GBOGBO ENITI O BA DAN RU E WO LATI SE LAJI ABBAS NI SUTA,ALLAH YO DOJU ENINA TABI AJO AWON ENIYAN WON YO SOOFO TIRAN TIRAN, ASEEEEEEE, EDUMARE MO WON LARA.
Ààbò, Àánú àti ojú rere Ọlọ́run alààyè a dájú lórí yín- Oloye LAJI ABASS Pẹ̀lú okun ati àlàáfíà ara tó pé níye fún ẹ̀yin àtàwọn ẹbí, ọ̀rẹ́ àti ojulumọ yín títí láéláé. Ẹrú ìtàn Yorùbá tí ẹ gbé lọ́wọ́ kò ní dànù lójijì láṣẹ Èdùmàrè látọ̀run wá. Àṣeyè, àṣe lọ́lá Pẹ̀lú ÀṢEYỌRÍ SÍ RERE NI FÚN YÍ, ÀÀRẸ ÒPÌTÀN. IRE LỌ́JỌ́ GBOGBO NI TIYÍN LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ LÁTỌ̀RUN WÁ ÀMÍN ŃLÁ ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤. Ẹ ṣeun lọpọlọpọ gaan ni. Àwa kan mọ rírì iṣẹ́ takuntakun tẹ́ ñṣe
Lóòótọ́ àti lódodo , ọlá Alimi àtàwọn alakatakiti ẹsin tí tán pátápátá porogodo ní ìlú Ilorin àti ní gbogbo àgbáyé láṣẹ Èdùmàrè látọ̀run wá, ÀMÍN ŃLÁ. Ààrẹ ÒPÌTÀN gbogbo ilẹ̀ Olómìnira Yorùbá ní gbogbo àgbáyé, Ẹ ṣeun o fún ìdánilẹ̀kọ́ pàtàkì láti jẹ́kí àṣà àti ìṣe àwa ojúlówó ọmọ Yorùbá lásìkò yí máa tẹ̀síwájú bótilẹ jẹ́ wípé àwọn ọ̀tá ñgbogun láti da ojú ìtàn bo,lẹ . Olódùmarè a máa sọ agbára yín di ọtun lojoojumọ . Gúnnugú kìí kú LÉWE , ÀÀRẸ ÒPÌTÀN LAJI ABASS YÓÒ DÀGBÀ BÍ ÀWỌN ARÁ ÌGBÀANÌ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ LÁTỌ̀RUN WÁ, ÀMÍN. ÀWỌN ỌMỌ YÍN NÁÀ A MÁA DARA SI NÍ NÍPA ÀṢẸ ÌTỌ́NI ÌRỌ́RÙN OLÓDÙMARÈ ẸLẸ́DÀÁ GBOGBO ÀGBÁYÉ ÀTOHUN GBOGBO TÓ WÀ NÍNÚ RẸ FÚN ÌṢELÓGO ÀÌDÍBÀJẸ́ AYÉRAYÉ. ÀMÌN ŃLÁ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ LÁTỌ̀RUN WÁ
GOD BLESS BLESS YOU . DR AARE LAJI ABBASI, GOD make you to help us no ,our HISTORY in YORUBA LAND, Thanks for teaching us are HERITAGE. Dr you are too much , thanks.
Yoruba lati Ile Ife niwon, Kaba ATI Ebira, tegbon taburo niwon, awon mejeji Jo jade pelu IFA lati wa ibiti won ma tedo si ni, culture won ki yato si ti awon Yoruba, Ede loyato
Aare, ki Olorun lora emi yin fun wa. E dakun mo ni ibeere kan o, se ojulowo omo bibi Ilorin ni ologbee Sheikh Adam Al-llory ni abi ara awon fulani omo alimi?.
It's absolutely n completely true, Aare Laji Abass. Emirs r not Oba {Kings} t4 can't ever b in d same category of/as Oba {King} Pls don't get it twisted; categorically Emirs r totally n entirely subordinates to Oba/s {Kings} Emirs r mainly Muslims ie Islamic Religion leaders n r only turbaned n don't wear crowns like real Kings. Bless Up🙏 @Aare Laji Abass
Ola Alimi tan nilorin, iyi Alimi tan nilorin.
YORUBA NATIONA IS THE BEST 👌 👍 😍
GBOGBO ENITI O BA DAN RU E WO LATI SE LAJI ABBAS NI SUTA,ALLAH YO DOJU ENINA TABI AJO AWON ENIYAN WON YO SOOFO TIRAN TIRAN, ASEEEEEEE, EDUMARE MO WON LARA.
WONFE SOLE YORUBA DILE HAUSA OLORUN NIKO GBAWA
EMIR OF ILORIN OLE 4 1 9 MABULLA
Yes na 419
Awowo ma wo awon olote tonda Yoruba lamu, Aare ma kowa niso.
