Breaking ,,ISELE NLA ,,After protest,,,,O MA KU,I military,,,, Yoruba Nation,,, BIAFRA,,,senators

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 12 вер 2024
  • #trendingnow #prophecy #yorubanation #entertainmentnews #yorubabroadcastingnetwork #yorubapeople

КОМЕНТАРІ • 21

  • @KoikiMedia
    @KoikiMedia Місяць тому +2

    Welcome again sir

  • @agnesakande5157
    @agnesakande5157 Місяць тому +11

    Baba wa Masunkunmo Ese pupo adupe fun Iran ti enfi fun wa Olorun yio ma mu yin tesiwaju ninu Oro re Amin loruko Jesu .Ema pe fun wa Amin Amin Ojo Ayo ni Ojo Ajodun na yio je fun Baba wa Masunkunmo Amin loruko Jesu.

  • @ladbol521
    @ladbol521 22 дні тому

    The Middle belt will be the 4th nation

  • @theresaatunde6955
    @theresaatunde6955 Місяць тому +1

    Emi yin agun Baba ejise Olorun pepe amin

  • @fadipefred9519
    @fadipefred9519 22 дні тому

    I want the presenter to reach out to the President to quickly do the needful for his name to be written in the book of life.

  • @sitepane
    @sitepane 28 днів тому

    Amen 🙏

  • @beautywealth4935
    @beautywealth4935 Місяць тому +4

    Baba masunkunmọ, ọjọ yin yio dalę, Ole ni gbogbo awon Ijọba Nigeria ti a wa ninu rę yi, nitoripe wọn ti ję, ijękuję iję wùrú ninu gbogbo ọrọ Nigeria ti o yę ki gbogbo ọmọ Nigeria ni anfani si, ohun ni wọn o ṣe fę ki a lọ, lagbara Ọlọrun Ọba ti o ni aye ati ọrun, pęlu ipá(force)pęlu àrá(thunder ni Yoruba, Ibo, North maa fi tuka laṣę Edumare. Amin. Bi Ọlọrun Ọba Oke ṣe kọju ija si Pharaoh ni igbaani, nigbati Pharaoh ko fę ki awọn ọmọ Israeli kọja lọ si ibi ileri wọn, bęęni Ọlọrun yio ṣe kọju ija si awọn ijọba ọta ilę Yoruba, ilę Igbo ati ilę North lagbara Ọlọrun ọga ogo. Aaaaaaamin loruko Jesu

  • @KoikiMedia
    @KoikiMedia Місяць тому +2

    Help me greet baba please

  • @adenikefadahunsi1076
    @adenikefadahunsi1076 Місяць тому +2

    Olorun gbodo se idajo larin awon ojelu ati awon ara ilu .Ti idajo kobasi ,ati oba ati ijoye ati awon olori ni Nigeria woni gba pe Olorun wa .Eku ISe takuntakun

  • @user-bg3rg4ds9y
    @user-bg3rg4ds9y 24 дні тому

    Oro agba

  • @lawrenceodubiyi4662
    @lawrenceodubiyi4662 29 днів тому

    Anaverage yoruba man want to leave Nigeria but surprisingly the Fulani who are wrecking Nigeria wants one Nigeria at their own benefit..

  • @AdeolaOhali
    @AdeolaOhali Місяць тому +1

    E se baba mi

  • @AdesolaKilanse
    @AdesolaKilanse Місяць тому +2

    Baba emi yin agun,ise iranse yin yin koni baje lagbara olorun,ejo bawo lase lede church yin sir

    • @John-yk7og
      @John-yk7og Місяць тому

      E pe number ti olootu pe forward the video to 16 minutes and listen to the number and call

  • @samuelekundayo3994
    @samuelekundayo3994 Місяць тому

    MO ki yin baba

  • @AdeolaOhali
    @AdeolaOhali Місяць тому

    Mo ki yin Baba wa, e Pepe fun wa Sir

  • @josephadetoye5527
    @josephadetoye5527 28 днів тому

    The northern people will be the first to leave Nigeria it will surprise everybody.

  • @theresaatunde6955
    @theresaatunde6955 Місяць тому +1

    Ese baba mi fun lbere ti enbere lowo Baba

  • @sitepane
    @sitepane 28 днів тому

    This guy is good, but he talks too much. He ran his mouth to the point that the man of God fell asleep.