ITAN ORISUN ODUDUWA

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 22 чер 2024
  • Fún alaye àti ibere nípa Itan Yoruba ẹ kan si wa
    Aare Laji Abbas +2348023687432
  • Розваги

КОМЕНТАРІ • 92

  • @temidayo6946
    @temidayo6946 23 дні тому +2

    Are Okpitan Ile Yoruba, you are a blessing to this generation. God bless you abundantly.

  • @deedotist
    @deedotist Місяць тому +10

    🙇🏾‍♂️Mo gbe fún ẹ baami olùkọ́ agba oloye Ààrẹ Laji Abass. Ẹ má pẹ fún wa láṣẹ Adaniwaye, pẹlu iranlọwọ àwọn onilẹ. Ẹ ṣeun 👍🏾

  • @ojoyekini6011
    @ojoyekini6011 Місяць тому +8

    Aare Laji Abass listened to your program every day reduced my high blood pressure to normal standard.
    I love AUTHENTIC HISTORY of the WORLD, especially AFRIKA.
    I wish the Almighty Allah will continue to guide you, also protect you from the hands of your both known and unknown ENEMIES.
    GOD GUIDINGS.

  • @ajojikogbodogbailewatv9632
    @ajojikogbodogbailewatv9632 17 днів тому +1

    Uunnn,Aree opitan,ema pepepe bi pepe tin npe,fun wa lase Èdùmàrè

  • @rajihakeeb-yn8fq
    @rajihakeeb-yn8fq Місяць тому +9

    Aare opitan,won nle bo leyin,ko si eni kankan ni wa ju re.

  • @Badryah-bi2rk
    @Badryah-bi2rk Місяць тому +1

    Good evening babami

  • @mrhotgist8121
    @mrhotgist8121 Місяць тому +9

    Soudi Arabia is Europe arab form european but people dont know what its going. Thats why religion if for political purpose

  • @sikiruoluwasegun6804
    @sikiruoluwasegun6804 Місяць тому +2

    Aree laji abas eku eto.Yoruba nation lafe Yoruba nation is the only way no going back 👍

  • @bamikoleolojuomo8447
    @bamikoleolojuomo8447 Місяць тому +7

    Thank you very much for your knowledge and wisdom. You will never die young, God will continue to protect you and your family, you are God sent.

  • @ayodejiowoeye2199
    @ayodejiowoeye2199 Місяць тому +5

    This is pure history Aare

  • @limatglobaltemp7181
    @limatglobaltemp7181 11 днів тому

    E je ki oro yin ma duro lori inkn to fojuhan ni taara. E ma ma fi aroso kun oro yin. Bawo le se mo pe tori oro awolowo lo je ki Bola Ige kede iku Adesoji Aderemi? Nibo leti gbo pe won so fun Bola Ige pe gomina ko lo ye ko kede iku Ooni to wa yari pe oun loun gbodo kede, kii se alafin? Ni gbogbo igba ti Bola Ige je gomina, se o se inkankan to fi tabuku alaafin ni? E fe so pe e o mo pe inkan ti nyi pada ko? Se gomina lo nfowo si yiyan Oba nile Yoruba tele? Se e fe so pe e o mo pe lode oni, eni to ba ni ase lati kede ati lati gbe opa ase fun Oba na ni eto lati kede ti oba ba waja ni? Nigba ti won ba yan Oba tuntun, ti gomina gbe opa ase fun, se iyen wa nibamu pelu asa ni? E o se so pe won ba asa je pelu iyen? Kin lo de ti awon afobaje ko kan kede funra won ki won si se iwuye? Ati pe nipa iku to pa enikan tabi ti ko pa enikan, kin ni iyen ni se pelu igbese ti eniyen gbe nipa asa abi nipa inkan to se? Iru iku wo lo pa Awolowo to sajeji? Ti Bola Ige ti won si pa, se eni ti won ba ti pa bayi, egun lo nja lori re? Se egun lo ja lori Akintola, Abiola ati awon miran ti ko ba ti fowo rori ku ni? Sebi majele ni won fi pa anobi Muhammed, se egun lo ja lori tire na ni? Olorun lo mo iku ti yio pa kaluku. O le ni se, o si le ma ni se pelu egun kankan lori eni yen. Aimoye ika eniyan to fowo rori ku, be ni aimoye olooto ati eeyan pele to ku iku gbigbona. Bi mo se so e ye ma fi aroso ti ko foju han taara si inu itan.

