FINALLY!! AWON MUSULUMI TI NI KI AWON OLOPA LOTI MUFTI IWO MOLE OO, LORI ORO SHARIA NILE YORUBA
Вставка
- Опубліковано 9 лют 2025
- #yorubanation #yorubaland #yorubaspacetv
FPINALLY!! AWON MUSULUMI TI NI KI AWON OLOPA LOTI MUFTI IWO MOLE OO, LORI ORO SHARIA NILE YORUBA
Thanks for watching.
You can become a member of my channel by clicking this link ua-cam.com/channels/BDjojLuu1CM_Nxzukx6Fzw.htmljoin
🎉. Love ❤ you all
God bless you more sa. Ile Yoruba ni won unpe ibi, Sharia law eewo ni ni Ile Yoruba Nation.
More wisdom Eyin Ologbon Alfa
They used Islam to take Yoruba land systematically in Ilorin but yet these Senseless illiterates never learnt anything from it now they want to take Iwo through the current king who is absolutely Salafi!!😭😜🥶
E seun baba wa Alhaji Rasheed Alagbaraomi. Olorun Oba ko ni pa laakaye yin rẹ. Adura yin a máa gbà l'agbara Olorun 🙏
I was born a Muslim, am still a Muslim, Am happy, our father sheikh are standing against Mufti, I trust Baba mi Sheikh Rilwan ❤️❤️❤️
I like that second man thank you baba🧠💯
Awon alakatakiti enia won ti buru ju ika ni gbogbo won Yoruba nation ĺafe
I like that second man thank you baba
Thanks baba
God bless these peace-loving papas. No sharia in Yoruba Nation.
Mufti Iwo kise omo Yoruba, omo Tapa ni Mufti Iwo, gege bi awon eniyan kan se nso.
Community Mufti is omo Igbira. Mufti Adugbo koye ni Mufti, nitori kin se asaju rere.
Bukolaosun4471 tell us where in Ebira land Where Mufti Iwo came from? Some say he is from Tapa, If you don't know much about something keep your mouth shut and go and solve your problems in your yoruba land. Bukolaosun ma wa di oro dada ki o to ma soro,.jade Ok. Happy 😮new year!! Ebira land is a peaceful land OK.
Sharia Law! ni'le Yoruba, iro ni Oluwo ati Mufti npa won ti gbowo lowo awon to ran won ni'se, won fe gba'le Yoruba fun Fulani ni, won ti ro pe o rorun bee naa ni, Sharia Law ni'le Yoruba! eewo nla, baba eewo, eewo to ju eewo lo, Eyin Afaa pataki, Eyin Afaa Ododo Olorun o ni pada leyin yin, atunbotan alayo yoo maa je tiyin lagbara Olorun.
Alatenuje ni mufty iwo if he has taken money for what he's saying aisan loma fi owo na gbo hospital loma spend gbogbo money yen si IJMN Amen
Eniti oba fe se sharia, kolo se ninun Yara baba ee,aiye opoo oo, awon alfa elebi....
Oloriburuku ni mufti iwo,, pẹlu gbogbo awọn ti wọn n tẹle,
Iwo gangan l'Oba awon dindinrin oloriburuku
@AllaniAbdoullah-j3l ayé gbogbo awọn ìran diran rẹ kò ni dára owó awọn larubawa ti ẹjẹ ni o n da yin láàmú ọmọ alè ayé gbogbo yín ko ni dára
You are totally daft
Kini iwo mon nipa Islam
That Mufti Iwo or whatever should have been locked up a very long time ago. It is sad that relevant security agencies are looking on while a tyrant like Mufti is running around and instigating violence, mind-boggling.
The rest of the world is developing, but Nigerians are fighting over religion. What is the contribution of any religion to the GDP of Nigeria? Has religion helped Nigeria develop Agriculture, Manufacturing or Scientific research? We waste energy on non productive things. No wonder we are backward.
Eeyan-keeyan ni Mufti adugbo iwo
Olohun yio sanyin lesan daradara Albarka Annabi wa muhammed SAWW,
Inu mi ma ndun ti mo ba ri musulumi daada toni laakaye
Good talk sir kemi Ola yin ogun ile Yoruba ko ni baje
Ke ise mufty nikan gbogbo awon ti o sa si Abe esin musulumi gbogbo won lo ma te. Ni ase edumare.
