My sister from another mom, gbogbo adura ti nwon gba fun yin fun Ile tuntun tie ra Oloun a mu adura na lo si Ile ase. E ma ra eyi to ju be lo IJN. E ku eto, getting to like ur platform more ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Awon forces that are following muyideen can't allow him to farabale, we are saying it from our view ni but oribuku ti tontele will not allow him to farabale.
Se ri alfa ajigini , Alafa folorunsho, ati baba legba iro ni gbogbo won bi e se ri won ye iyawo won lo nboo won won ko ni fi kobo sile bi iyawo ba soro ija ni won yio gbe kale awon lo nhun da rugudu si adugbo ole ni won da bi won se da ni won oju muideen fee clear ka sa ma woran
To ba Se PE Ala Ni ki muideen lo mu iwe Ile ti won fun pada fun agbala Gabriel Ko si divorce iyawo re now ki oju re le clear to ba le Se eyi Ko si ija Ni be ati muideen , Ajigiñni ati baba legba oniro Ni gbogbo Yin patapata
Iya laje eku orire orire na koni di ibanuje ale kun ore ore de emi pin koni je tiyi alafia emi gigu ni ema fi lo ologo yi eni gbe omo pin eni gbe omo si awon omo yi koni pade iru muyideen ni iyawo awon omo yi won nife iru muyideen ni oko eku orire ma 💔💖🤩🥰😍💞🧡🥰🌺🏖️🚘🥰💕💞🌷🌺🤟💪🌴🌈 🚘💟❤️💯💋
Ooto ni Alfa legba lo lo ji loju oorun,adupe ko lo ji si odo Legba jeje ko bere igbesi Aiye eni to sese ji ni odo e Eyi to tumo si pe gbogbo ori ire to se ni odo Agbala Gabriel ala ni Ko jo, ko mo ranti pe oun ni iyawo,pe ile wa fun oun mo nibikankan O di gbose Ki won fi Agbala Gabriel sile jeje
Alfa Legba, tell Muyideen to remove Agbala Gabriel from his name. Eyin Alfa Iro, Alfa amugbo. Olorun abinu si gbogbo yin nitori eti yi esin Musulumi pada. It has never been like this. Gbigbo awan Alfa dada ti ku awon Alfa Ina loku bayi. Nonsense All his curses will go back to Alfa Legba and his generations .
Agbala Gabriel was the one who announced that Muyideen’s wife has fibroids and that she was pending surgery. He said it the day Oriyomi Hamzat went there with Muyideen. This Alfa Legba is so dumb that his family should be ashamed of him.
Now that muyideen tiwa ji sojuaye, we're expecting triple of all he saw loju ala from from gbogbo eyin alfas yen. Bunch of shameless oloriburukus Wonti batie je muyideen they don't have anything good to offer you take it or leave it
Alfa Legba, tell Muyideen to remove Agbala Gabriel from his name. Eyin Alfa Iro, Alfa amugbo. Olorun abinu si gbogbo yin nitori eti yi esin Musulumi pada. It has never been like this. Gbigbo awan Alfa dada ti ku awon Alfa Ina loku bayi. Nonsense
Legba yen gan need psychiatric doctor. Awon alfa to ku gan sope awon o mo ni Alfa. We're tiutu ni man yen. Oun lo npe Christians ni keferi ota olorun. Itiju aiyeraye lo ma gbehin Legba yen.
Congratulations iyalje I am happy for you🎉❤
Eyin bloggers yi e de fi oro Muyideen ati ti agbala Gabriel yi sile ke je ka mu oro mi so
Amin ni oruko jesu ❤❤❤❤❤❤
Amin Jesu. I agree with the prayers. May God continue to promote and protect you and the pastor who prayed for you.🎉🎉🎉
Amin loruko Jesu. I tap your anointing ma.
Waaaaooo Iya Laje, Congratulations on your new house, more blessings, more grace Ijmn.
Good
Amin Jesu🔥🔥🔥
Àmiin Amiin Amiin Amiin Amiin AmiinAmiin Loruko Jesu.Ile na atura ,eru ti abiyamo ki TU won ni gbe ka a mo Ile o.Amiin loruko Jesu.
Oponu ni caller yioo, Agbala Gabriel ni wa gbelo ile ejo.
