ASIRI TI TU OO. Tani Odale Ile Yoruba? Se Tinubu ni abi Afenifere?Afenifere Finally Support Yoruba..
Вставка
- Опубліковано 10 лют 2025
- #tinubu #yoruba #sundayigboho #oduduwa
ASIRI TI TU OO. Tani Odale Ile Yoruba? Se Tinubu ni abi Afenifere?Afenifere Finally Support Yoruba..
With all this stories why is Afenifere running away from disintegration,why can't Afenifere support Oodua nation, please let all of unite and fight for salvation of our Oodua nation,, Oodua nation is the way out of the problems.
I don't think the video is new. It appears I have watched it somewhere before.
I wonder o! What exactly do they want, these evil old men called Afenifere?
@@morolakeaduloju9096 n
Baba agba yin a dale Thy Lord is ur strength sir Amen
Thank you Bros for bringing this forward. At least I'm able to see two sides of the coins.
Olorun Oba ni oba elesan tiyio San fun kaluku gegebi ise owo re, Eniti ogban to sope Enikan kogbon Ohun gan ni baba dugbolugi ,Oro maunsun ni,ki hiku, Odale baleku, gbogbo wa lamonti Arabinrin Mulika tie so,, mofi akokoyi be eyin baba wa AFENIFERE pe titori Olorun Oba ebawa gba Yoruba nation fun away omo Yoruba, titori ojo ola awon omo wa
Afenifere is still fighting a wrong fight. Support Yoruba nation and stop anything about Nigeria ....
I really like this channel.., your content is always loaded
Thank you!
Thank you sir, we're always at your service.
Mogaji Adejumo is not sayiing the truth. What Tinubu was doing now was what Chief S L Akintola was advocating that led to political misunderstanding in the sixtys.
Afenifere played into the hands of Obasanjo in the 2011. That led to loosing of AD in the 2011 general election in the south west.
If Tinubu did not stood on his feets in Lagos, PDP would have taken over Lagos.
Where were the Afenifere when Obasanjo withheld Lagos allocations for 4 years.
Afenifere were too politically rigid and not ready to play with the reset to time.
Whether Adejumo like it or not Tinubu will become President of Nigeria by the grace of God.
@@thomasbamidelebanmore6583
❤️😢
Yoruba nation will come to light with the cooperation of Yoruba young and old.Let us forget pastt grievance. With support of all Yoruba decent all will be well at no distant time. Meanwhile Let us all work for the success of Baba Asiwaju Tinubu
Afenifere need to declear support for YORUBA NATION because that is what the masses want and obviously,that's the only solution that can better the life of the masses which is supposed to be the major priority of any good man/organization
If other countries that our youths are running to and even that the politicians and wealthy people are running to for medical treatment have not done the needful can they be going there,
Let's have our country as a self determination and nothing else
Yoruba Nation no going BACK
Yoruba Nation no going back thank you sir, more grace in Jesus name amen long life.
ODODO ORO. GOD BLESS YOU SIR. More over Let us make sure ODÙDUWÀ NATION STAND. GOD bless Afenifere, we are one. FULANI must go..
Tinubu babanla Odale Yoruba
A fi ki Olorun ko wa yo.
Tinubu o ku e o ku Olorun
Tinubu e yi ti o da ile Yoruba ru ti to.
Tinubu enough is enough let Yoruba go and leave Yoruba alone
Baba Mogaji Gboyega Adejumo you are great sir for all your contributions as the Chieftains of Afenifere and the asoju of Yorubaland. E se sir.
Tinubu os a bad Omen to Yoruba race.
1999 Constitution is a fraud and is a scam
Yoruba Nation no going back
Yoruba Nation is the Answer
Tinubu Odale ni
Tinubu ti dale Yoruba ni Ona pupo.
Tinubu you are on your own oooo
Omo Yoruba ile ya. A fe atun to Yoruba nation is the answer.