Mo gbe oriyin fun yin. Eku ISE .Alaafia ni a nfe ni ile Yoruba. Alaafia ni Jesu mu wa si aye. Sugbon awon eniyan Koo sile. Ile Yoruba ko fe Sheria law.
Eegun wa ilorin o..talo sowipe kosi eegun ni ilorin..omo Kwara ni awa omo elegun de ni wa
Eegun wa ni kwara o ejor...egun elewe, eegun oje, ko si eegun ti o si ni kwara. Omo elegun lawa o
Edakun eduro Naa Se mufuti Iwo nikan Ni afani Nile Yoruba Ni wonfe Fi day iluru Ni oooo
Awon were, olori buruku ni won, awon gba ogo ologo gba asiki alasiki sharia court koo sharia court nii, OLUWA OLORUN ELEDUMARE A BA AWON ATI SHARIA WON WI, IDA OLUWA OLORUN AWON OMO OGUN A BA WON AMIN ASE EDUMARE
I live this Alfa, he said Jihad it lo, cuz anobi no more jihad, It’s only Jihad owo that we have now. 😅
E jo Ko soi Oye Emir ni ile Yoruba. Awon Yoruba ti won wa ni Ilorin ki won koja si ile Hausa .Awa o je Emir ni ile Yoruba o .Awon Fulani o le gba ile Yoruba lowo wa .Ile Yoruba ni Kwara
Ile Yoruba ni ile Ilorin o .Yoruba Nation ni Ilorin ati Kwara .Ki Emir kuro ni ile Yoruba A o ba Fulani tan o .Hausa lo ni Oke Oya ki ise Fulani .Emir ki ise Nigeria o...oba la nje ni ile Yoruba o
It shall be well with that alfa and his generation
Wolewole wodi alaseju aseju baba asete omoaale onibe lenu
Baba e ku lakaye OLORUN a lekun oye yin
Oluwo of iwo ati mufti iwo ni isoro ti a ni nile Yoruba.Olorun oba yio se idajo fun won laipe.
Baba ooo , oro buruku to n terin , se wipe Sambisa ni ile won . Awon alakatakiti esin .
Akoba to nko ba awon eniyan Iwo nko. Ti gbogbo won si dake sibe. O ga o.
Iwo baffles me honestly. It is like oju ewure n won she n fi tie joogun. Olorun ma je ki epe ja wa but Yoruba o ni laju e sile ki awon ode kan ko randan randan tiwon ba wa. Iwo!!! history will remember your docility.
Far overdue
❤❤❤
Mufty oni wonro wonron
Mufuti oni kantankatan. Osoro so boto.
E seun baba Alubarika, e o ni daamu ninu aye, gbogbo agbokanle yin o ni dofo.
Yoruba Nation no going back.
What is the real name of mufti iwo, e je ki a ma pe ni oruko ti baba re so o.
GBO EYIN AJEJI OMO FULANI YI NI A MA PA TAN PATAPATA (WHEN D TIME COMES) IN YORUBA LAND
Our Yoruba land, will not be a land of murderals, we're going to love,and respect people lives.
ÀȘẸ O!
Mumufitinah😂😂
Ki se yoruba ni baba iwo yen
Baba Rasheed, Emi yin a gun lagbara Olorun
Let mulft Iwo take sharia law to his family him his wife and children alone
Anytime a Southerner is the president they always try to stoke religious strife....they started their political sharia during Obsanjo's time now they want to cause dissafection in Yorubaland, the most urbane and tolerant people known worldwide for peace within their various religious adherents...hope Tinubu understands the greater picture!
Point of corrections sir eyin musulumi ile Yoruba ni o koribe loke oya o edekun ebawamojuto oro ile Yoruba yi dada o oloun abawa selekun imo yin Sir
Yoruba ni wahala Nigeria
Yoruba buru o. Olote wahala sa. Esi Fe da Duro pelu wahala.
Olorun ko ni je ki oro muffti ma dabi El zazaki that hw he started, moreover,.Efunra si muffti and Oluwo iwo
Rasidi abi kini wonpeo , oku nie, okuafa.
Obun alfa
Alfa wa olorun yio jeki o da fun yin,awon oni sokoto penpe 3/4 gbogbo won oni lankaye bitiwu o mo,ba aunkali
Send data to watch to the end .
You don't know if we have data or not you are asking us to watch to the end
Awon Alfa elebo wont love this...