Amin Amin Amin
TO ALL THE PRAYERS FOR IYALAJE
AMEN AMEN AMEN IJMN 🙏 🙏🙏
Amin o ile na atura
Ebi ni pa monamona ku, ti ebi ba pa Muyideen ati awon alfa oniro yin ori won a pe.
😂ijanokehin ale ...
Amin loruko jesu, Congratulations ma
Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin o Jesu Kristi Oluwa ati Olugbala wa ❤🎉❤oti ri be osee be ase orun gun koni yipada fun yin ma Amin ❤🎉❤.
Amin Amin Amin Jesu Kristi,Congratulations Ma Iyalaje Adajo Agba.more grace ma.
CONGRATULATIONS 🎉🎉🎉 MADAM ❤❤❤
Amen oooooo
Won fe Han Ibk le e Mo ni o, ko gbo do tele rara, Agbako Okunrin !
Congratulations ma for the new house.
Congratulations Iyalaje, ile atura o, Asee.
My sister from another mom, gbogbo adura ti nwon gba fun yin fun Ile tuntun tie ra Oloun a mu adura na lo si Ile ase. E ma ra eyi to ju be lo IJN. E ku eto, getting to like ur platform more ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Amen Amen Amen in Jesus name
Please let us move on We are tired of Muyideen he should go and work
Emi yin ma gbe inu ile yin , ibere ore lo ma je fun yin LJK, u ku eto ma
Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin ooooooooooooo loruko jesu
Iyawo Muideen disclosed her médical history on social media, case closed.
Awon forces that are following muyideen can't allow him to farabale, we are saying it from our view ni but oribuku ti tontele will not allow him to farabale.
I tapping the prayers and so shall it be ijn
Amin,Amin ,Amin ni oruko jesu
AMEN IN JESUS NAME FOREVER
Almighty GOD will help.ibukun those Alfa's are not worth it
Se ri alfa ajigini , Alafa folorunsho, ati baba legba iro ni gbogbo won bi e se ri won ye iyawo won lo nboo won won ko ni fi kobo sile bi iyawo ba soro ija ni won yio gbe kale awon lo nhun da rugudu si adugbo ole ni won da bi won se da ni won oju muideen fee clear ka sa ma woran
Amin Amin Amin Amin Amin loruko Jesu Kristi
Amin to the man prayer
Amen Amen Amen
Amino jesu
AMIN AMIN AMIN NI ORUKO JESU KRISTI 🙏
Uuuuuuuh kare bami oro gidi le le yi ooooooooooooo
Amin loruko Jesu Kristi
Muideen shoud change his name to Muideen Ajiginni baba legba yoyin alapamasise
Eni to rowoe lojuala todun esofun pe kotepamo ise ni tori ebi Oro muidini lowo oluwa lowa
Amin lorunko jesu
Iyawo yen o gbodo fe mo
Ki Ibuku mase tele rara ooo
Tori owo ojiji ni Muyideen nwa,o le fi se owo ooo
Olorun a wa pelu e Olorun a sona e ni rere
Ki o lo Divorce kia
Amen 🙏🏻
Iya laje, Ile atura loruko Jesu.
Amen
Ile titun naa atura. Gbogbo Adura ti won se Olorun a mu lo ile ase loruko Jesu E ku eto
Amin jesu
AMEN
Amin si gbogbo Adura o IJMN
Ile a tura o,e o ni sinku oku omo nibe o,e ko ere oko dele o
AMIN LORUKO JESU OLUWA
Ile atura loruko Jesu krist Amin
Amin loruko nla Jesu
Alfa, just tell muyideen to remove Agbala Gabriel from his name since he's now awake from his dream
To ba Se PE Ala Ni ki muideen lo mu iwe Ile ti won fun pada fun agbala Gabriel Ko si divorce iyawo re now ki oju re le clear to ba le Se eyi Ko si ija Ni be ati muideen , Ajigiñni ati baba legba oniro Ni gbogbo Yin patapata
Amin jesu ,Amin jesu
Amin olorun oooo 🙏🙏🙏
E jowo sebi o ti ji soju aiye , e ma gbagbe ko yo teeth ti agbala Gabriel se fun kuro o , ko ma gbe teeth yen lo o . Ko pada si Muyideen yoyin .
