O ye ki awon idile jagun jagun ba arole Oderinlo wi gidi gan. O lo irun iwaju po mo ti ipako. O n mu itan Sobo yoke wo inu itan Oderinlo,ko papo rara. Ibadan keji ni itan sobo yoke ti sele,Ibadan keta ni Oderinlo ti je Balogun. Koda,oun gan ko ni Balogun tosi,Elepo ni o ye ko je oye na.
Aare, aalo patapata gbaaa ni Magaji yi n so. Mo ti n so tipe pe awon opitan afiro-gbayi bayi lo n ba itan Yoruba je. Ise po pupo lati se. O je ohun ibanuje pe opolopo awon ti a fi n joye wonyi ko mo itan rara, beeni won ko gbiyanju lati beere tabi wadi itan. E ku ise takuntakun Asre Abass.
You are doing amazing job sir and I love all your narrative of history but on this one sir I’m not in total support of the way Oderinlo effort was illustrated here. It’s seems like you ridicule his image in order for you to debunk all that said by his family. My point is that you can correct Oderinlo family story without make Oderinlo himself look like person of no value. In my opinion

This odenlo is a mule in chief...Emmanuel odenlo fi lamba sile
Gbefun bámi
Alafia fun ile Ibadan
e ku ise ilu ooooo
Gbafun Gbefun Aree number 1
Very interested
Aare, aalo patapata gbaaa ni Magaji yi n so. Mo ti n so tipe pe awon opitan afiro-gbayi bayi lo n ba itan Yoruba je. Ise po pupo lati se. O je ohun ibanuje pe opolopo awon ti a fi n joye wonyi ko mo itan rara, beeni won ko gbiyanju lati beere tabi wadi itan. E ku ise takuntakun Asre Abass.
Eku eto🎉🎉
Pls Are opitan my question is that is all dis happened after death of afonja?
Bẹẹni
You are doing amazing job sir and I love all your narrative of history but on this one sir I’m not in total support of the way Oderinlo effort was illustrated here. It’s seems like you ridicule his image in order for you to debunk all that said by his family. My point is that you can correct Oderinlo family story without make Oderinlo himself look like person of no value. In my opinion
He has mentioned the story of oderinlo before. You can search for itan kurunmi ijaiye. he did not ridicule the man.