  • @AdebayoBamidele-xe8gd
    @AdebayoBamidele-xe8gd Місяць тому +4

    Mo ki YIN Baba Layi Abass ,Eku ise Lori ede ati Itan Yoruba . Mo be YIN , Ejeki gbogbo Ile_iwe pada lati ma ko itan yoruba

  • @anthonyfresh321
    @anthonyfresh321 Місяць тому +6

    Chief God bless you
    You always talk sense thanks you so much

  • @chukwuemeka1202
    @chukwuemeka1202 Місяць тому +2

    Awa lomo Olufe Abure,Omoba Adede Owo Remo

  • @sirheedabiodun4809
    @sirheedabiodun4809 Місяць тому +5

    Aare opitan number 1

  • @TONITONIFADA
    @TONITONIFADA Місяць тому +3

    Gbe fun Baba. you are too much

  • @oyeyemisosanwo7646
    @oyeyemisosanwo7646 Місяць тому +5

    Eseun pupọ Aarẹ Opitan

  • @user-yw3iy7iu6w
    @user-yw3iy7iu6w Місяць тому +6

    Baba mo teriba fun itan o , ama JU yin se o .

  • @gbengaolaitan353
    @gbengaolaitan353 Місяць тому +4

    Thank you so much, aare opitan

  • @odogunloye
    @odogunloye 14 днів тому

    Baba ẹ pẹ fun wa o.

  • @KazeemBabatunde-my7ps
    @KazeemBabatunde-my7ps Місяць тому +5

    Aare laji opitan word wide

  • @sadeniran2001
    @sadeniran2001 Місяць тому +3

    The only LOGICAL and sensible ODUDUWA history I've ever came across..... However, kindly let us know the name of OLUFE that Oduduwa dethroned when he came back from war?

  • @adenijiakinsemoyin9408
    @adenijiakinsemoyin9408 Місяць тому

    Oro Sunukuñ!!!!

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 Місяць тому +3

    Èdè Latin gan wọ inú tí Gẹ̀ẹ́sì (English language).. "ambulo" "ambulare" (Latin conjugation - to walk). Kí èèyàn rìn..Tàbí kí èèyàn rìn kíá kíá. Òun ló di ambulance lédè Gẹ̀ẹ́sì yẹn.

  • @Ireakari33
    @Ireakari33 Місяць тому +2

    Kare baba itan

  • @olamilekanayodele6177
    @olamilekanayodele6177 Місяць тому +2

    Great job sir 👏👏👏👏

  • @user-yw3iy7iu6w
    @user-yw3iy7iu6w Місяць тому +3

    You're wellcome Aare , we're here .

  • @adesinataiwo9785
    @adesinataiwo9785 19 днів тому +1

    There was another Odudwa in Ifa, which was different to the Odudua the warrior

    • @user-no8gn2lt8o
      @user-no8gn2lt8o 15 днів тому

      ODÙWÀ not Oduduwa
      Oduwa is an irunmolẹ

  • @Adekola-gu1fl
    @Adekola-gu1fl Місяць тому +1

    God Bless You Greatly My Chief 🙏🏽🙏🏽🙏🏽🙏🏽🙏🏽🙏🏽🙏🏽

  • @user-no8gn2lt8o
    @user-no8gn2lt8o 15 днів тому

    Aarẹ, alagbra maa n wolẹ ni ilẹ Yoruba
    Şebi ẹyin naa ti lo wo Ogundigaro ni Iwo ri?

  • @olaafolabi2892
    @olaafolabi2892 Місяць тому +4

    More knowledge, God's guidance and protection over you Aare Opitan. May God bless you and your family.

  • @isholasulaimano.7903
    @isholasulaimano.7903 Місяць тому +2

    You much baba

  • @sijiomoniyi5823
    @sijiomoniyi5823 Місяць тому +1

    E kuse ọpọlọpọ. E jo, e ní Orafe lo ni Ufe. E jo e bawa daruko ninu awọn ọmọ Orafe. Tani Ọsángangan Obamakin? E ṣeun!

    • @user-no8gn2lt8o
      @user-no8gn2lt8o 15 днів тому

      Aarẹ ti şe àlàyé yi tẹlẹ, o wa lori UA-cam

  • @olamilakansoclassyinterior9275
    @olamilakansoclassyinterior9275 Місяць тому +2

    Baba aare please don't forget to tell us about orisha olokun next time.
    Olorun ama kunyin lowo...

