O DA BII PE APA TINUBU KO KA IṢORO NAIJIRIA YII MỌ O

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 10 вер 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

КОМЕНТАРІ • 59

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi 26 днів тому +8

    IYÀ ALAROYE niagbara Olorun Atunbo maadara fun yin NIOOOO nioruko JESU Oluwa waa AMIN ❤

  • @olajireridwanolaitan3284
    @olajireridwanolaitan3284 24 дні тому

    Iya alaroye voice Lasan gan sweet passed my relationship ajeh the women too good

  • @ABDULKARIMSALMAN-d5m
    @ABDULKARIMSALMAN-d5m 26 днів тому +3

    ❤ Alaroye ko si eni to ye afi oba aseda,ki eledumare saanu fun wa,ki o fun wa ni ona abayo,lase edumare.

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 26 днів тому +4

    Ibere kan timo bere lowo awon ojelu eda tani!!! Ejowo ki wani gbogbo wahala ti Mr Aliko Dangote se wa jasi fun gbogbo ilu Nigeria.... Mr Aliko Dangote!!! Awon ojelu ilu Nigeria ko feran e rara!!!! Ika, ole, niwon

  • @pauloladimeji2514
    @pauloladimeji2514 25 днів тому

    Adanwo nla lonba Ilu Naijiria ja.
    Kolorun bawa gba emi gbogbo awon to nyo Naijiria lenu kiakia.🙏🙏🙏🙏🙏

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff6458 26 днів тому +3

    Mama Alaroye you are too sweet ❤❤❤

  • @oriyomiokunoye7772
    @oriyomiokunoye7772 26 днів тому +1

    Mama alaroye imo ati oye ti olorun fun yin ko ni di ibaje oo

  • @olamilekanfabunmi1676
    @olamilekanfabunmi1676 25 днів тому +1

    Iya alaroye kosi ironinu oroyin ooooo olori buruku ni ijoba Nigeria 🇳🇬 Libya 🇱🇾 epo 5 Lita ni Libya 🇱🇾 1dina 100 naira ti Nigeria 🇳🇬 sebi awalalepo kilode ti epo nwan wa aaa ijoba Nigeria 🇳🇬 olorun afi iyajeyin ooooo ooooo

  • @banirefatiualao9249
    @banirefatiualao9249 24 дні тому

    Oro gidi wa ninu eyi ti e wi lote yii 👍

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 26 днів тому

    Alaroye God almighty will bless you ma Nigeria leader are very wicked and heatless God is watching them

  • @labakefunmi7319
    @labakefunmi7319 26 днів тому

    O ga ooooh, olorun ooooh, sanu wa

  • @jidesunday
    @jidesunday 25 днів тому

    💯💯💯

  • @adeyemoademolajammy2002
    @adeyemoademolajammy2002 26 днів тому

    Mama alaroye opolo yin o ni doba, ki a ma tanrawaje, ijoba apapo mo si gbogbo isoro epo robi ti a ndojuko lorilede yi.

  • @victoriaadebayo6446
    @victoriaadebayo6446 25 днів тому

    Alaroye mama, ise iwadi yin o je gbogi lati gbo fun onikaye enia. Asiri nla leyi. Ibaje ti won nyo ninu re yi lo ma mu idajo ba won laipe.
    E ku ise tankuntakun.😊

  • @APPTVchannel
    @APPTVchannel 25 днів тому

    Hmmm 🤔🤔🤔

  • @truthsquestions1532
    @truthsquestions1532 25 днів тому

    ❤❤❤

  • @fatalkehinderaheemat1513
    @fatalkehinderaheemat1513 26 днів тому

    Ori Nigeria daru awon ori gan o gbadun rara oro nigeria ti di Owo olorun hmmm o ga oooo

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi 26 днів тому +3

    Awon Oloriburuku OLEE ni Adaari Nigeria , NIPAA TI Petrol, TINUBU NI NUMBER 1 , BUHARI TELE 2, OMO OTEDOLA, DANGOTE OLEE NI GBOGBO WAN OOO, TINUBU BOLA HAMEED LOGAA WAN NINU OLEE JIJAA , OHUN LOGAA BEFORE BECOMING PRESIDENT , GBOGBO WAN LONI FEELING STATION. AWON TI WAN NIJERE LAALE AMIN AMIN AMIN ASE.

  • @titilayooyinloye2994
    @titilayooyinloye2994 26 днів тому

    Olorun a tu gbogbo Epo to so mo Alikiamo Nigeria tu ti agbongbo ti agbongbo loruko Jesu Amin.

  • @user-sb9lv9pg6g
    @user-sb9lv9pg6g 26 днів тому

    Iman tara eni nikan lo nba awon oloselu wonyi fira

  • @FolarinNureni
    @FolarinNureni 26 днів тому

    We'll done ma continue with your good work you always saying the truth God bless you

  • @goldenroyal7351
    @goldenroyal7351 25 днів тому

    TINUNBU BOLA OTIFI OKAN BALEEE AWAN OJELU IKA BABA IKA ODAJU ABIYAMON

  • @kazeemibrahim2034
    @kazeemibrahim2034 26 днів тому

    Oni Angara... May God Help us in Nigeria.