Intelligent man more blessings sir
Baba you are doing great sit keep it up
Baba e so ninu ninu oro yin pe gbogbo awon to n dije fun ipo aare le n ba ja. Ki lo wa de ti e fi n support omo Ibo Peter obi?? Nigbati e mo pe bi jesu tabi anabi di aare ile Nigeria nkan o le dara nitori constitution ti a n lo ko dara. Ki lo de ti e o kuku support Yoruba nation. Tabi omo abiola ti oun naa je omo Yoruba. Abi odale ni oun Naani. Yoo yoo yoo Yoruba ronu wo.
Okay sir
YORUBA NATION, NO GOING BACK
Afenifere e dide ki ti baba Akintoye ati Sunday Adeyemo leyin, Yoruba nation ni yoo mu wa lo ile ileri wa.
Ajo ko le dundun ko nile ma re le, Yoruba nation,eyi to se nile ajoji yi ti to,oun ti a npe lorile ede ni,eya kan,asa kan,iwa kan,ise kan,ede kan,pelu ilepa kan, leyin opolopo odun Israeli jade kuro ni oko eru. Laipe laijina, Yoruba nation yoo jade kuro ni oko eru. Baba wa Akintoye ati Sunday Adeyemo Olorun yoo ti yin leyin,ki wura to dan o ti lanan koja, leyin okunkun imole yoo tan,e se Kiri sir,ki e si mu okan le,tori eyin ni yoo pin ile naa.
Asoju oro po fun baba yi. Awon Baba wa sope ikora eni ni ijanu se pataki fun ologbon eniyan. Wayii oo, eje ki a be Asiwaju Bola Ahmed Tinubu pe ki won jebure, ki won fowo wonu lakoko yi. Olorun ni ngbeni ga, kii se lati owo omo eniyan. Aare tuntun ti mo awon ota re ati ota gbogbo Yoruba patapata. Oduduwa a gbe wa ooo. Amin l'ase Edumare 🙏🙏🙏
Fake story. Foolish man. Odale Yoruba.
True talk sir ❤
Yoruba Nation need to take effect immediately with the light of this speaker to spare head Yoruba Nation as an elder with the likes of Professor Akintoye Sunday Igboho Madan Onitiri Professor Whole Soyinka This coming election therefore must not hold by all means possible Tonubu must be made to understand all the issues at stake and step down from the election to be compensated handsomely at Yoruba Sovereign Nation while Afenifere should withdraw support for Peter Obi immediately to let their people form Biafra Nation Let everyone go their separate ways Now Not tomorrow December 31st 2022 is the deadline
Ojo wo lema Simi ote,ote,ote,a polite,ote to ko jeki Awolowo de presidency,ote to ko je ki Abiola de be e tunti beer ote,olodumare a pale yin mo gbogbo olote,
Yoruba enemy thst destory yoruba land and race is Nr.1 Obasanjo and Nr.2 Tinubu
Afenifere ati Obasanjo ni odale. Awon wonyi ni ko je a GBA orile exe tiwa. Dandan ni iku ekeya ni gbogbo won ati Ayo Adabanjo pelu Obasanjo maa ku. E naa wo eleya won.
Sugbon linde ti afenifere are supporting obi iru iwa odale wo lo to yin
God bless you more Sir long life to you baba
Hmmmm baba agba yin a dale sirooo Afi kolorun gba wa bayiooo
Good product
Wow!!!
Yoruba nation is here to stay
The evil that man do live after with him .Tinubu's character is living with him.
This is true 👍 Tinubu is real Odale yoruba and fulani will deal with him badly.
U have jump to conclusion my brother
Eyin baba wa AFENIFERE, omo eni Koni da epo oyinbo nu, ki apa, ki efi IYE de nu, Olorun ko ni Jeki ile Yoruba o baje, eyin baba wa epe fun wa.