  • @musediqsalami8548
    @musediqsalami8548 Місяць тому

    Thank you very oluko agba, but I have a question about the documentary of queen Seba grave at Sudan, can you please sir put a light to this, thanks so much sir.

  • @olumiderichard4496
    @olumiderichard4496 Місяць тому +3

    100% correct sir.

  • @olorioritokesalami1452
    @olorioritokesalami1452 Місяць тому

    Eku ise takuntakun sir

  • @Ogidiolu
    @Ogidiolu Місяць тому +2

    Gbefun

  • @Badryah-bi2rk
    @Badryah-bi2rk Місяць тому

    ❤❤❤❤❤❤

  • @KazeemBabatunde-my7ps
    @KazeemBabatunde-my7ps Місяць тому +2

    Arare no 1

  • @augustineosijo2026
    @augustineosijo2026 Місяць тому +4

    Alhaji Opitan Yoruba land. Please we want you to tell us more on the history of Yoruba and Benin Kingdom( Edo State).
    The Benin people are claiming Benin existed before Yoruba Kingdom.
    E ku ise.

    • @akeemadedayo9626
      @akeemadedayo9626 Місяць тому +1

      The Ogiso/Benin people are descendants/reminants of the destroyed IFE with the people that came back with Oduduwa from his journey. It was a clash of civilisation between them that caused fight and misrule that made of them to send emissary to IFE for help. Oranmiyan was sent to them to go and instill orderliness and governance into place, which was why the first thing Oranmiyan did was to create USELU/OSELU meaning; governance and politicking. It's wealth and fame they got from trading directly with Portuguese that is making them to be overhyping their achievements.

  • @PrinceB1212
    @PrinceB1212 Місяць тому +1

    Hot 🔥🔥🔥🔥

  • @horlat215gideon2
    @horlat215gideon2 Місяць тому +1

    Eku ise Aare opitan.

  • @lmdglobalinvestment9305
    @lmdglobalinvestment9305 Місяць тому +1

    ❤❤❤❤❤

  • @olumiderichard4496
    @olumiderichard4496 Місяць тому +3

    Ejo, kini Alubosa ni ede Yoruba

    • @duduarts7
      @duduarts7 Місяць тому +3

      Alubosa ni ede Yoruba/Ootu, Albasa ni Hausa, Onion in English, aimoye ounje/Eso ni a nje ni ile Ootu, ti won muwa lati ile okeere, gbogbo agbaye loti nsele bee

    • @olumiderichard4496
      @olumiderichard4496 Місяць тому +1

      E seun fun idahun si ibeere mi.

    • @ayodeleomotunde5471
      @ayodeleomotunde5471 Місяць тому +1

      Eku ise baba,ni Ile Yoruba eni parun tomotomo

  • @user-rn8pw6vs8t
    @user-rn8pw6vs8t Місяць тому +6

    Yemenis are the aborigines of Arabs and they were blacks (some are still in the present day Yemen). Awọ wa bara mun lojẹ ọrọ aje awọn orírun wa wọ.
    I see no reason why Saudi keeps bombing their ancestors. Ìtàn o ni tan lẹnu agba Abass

  • @apalarababatunde7491
    @apalarababatunde7491 Місяць тому +1

    God bless you more aare. But please sir baba. On this oduduwa I once inbox you and also emphasize that oduduwa is two one was born why the ateworan was descending. The first oduduwa ooni was born through the lineage of oranfe. But the ooni is alive before Solomon sir with every prove shows that Egypt is older than Isreal why obalufon ogbogbodirin oversee Egypt and kemi now know as Kermit. Please do more of research. We have two oduduwa in ule ufe sir.

    • @loantha2996
      @loantha2996 Місяць тому +3

      Are you the second one

    • @olawaleakinkunmi3713
      @olawaleakinkunmi3713 Місяць тому

      We have divinities that reincarnated however in Yoruba traditions when a new child has characteristics of past divinities, we ascribe the name of divinities to such child. e.g. Okanbi as Ogun, Alaafin Sango as Sango divinity.

    • @user-no8gn2lt8o
      @user-no8gn2lt8o 15 днів тому

      Odùwa is IRUNMOLẸ, while Oduduwa is just a man like u

  • @atibaadewale8341
    @atibaadewale8341 Місяць тому +1

    Where is the first location of Ife, second,third fourth and fifth.?