Oromi koyipada asiwaju rere ti o ye lati tele adua yin o gba amen
He should be jailed forever
Oba won ni ilu iwo lo n' gbe Mufti na laruge. Ko daa kini na se. And another correction of the ilorin?. Ilorin never a lslam territory. History speaks volume.
This mufti Iwo must be carefully interrogating, I mean his origin must be traced 🥺
Awan Ahlfa oni iro ti poju ni ile yoruba awan onijekuje Ahlfa ti wan da ile yoruba ru ti wan si nin alatileyin ni ile okere ti wan ti ta yoruba fun fulani ti e ban se esin ki e ma se pelu opolo e ye ta yoruba soko eru torii esin awan gbesin yawere e man ronun pe wan biyin sinun esin ki a si se dada ti e ba de Sénégal ati Mali ati Morocco gbogbo ilu ti mo daruko yi wan se esin lonan toto ati to ye lafipa enikeni lara lasi ofinkofin ki e sora nile yoruba kia ye gbesin sodi gbogbo orile ede Muslim ti mo gbe ti ile yoruba yato wan ti ba gbogbo ebi je tori esin wan ti fi esin ba gbogbo ilu je ka sora gidi gidi kia ma sorawa di ero eyin nitori esin awan ilu kan ni ile yoruba loni ti ko si OBA torii esin Muslim nin yio jje OBA kaka keku meje sese ki a fi se awa danun eje ka ronun wa omo yoruba yoruba ronun oola
Anyone know which sect Chief Imam Ogbomoso is, that man is not allowing the current King of Ogbomoso to enjoy his doula at all. I mean, the only conduit for the King to integrate with the wider Muslim community in Ogbomoso has called himself Baba Oba!
But Sharia court doesn’t tamper with other faiths… it’s only for Muslims who wish to adopt the rules of God in their everyday lives! So according to this Alfa now, it’s ok to have Sharia in Ilorin but other Muslims in Yoruba land should not have it because they’re mixed with idolatrous people and they shouldn’t attempt to separate themselves from them abi? Ikaa ni yin sir
Arest Mufuti and locking him up. They are stupid. Awon omoale Yoruba akotilta ede. Egbeade kuro lori Oluwo se OBA Yoruba ni oje tabi OBA fulani, Saudi awon omo ale Yoruba. Efi olopa mu Mufti. Yoruba suru yin tipoju. Edajo fun awon omo ale Yoruba. Sebi Muslim nfe Christian ni ile Yoruba. Esin kise nkan to lagbara ni ile Yoruba. Etiwon mole ki efi won sinu ewon. Eru ni awon Saudi npe won. Gbogbo Yoruba lowa lati ile isise tiwa. Egbe tiwa ga.
Imagine!
Arab don't even practice Islam like they do in Nigeria.
Gbogbo orilede ki orilede ti wan ti ja ija esin awan na ni oni jagidijagan ti wan da ija sile.
Oponu niyin, sharia kosi fun eyin ti nki se musulumi
Ode,ose gba Saudi Arabia lo
Sulaiman didirin gba north lo se sharia re nibe
Olomi pokiti pelu isokuso
😂😂😂😂 ani suffi is not a part of Islam lol 😂😂😂😂 suffi and eru iron rod they're brother
😂😅
Alfa site yin to da patapata. Awon Kan ti day gbogbo awon musilimu lo si christiani ati onisese Lori Oro to o Kan. E lo wadi mufti, ki I Se pure yoruba
Baba Sufi alaimokan niyin
Alaye, keep quiet. What do you mean by 'ekan ekan Alfa'
You need to understand that does people talking are not Alfas they are Alufas like you.
Alagbara omi, you no nothing about Islam
Baba Rasheed, Emi yin a gun lagbara Olorun
E jo Ko soi Oye Emir ni ile Yoruba. Awon Yoruba ti won wa ni Ilorin ki won koja si ile Hausa .Awa o je Emir ni ile Yoruba o .Awon Fulani o le gba ile Yoruba lowo wa .Ile Yoruba ni Kwara
Ile Yoruba ni ile Ilorin o .Yoruba Nation ni Ilorin ati Kwara .Ki Emir kuro ni ile Yoruba A o ba Fulani tan o .Hausa lo ni Oke Oya ki ise Fulani .Emir ki ise Nigeria o...oba la nje ni ile Yoruba o