Afenifere ni problem yoruba, that man is lying
Baba ! Gbogbo oro ti e so yii' E yin agba gba yoruba e pe ara yin jo ki e pari dukuu yin e yi ti e so yi kii sevohun o maa pari ija
Ejowo eye maso wipe ojo idajo kosi ojo idajo nibikankan. Gbogbo iru oro bayen won fi eru nba enia ni. Kosi ONE Nigeria iro ninu gbogbo e. Awa Yoruba lanu e nsemi ju. Yoruba enu poju kosi otito lenu Yoruba.Tinunbi kise enia gidi akotile ta enia ni Tinunbu. Owo ni Tinunbu nwa. Tinunbu loma da ilu Yoruba ru.
My problems with all this people is that they will never talk anything about Obasanjo is only about Tinubu, that's why where not moving forward. You're not supporting him and the man his moving forward.
Shut your mouth because you don't know what you're talking about.
Good Talk
3VEN GUNMI SAID TINUBU CAN BE TRUSTED IF HIS FROM FULANI THEY WE JAVE ELIMINATE HIM BY NOW BECAUßE HIS BETRAYER AM9NG YORUBA
Nice one
Baba gbogbo ise ti Sunday Igboho Ati baba Akintoye se e o mu enu ba eyi ti otumo si wipe inu meji lenlo. YORUBA nation lafe, ejeki Alo ife Ni ile YORUBA.
Now what can u do now that tinunbu has become president,
Yoruba? Yoruba? Yorubawa?
Oju ti already tiyin baba afenifere eni enu oro oju ti tiyin pata pata
I am happy that this man and PA Adebanjo has been proved wrong.
Who is a traitor d person supporting ibos or who?Iam happy baba Fasoroti has taken part of honour.
Time will tell.
Baba agba to mon itan. Esima SOROSOKE ni igba ti ASIWAJU ba di AARE NIGERIA. Eyin gangan ni odale.
Thank you sir
Sir baba afenifere kilode sir ti ekofe yoruba nirere lati gba orilede tiwa, lati 1950 ti baba awolowo ti nbabo koma babaje lowoyin pelu agbara awolowo ti enlo fun Oku Nigeria ti ko gbewa, kilode ti e ko fi gba ile baba yin toje iran yoruba nations ti iya mobaa jewa mo la.
This man is talking nonsense, because he didn't like tinunbu, nothing like governor in abacha time
Eyin gaan ni odale, ni 2003, oro Obasanjo to fa Gbenga Daniel sile gege bii gomina ipinle Ogun loda ija sile laarin afenifere ati Tinubu nitori o so funwon wipe ki won ma tele Obasanjo mo nitori wipe o ti fa elomiran sile ninu egbe PDP sugbon e o gbo, sebi PDP lo pada was gba ijoba ni gbogbo ile Yoruba yato si ipinle Eko ti Tinubu ni ki won ma dibo fun Obasanjo mo.
God bless you Baba
Omoale ibe Ni oti dagba
And no body steal money in those day as baba is saying and now a days the thief’s are in power how can we get read of the thief’s in all area from President level to the level of any police level. We are all tired
HISTORY WILL TELL, NO MATTER HOW, EITHER GOOD OR BAD, THINK BEFORE YOU DO BAD, IT WILL TELL, THE TRUTHS SHALL PREVAILS, A NEW DAWN ALREADY EMERGED, APC,PDP,NO MORE, LP ON THE WAY,WE WILL SURELY SUCCEED IN SHALL ALLAH,OR YORUBA NATION STRAIGHT, NO GOING BACK,NO MORE ONE LIEGERIA, PERIOD
😮 Wow
Yoruba ni oselu to gbon to loye
Afenifere ni odale Ile YORUBA. Aeon ni won fa emilokan kale dipo Funso Williams. Odale egbe ni won o. Omo Yoruba e yera fun won.