  • @sannigarubaabubakar
    @sannigarubaabubakar Місяць тому +1

    Pls did oduduwa didn't have siblings and if he has what are the siblings name and where are his siblings......

    • @olugbengaoyewusi9835
      @olugbengaoyewusi9835 Місяць тому +4

      Who were the siblings of Noah. If you don’t know as Bible didn’t mention it, does that make Noah history invalid?

    • @olawaleakinkunmi3713
      @olawaleakinkunmi3713 Місяць тому +2

      he has siblings, and one of them found Idanre because we read that when Oranmiyan went to Benin he branched his uncle at Idanre.

  • @LeksiteDollar
    @LeksiteDollar Місяць тому +3

    Sir @Aare can will say Yoruba is the Foundation of the world 🌎??

    • @adewilliams8
      @adewilliams8 Місяць тому

      Black Africans, including the Yoruba are the foundation of the world. Our African DNA is the oldest therefore, black Africans are the Original, and first and only people created by GOD!

    • @user-no8gn2lt8o
      @user-no8gn2lt8o 15 днів тому

      No, but has a big impact and contributed to ancient civilizations

    • @LeksiteDollar
      @LeksiteDollar 15 днів тому

      @user-no8gn2lt8o thanks sir 🙏

  • @mofolorunso1
    @mofolorunso1 Місяць тому +1

    Aare Opitan don't get worked up. You need to channel this energy to your PBAT. His foot soldiers are already seeking regional despite the mess we are

    • @user-no8gn2lt8o
      @user-no8gn2lt8o 15 днів тому

      Oloriburuku omo irankinran, omo ale Yoruba
      Stop using Yoruba name

  • @AHMEDBASHIR-yi8jg
    @AHMEDBASHIR-yi8jg Місяць тому +1

    😂😂😂 deceivers are plenty here and this man is telling you want you people want hear by saying we can't trase Yoruba history to any other tribes or countries let him even say Yoruba has been existing before prophet Adam ( ASW)

  • @crownedking2567
    @crownedking2567 Місяць тому +3

    Well done Aare.
    But the Edos are saying Oduduwa which they call Izoduwa is from Benin, although i do not agree with their assumptions.

  • @oluwasanmisojobi7073
    @oluwasanmisojobi7073 Місяць тому +1

    SAUDI ARABIA HAS NO KING OR LEADER IN THE TIME OF MOHAMED
    NO HISTORY OR VERSE IN THE QURAN PROVES OR MENTION ANYTHING OF SUCH

  • @AHMEDBASHIR-yi8jg
    @AHMEDBASHIR-yi8jg Місяць тому

    😂😂😂 this man you're losing every day and I challenge you to tell people the reason why Quran and Bible didn't mention the history of Yoruba or mention of ile ife, you can't be deceiving us iron lason Yoruba level 😂😂😂 Islam and Bible has their own scripture why traditionalists didn't have scriptures

  • @adewilliams8
    @adewilliams8 Місяць тому +1

    Kinni itumo Yarubawa?

    • @atibaadewale8341
      @atibaadewale8341 Місяць тому +4

      The land that can grow different types of fruits 😅😅😅

    • @Ogidiolu
      @Ogidiolu Місяць тому +4

      Yaruba means people living in the rain forest

    • @atibaadewale8341
      @atibaadewale8341 Місяць тому +1

      @@Ogidiolu what about Yorubawa?

    • @Ogidiolu
      @Ogidiolu Місяць тому +2

      It's the same..

    • @atibaadewale8341
      @atibaadewale8341 Місяць тому

      @@Ogidiolu okay sir

  • @AkinkunmiSegun-dw3hl
    @AkinkunmiSegun-dw3hl Місяць тому +1

    Mecca ni Oduduwa tiwa.

    • @ojosamuel1123
      @ojosamuel1123 Місяць тому +6

      Does it even make sense to your head that he came from Mecca. Even since I was a kid, when I heard the story, I knew it was fallable.

    • @idowuakinlade2317
      @idowuakinlade2317 Місяць тому +5

      😂😂😂😂 MECCA KO 😂😂 MEDINA NI😢😢😢

    • @loantha2996
      @loantha2996 Місяць тому +3

      Jagidi jagan

    • @duduarts7
      @duduarts7 Місяць тому +4

      Kogi ni anobi mohanmo ti wa, abi?

    • @Princeoloto
      @Princeoloto Місяць тому +3

      Mecca ko, Mercury ni