  • @aadeoyemosun0359
    @aadeoyemosun0359 26 днів тому

    Aye n se Nigeria,awoon oyinbo lo n se wa

  • @AdeyemijamiuTaofeek
    @AdeyemijamiuTaofeek 25 днів тому

    Hmm wahala pro 🤔 max

  • @oe6526
    @oe6526 26 днів тому +1

    Eni kankan ko se wa! 1977 ni nigeria wo wahala through Festac 77.

  • @emmanueladeniyitosin1172
    @emmanueladeniyitosin1172 26 днів тому

    Pls we need Yoruba nation. Because Nigeria is finished olohun oba gbo.

  • @user-xn6kn6eg6q
    @user-xn6kn6eg6q 24 дні тому

    O so oju mi koro e ku ise opolo ooo

  • @omoyelesamson2150
    @omoyelesamson2150 26 днів тому

    Nigeria ko le dara mo, e jeki a pin Nigeria gege bi a ti wa ki awon oyinbo to de. Ona abayo kan to wa niyen. Sugbon gbogbo yin ko Fe ooto oro

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp 25 днів тому

    APA BABA TINUBU KO LE WAHALA TO WA NI NIGERIA RARA

  • @oduatide6849
    @oduatide6849 26 днів тому +2

    YORUBA NATION NI ONA ABAYO

  • @OlasunkanmiFasasi
    @OlasunkanmiFasasi 25 днів тому

    Fun rara oniko lo nifi owo a rare lonfi owo re fa iku

  • @MoshoodOriyomi
    @MoshoodOriyomi 26 днів тому

    Omo daada ,Eri re koni daru

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 25 днів тому

    E je kia pin ilu yii

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 25 днів тому

    Ika ni Tinubu o mo ohun to nse, o mo pe ohun ko lese kankan ni Nigeria lo je ko ma sa fun iforowe oro.ohun ni inu se bi si Omoyele Sowore pelu gbogbo asiri re totu sowo omo Nigeria, Revolution now .Olorun agba wa, awon to jade fun iwode kere niye.

  • @Babatope-up4iu
    @Babatope-up4iu 26 днів тому

    Aye naijiria ti baje patapata.. Yoruba Nation la fe

  • @agbekeaiyedun7107
    @agbekeaiyedun7107 26 днів тому

    All cos dey have passion for their country, Liegeria, Liegeria my country 😂😂😂

  • @user-tr1nu6ef7z
    @user-tr1nu6ef7z 26 днів тому +1

    Awon Alaini opolo kan shi fi 1 state compare 36 problems Etan je lokun Nigeria

  • @OlowoleSunday-xg1gv
    @OlowoleSunday-xg1gv 25 днів тому

    Alawọ dudu ni o

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 26 днів тому +1

    Awon Oloselu ilu Nigeria wa... Lose wa, awon Olori tani 🙄🤓👈

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 26 днів тому +1

    Ilese Alaroye... Eku ise nla naa sir/ma

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 25 днів тому

    Eyin se mo iyen ni
    Ipa Tinubu kole ka Lai
    Melo ni Ara Tinubu pelu isoro toba ni Nigeria

  • @StonePilusa
    @StonePilusa 25 днів тому

    Nigerian is not working for anybody anymore let breakup once, Yoruba Nation is the solution No going back together we moved.

  • @truthsquestions1532
    @truthsquestions1532 25 днів тому

    Oyinbo ti mu yin leru still in 21century 😮 sad though

  • @abetoba2331
    @abetoba2331 26 днів тому

    Ejeki awon soldiers gba ijoba , kiale bo lowo awon 419 government people

  • @OlasunkanmiFasasi
    @OlasunkanmiFasasi 25 днів тому

    Lori iro ni gbogbo ijoba won

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b 26 днів тому

    Ole ni gbogbo won ko si ina ko si titi to da ni Nigeria

  • @yetundesokoya3534
    @yetundesokoya3534 25 днів тому

    What a shame 🙄😔😭😭

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm 26 днів тому

    Tinubu ati awon omo leyin e toko losi abuja lati eko tiwon jongbe eegbogi oloro won olese aseyori kankan ofoni wonmamu ijokeji oja walahi

  • @titilolashaw4315
    @titilolashaw4315 25 днів тому

    Is thieftinbu not one of the owners, Awon oloriburuku somebody.

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 25 днів тому

    Awon American pelu awon ti won se Nigeria

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 25 днів тому

    Awon ( NATO) ni won se Nigeria

  • @AyotundeOjuade
    @AyotundeOjuade 26 днів тому

    Kosi enikankan tole tun Nigeria se, ayafi pinpin, there's no plan to be good in the next 20 years.

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681 26 днів тому

    IYA MI ALAROYE E KU OHUN JARE YIO MA JU YIN SE ODODO ORO LATI ENU YIN LO MA NJEKI NGBE OSUBA NLA FUN YIN KO NI SU YIN SE KO SI NI SU YIN SE ODODO LO NGBE ORILE EDE LEKE OLORUN YIO FUN AWON IJOBA YI NI ETI I GBO ATI AYA GBASE YIO SI MA JUSE FUN YIN IRE O

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b 26 днів тому

    Nigeria president ole ni gbogbo won ati awon government's lati tori president to dawn there all robbery and theft where Nigeria president get money to president you and wife Olorun a gba Agbara lowo yin Atubotan bo