Hymn 58

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 7 лют 2025
  • HYMN 58
    E korin k'e gborin soke
    S'Oba Oluwa mi
    K'Oba Mimo ko gba wa la
    Ninu ijo Mimo yi
    K'Oba Mimo ko gba wa la
    Ko fun wa laran se
    Ko pa wa mo kuro ninu ese
    Ko wa dariji wa
    Amin

КОМЕНТАРІ • 14