Amin loruko Jesu
O ji saye,aye iya.
Iya lake Ile atura o amin
❤Aaamin Jeesu
Iya laje eku orire orire na koni di ibanuje ale kun ore ore de emi pin koni je tiyi alafia emi gigu ni ema fi lo ologo yi eni gbe omo pin eni gbe omo si awon omo yi koni pade iru muyideen ni iyawo awon omo yi won nife iru muyideen ni oko eku orire ma 💔💖🤩🥰😍💞🧡🥰🌺🏖️🚘🥰💕💞🌷🌺🤟💪🌴🌈 🚘💟❤️💯💋
Ooto ni Alfa legba lo lo ji loju oorun,adupe ko lo ji si odo Legba jeje ko bere igbesi Aiye eni to sese ji ni odo e
Eyi to tumo si pe gbogbo ori ire to se ni odo Agbala Gabriel ala ni
Ko jo, ko mo ranti pe oun ni iyawo,pe ile wa fun oun mo nibikankan
O di gbose
Ki won fi Agbala Gabriel sile jeje
Amin amin
That alfa legba needs to be arrested and sue
SO' IYAWO MUDEEN NI IJU ?BUT KINI WON TUN SO PE KO PADA SODO MUIDEEN FUN...KI WON FI OMO OLOMO SILE KO MA BA KADARA E LO.
EJOO, NIPA ORO FIBROD TIWON SO, AGBALA GABRIEL LOSO NIJO TI WON LO GBA IWE ILE MUYIDEEN
Beeni oro lo ba oro wa nigba ti won soro pe Ohun ni awon Fe yanju ibe ni won ti mu oro so
Alfa Legba, tell Muyideen to remove Agbala Gabriel from his name. Eyin Alfa Iro, Alfa amugbo. Olorun abinu si gbogbo yin nitori eti yi esin Musulumi pada. It has never been like this. Gbigbo awan Alfa dada ti ku awon Alfa Ina loku bayi. Nonsense All his curses will go back to Alfa Legba and his generations .
Igba ti muyedeen wa ni Abe brigde oju ala ni
Ala yen o de le se mo laiye
Agbala Gabriel was the one who announced that Muyideen’s wife has fibroids and that she was pending surgery. He said it the day Oriyomi Hamzat went there with Muyideen.
This Alfa Legba is so dumb that his family should be ashamed of him.
Ije eni wa nkan misobayi kefi oro muideen lebayi
Now that muyideen tiwa ji sojuaye, we're expecting triple of all he saw loju ala from from gbogbo eyin alfas yen. Bunch of shameless oloriburukus
Wonti batie je muyideen they don't have anything good to offer you take it or leave it
Alfa Legba, tell Muyideen to remove Agbala Gabriel from his name. Eyin Alfa Iro, Alfa amugbo. Olorun abinu si gbogbo yin nitori eti yi esin Musulumi pada. It has never been like this. Gbigbo awan Alfa dada ti ku awon Alfa Ina loku bayi. Nonsense
Aminnmmnmmmmmmm
Inu kan ati okan ti agbala ni lokoyo gidi gidi nijo ti muhideen bosita yee ko toti plan gbogbo ohun tose yen mama e pelu si Mon si
Legba yen gan need psychiatric doctor. Awon alfa to ku gan sope awon o mo ni Alfa. We're tiutu ni man yen. Oun lo npe Christians ni keferi ota olorun. Itiju aiyeraye lo ma gbehin Legba yen.
Oro buruku ni Alfa yes so,ko daa rara, eniyan buruku ni.
Ejowo se pelu bi gbogbo nkan seri ni Nigeria yi, oro ti Muyideen ni ewa ri ran kankan man bayi, ejowo ewa oro miran so, iyen tito be yen
It's a mere game!
Pastor Àgbàlá Gabriel loose woefully!
Congratulations ma ile a tura o
Alfa ero to lorun kie to soro kie toro idarijin eshe .muidini ni ofe iyawo re ninu chuch fun rare.
Oponu alailopolo didinrin were ni alfa na
Muyideen mule muyideen o ma mu iro loye ni muyideen koki mu iro loku o ye loma mu iro e
Amin loruko Jesu Kristi
Amin lorunko jesu
Amin jesu
Amin loruko Jesu Kristi