Apata ayeraye Se ibi isadi mi; Je ki omi oun eje, T'o n san lati iha Re, Se iwosan f'ese mi, K'o si so mi di mimo. K' Ise ise owo mi, Lo le mu ofin Re se; B' itara mi ko l'are, T' omije mi n san titi; Won ko to fun etutu, 'Wo nikan l'o le gbala. Ko s'ohun ti mo mu wa, Mo ro mo agbelebu; Mo wa, k'o d'aso bo mi, Mo n wo o fun iranwo; Mo wa sib' orisun ni, We mi, Olugbala mi. 'Gbati emi mi ba n lo, T'iku ba p'oju mi de, Ti mba n lo s'aye aimo, Ti n ri o n'ite 'dajo; Apata ayeraye, Se ibi isadi mi.
I never knew what the people on this side were enjoying until me and my household decided to check on them. Maybe you should come join us sir. Christ is sweet and secure to be with.
Apata ayeraye
Se ibi isadi mi;
Je ki omi oun eje,
T'o n san lati iha Re,
Se iwosan f'ese mi,
K'o si so mi di mimo.
K' Ise ise owo mi,
Lo le mu ofin Re se;
B' itara mi ko l'are,
T' omije mi n san titi;
Won ko to fun etutu,
'Wo nikan l'o le gbala.
Ko s'ohun ti mo mu wa,
Mo ro mo agbelebu;
Mo wa, k'o d'aso bo mi,
Mo n wo o fun iranwo;
Mo wa sib' orisun ni,
We mi, Olugbala mi.
'Gbati emi mi ba n lo,
T'iku ba p'oju mi de,
Ti mba n lo s'aye aimo,
Ti n ri o n'ite 'dajo;
Apata ayeraye,
Se ibi isadi mi.
Thank you sir/ma
I love it too even I am a Muslim. Never forget the lyrics of this song right from primary school
I never knew what the people on this side were enjoying until me and my household decided to check on them. Maybe you should come join us sir. Christ is sweet and secure to be with.
Well delivered.
Weldone!
God's best, in Jesus name, God's crew.
Amen. Thank you sir. God bless you too
Beautifully crafted. Praise God
More anointing.
Amen
Thank you
Joyfully overwhelmed.
Hallelujah
I love this song it open my heart ❤️
Wonderful Gid bless you
Ammen. Thanks
ILORI ORIYOMI COME AND SEE THIS....
Glory to God