EKU ETO SIR OLORUN OLODUMARE AMAWA PELU YIN
Olohun Oba a ma wa pelu yin.
The president of oopintan Aare laji Abass😂
Baba oloye temi niyen!!!
Ààbò, Àánú àti ojú rere Ọlọ́run alààyè a dájú lórí yín- Oloye LAJI ABASS Pẹ̀lú okun ati àlàáfíà ara tó pé níye fún ẹ̀yin àtàwọn ẹbí, ọ̀rẹ́ àti ojulumọ yín títí láéláé. Ẹrú ìtàn Yorùbá tí ẹ gbé lọ́wọ́ kò ní dànù lójijì láṣẹ Èdùmàrè látọ̀run wá. Àṣeyè, àṣe lọ́lá Pẹ̀lú ÀṢEYỌRÍ SÍ RERE NI FÚN YÍ, ÀÀRẸ ÒPÌTÀN. IRE LỌ́JỌ́ GBOGBO NI TIYÍN LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ LÁTỌ̀RUN WÁ ÀMÍN ŃLÁ ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤. Ẹ ṣeun lọpọlọpọ gaan ni. Àwa kan mọ rírì iṣẹ́ takuntakun tẹ́ ñṣe
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Lóòótọ́ àti lódodo , ọlá Alimi àtàwọn alakatakiti ẹsin tí tán pátápátá porogodo ní ìlú Ilorin àti ní gbogbo àgbáyé láṣẹ Èdùmàrè látọ̀run wá, ÀMÍN ŃLÁ. Ààrẹ ÒPÌTÀN gbogbo ilẹ̀ Olómìnira Yorùbá ní gbogbo àgbáyé, Ẹ ṣeun o fún ìdánilẹ̀kọ́ pàtàkì láti jẹ́kí àṣà àti ìṣe àwa ojúlówó ọmọ Yorùbá lásìkò yí máa tẹ̀síwájú bótilẹ jẹ́ wípé àwọn ọ̀tá ñgbogun láti da ojú ìtàn bo,lẹ . Olódùmarè a máa sọ agbára yín di ọtun lojoojumọ . Gúnnugú kìí kú LÉWE , ÀÀRẸ ÒPÌTÀN LAJI ABASS YÓÒ DÀGBÀ BÍ ÀWỌN ARÁ ÌGBÀANÌ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ LÁTỌ̀RUN WÁ, ÀMÍN. ÀWỌN ỌMỌ YÍN NÁÀ A MÁA DARA SI NÍ NÍPA ÀṢẸ ÌTỌ́NI ÌRỌ́RÙN OLÓDÙMARÈ ẸLẸ́DÀÁ GBOGBO ÀGBÁYÉ ÀTOHUN GBOGBO TÓ WÀ NÍNÚ RẸ FÚN ÌṢELÓGO ÀÌDÍBÀJẸ́ AYÉRAYÉ. ÀMÌN ŃLÁ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ LÁTỌ̀RUN WÁ
Ẹkú Àgbà Ôlùkọ Àgbà
EKU ISE takuntakun
GOD BLESS BLESS YOU . DR AARE LAJI ABBASI, GOD make you to help us no ,our HISTORY in YORUBA LAND, Thanks for teaching us are HERITAGE. Dr you are too much , thanks.
EKU ISE OLODUNMARE HA MA FUNYI SE
Eku eto sir o
Great
Ogboato babayi
Won Gba Were Mo Esin
😂😂
Lajiabas ejowo se ebira Yoruba ni won.
Yoruba lati Ile Ife niwon, Kaba ATI Ebira, tegbon taburo niwon, awon mejeji Jo jade pelu IFA lati wa ibiti won ma tedo si ni, culture won ki yato si ti awon Yoruba, Ede loyato
Aare, ki Olorun lora emi yin fun wa. E dakun mo ni ibeere kan o, se ojulowo omo bibi Ilorin ni ologbee Sheikh Adam Al-llory ni abi ara awon fulani omo alimi?.
Ejo Eba wa so itan Asotun ti ilu isotun ile ilesha
APC AND PDP QURAN AND BAIBU 4 1 9 🇳🇬 OLE
It's absolutely n completely true, Aare Laji Abass. Emirs r not Oba {Kings} t4 can't ever b in d same category of/as Oba {King} Pls don't get it twisted; categorically Emirs r totally n entirely subordinates to Oba/s {Kings} Emirs r mainly Muslims ie Islamic Religion leaders n r only turbaned n don't wear crowns like real Kings.
Bless Up🙏 @Aare Laji Abass
I mean FLAGGING, there's a typographical error..
For God's sake what wrong have you done?You are only promoting Yoruba's Culture.
YORUBA NATIONA IS THE BEST 👌 👍 😍