Kini Tinubu se pelu Yoruba ti oto ti awon Igbo, nipase Asikwe si Awolowo? Ejo iro lo npa yi, kilode ti efi nse eleyi lai ranti iwa awon Igbo? Sebi otile wa idariji wa sodo yin, se Igbo ti le wa idariji wa sodo yin? Se iye lowa fa ti awon Igbo fi sope, awon loni Eko, ti eyin na ko da won lohun? Se iye lofa ti en tele Igbo lati wagba ile Eko mo Yoruba lowo. Etele won nigba ENDSARS lati wa ba Eko je ati lati ba nkan je mo Tinubu lowo. Se Obi je ololufe Yoruba ni? Kini eyin nse lehin ti Awolowo ti lo, lati tesiwaju Lori nkan ti Awolowo ti se? Ote yin poju. Se Buari gba fun Tinubu lati ba sise ni? Tabi ipo wo lowa lati igba ti Buari ti de be, tofi je pe, Tinubu le nda gbogbo esun le lori. Elo koju won, Lai ni Agbara ija lowo. Nigbati Jonathan wa ni be, ipo wo ni Yoruba wa ninu Ijoba re? Selo yeki ese ipade Po pelu Tinubu e ohun ti efe ni yi, sugbon ote ni ense si
Tinubu ! We need no Nigeria election.
Sir, what Abacha do to Mr Tinubu that moment?????
Huunnmm, Ododo Oro reee; this is d true picture of Yoruba Nation's problem,so we bear it in our minds that;d "Law of Karma"is awaiting everyone of us,so in Yoruba Language; there's an adage; which says,"Lala ti o lo s'oke;Ile lo nbo,so in conclusion;"ESAN",reee,so there's no"Doubt";no "Short Cut", everyone of us'll "Reap what he/she sowed".
Oro awon Agba Ni, ko se f'owo rotisehin.
Baba kilode tii e ko so nipa good luck jonathan eyaa melo niwa ni nigeria gaa kilode tii e ko so nipa gbogbo eleyi latii ojo yii seri Akole
tori awijare kii itoota lenu
Yoruba nation ijee eyi so ikanka
latii ojo yii
Then if you are fighting for the YORUBAS why can't you babas support YORUBA nation? Before you can be appreciated for all you have done you should support YORUBA nation sir.
All is lie and envy we talk about Yoruba nation afenifere said no presidency for a Yoruba you people are also against it , who is odale here, about Kola Abiola Lola should be ask where is he when the father is in prison
Eleda gbogbo Omo Yoruba ada fun
Awon Afenifere
Ijoba Eko ni o dale YORUBA
Baba you don't have anypoint sir
Why are u people soporting obi
Afenifere is traitor to Yoruba land
Fasoranti did gave support. Yoruba and egbinrin ote!
Jowo mabinu sir egbagbe re eforiji Omo yin ni efowosopo pelu re o
Divine covenant parish ccc losangeles California
History will always be there go check it out
Pls I Lorin stay on its own, Alafin has never for once collect isakole in Ilorin
Get the history right pls
Both political groups failed Yoruba woefully so, how can you offer any choice between the devil and deep blue sea??
Ododo Oro ni
Words of wisdom indeed
Nonsense talks. You better forget all these stories and join hands to lift Nigeria up.
Baba pls let's stop all these . I said it earlier .that hausa will come out massively to vote in tinubu . We're u not all of u that said abacha should not leave abiola ? Swear sir that u not part of the plot ? Tinubu is a politician. God want him and he will be there . Abegi . You hv decided to follow tge wrong side . You guys don't belive in nigeria . You better start fighting for your yoruba nation it may take u 20 to 25 yrs not one month u thinking Let's be proud of tunubu and support him . Eyin odale . However shagari ruled .Blablabla .
Divine cov
Intact, Yoruba got Brain
Is oodua invesment not arenifere
You said iigbo turn because did hausa did but you don't mention goodluck which means that all what you're saying is a lie
And loju yin o tun wole si ipo are
Almighty bless you sir
Odale to ba dale, koni dale.
It seems l know this guy o
Pop
rswz😮
Ejeoda kosinkan tiosele
S A W