

      Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o @@OLUTOYINOLATUNBOSUN

  • @Imctv2022
    @Imctv2022 2 місяці тому

    ❤❤❤❤🎉

  • @Imctv2022
    @Imctv2022 2 місяці тому

    Happy birthday to you dear 🎉

  • @isedaleabinibiwa2020
    @isedaleabinibiwa2020 2 місяці тому

    🎉🎉🎉🎉🎉🎉

  • @joanrita6333
    @joanrita6333 2 місяці тому

    ❤ALAFIA YE YE ADIUPE ASE O

  • @bosededaniel4754
    @bosededaniel4754 2 місяці тому

    Olukoo mi tooto E seun e ku ohun Mo je okan lara akekoo yin ni odun Melo kan seyin E ku ise opolo o

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 2 місяці тому

    Ohun yin o jade a gbo nte so ooo

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 2 місяці тому

      Ẹ ṣeun púpọ̀ fún àkíyèsí pàtàkì yìí o, ìyá wa @@rachaelokediji-hv2bx

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 3 місяці тому

    E seun pupo iya wà eni tenu gbo bi owo lase olodumare.ose yi a rorun fun wa ani Shirin ni oruko Jesu ❤️

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 3 місяці тому

      Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o, ìyá wa @@rachaelokediji-hv2bx

  • @isedaleabinibiwa2020
    @isedaleabinibiwa2020 3 місяці тому

    🎉🎉🎉🎉🎉

  • @IMCTV-me4jn
    @IMCTV-me4jn 3 місяці тому

    Happy 80th birthday to you Sir

  • @ewaedeatiasayorubaponnbele2340
    @ewaedeatiasayorubaponnbele2340 3 місяці тому

    Àṣèyí ṣàmọ́dún lágbára Ọlọ́run bàbá wa

  • @ewaedeatiasayorubaponnbele2340
    @ewaedeatiasayorubaponnbele2340 3 місяці тому

    Àṣèyí ṣàmọ́dún lórúkọ Jésù 🙏

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 3 місяці тому

      Àmí o, ẹ ṣeun púpọ̀ o, ìyá wa pàtàkì.@@ewaedeatiasayorubaponnbele2340 Ẹ kú ìnáwó nára

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 3 місяці тому

    E Ku Odun e Ku ijo e Ku inawo koni tan nbe tamodun a ju bayi lo eni se lasan ni oruko Jesu ❤️

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 3 місяці тому

      Àmí o, ẹ ṣeun púpọ̀ o ìyá wa @@rachaelokediji-hv2bx

  • @mikeplucy2000
    @mikeplucy2000 3 місяці тому

    A ko gbodo tun ri iru Samuel Ladoke omo Akintola mo ni Ile Yoruba. Ifashein ayeraye ti o se si gbogbo omo Yoruba ko sehin “Akintola taku” ti o sele ni western house of assembly ni ipinle iwo orun Nigeria ni 1962. O di gbere, Yoruba ko tun ni ri enia bi Ladoke Akintola Amin, Amin ati amin.

  • @adewumiadio5029
    @adewumiadio5029 3 місяці тому

    jagun Alekuso Wole ni ilu ibadan ni, ewon si jade ni bi ti o wole si , won Ma lo ta epo pupa si ni ododun. There more to this story, Jagun Alekuso is one of the greatest worror that Ibadan will ever know.

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 3 місяці тому

      Ẹ ṣeun púpọ̀ fún àfikún pàtàkì yìí, a ó tùn-ún ṣiṣẹ́ sí i lórí rẹ̀. @@adewumiadio5029

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 4 місяці тому

    E seun pupo iya wà.amu ladugbo yin ko fo lase olodumare.a ku ojumo ose yi atuwa Lara anu olorun abawa rin larinye a nishirin Ohun gbogbo a rorun fun wa ni oruko Jesu ❤️

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 4 місяці тому

      Àmí lórúkọ Jésù Kristi. Ẹ ṣeun púpọ̀ mà.@@rachaelokediji-hv2bx

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 4 місяці тому

    O ti gba suuru bayi olorun a kowa ara oni niwa.ki olorun funwa ni okun ati Agbara ese wa a se die n be.a Ku opin ose yio rorun funwa ni oruko Jesu ❤️

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 4 місяці тому

      Àmí o. Ọlọ́run á ṣàánú wa @@rachaelokediji-hv2bx

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 4 місяці тому

    Beeni oooo e seun pupo iya wà.a Ku ojumo ose yi atuwa Lara anu olorun abawa rin larinye a nishirin Ohun gbogbo a rorun fun wa ni oruko Jesu ❤️

  • @JosephAyanwola
    @JosephAyanwola 4 місяці тому

    Imoran Baba wa Oniwere yan lotun se pataki liju temi .verygood. Advise to All Yoruba Lands.

  • @AdeolaBello-z1w
    @AdeolaBello-z1w 4 місяці тому

    Igba odun ojo Kan loruko Jesu 🙏 grandma

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 4 місяці тому

      Àmí lórúkọ Jésù Kristi. Ẹ ṣeun púpọ̀ mà @@AdeolaBello-z1w

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 4 місяці тому

    Huuuuu e seun pupo iya wà.fun a kiyesi te pe wa si eni tenu gbo bi owo lase Edumare

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 4 місяці тому

      Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o ìyá wa pàtàkì @@rachaelokediji-hv2bx

  • @rachaelokediji-hv2bx
    @rachaelokediji-hv2bx 4 місяці тому

    Adupe e seun pupo amu ogbon yin ko ni fo ni oruko Jesu. mo gbadun yín pupo ❤

    • @isedaleabinibiwa2020
      @isedaleabinibiwa2020 4 місяці тому

      @@rachaelokediji-hv2bx Àmí lórúkọ Jésù Kristi. Ẹ ṣeun púpọ̀ mà