ÈSÌ Ọ̀RỌ̀ FÚN BỌ̀DÁ ABUDU RÀSHÍDÌ ÌLÚ ÌWÓ!!

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 8 жов 2024
  • Message to oluwo from ominira omo oduduwa

КОМЕНТАРІ • 26

  • @deborahadenike560
    @deborahadenike560 21 годину тому +2

    OWO ISE TI ABDU GBA LATI DA ILE YORUBA RU ,OHUN LONSE , OLODUMARE LO MA DA FUN RASIDI ,FUN GBOGBO ABURU TON NSE LORILEDE YORUBA 🙏

  • @krystalamb764
    @krystalamb764 21 годину тому +2

    Oro werey lenu Rasidi dindinrin oba

  • @aminuphilip1841
    @aminuphilip1841 22 години тому +5

    Maa gbo oro katikati lenu okunrin elete bombo yi. Igbo to mu kehin ndaa laamu. Eni ibi to gbowo saudi lati ta ile yoruba fun awon fulani nipa esin etan, jagidijagan, dobo-dobo, paniyan-paniyan, odale, ole. Epe kankan ko ja Yoruba. Esin odale yin ni ogun to ndojuko ile yoruba. Ko seni to be o nise pe ki o bawa waasu Jesu tabi bibeli. Ona iye ati alaafia yato gbaa si ona iku ati jagidijagan tiyin. Bi awa ko tile gbagbo ninu orisa bibo, sibe a feran awon elesin yoku nitori eniyan ti Olorun da ni awon naa. Beeni won ni eto si igbagbo tiwon. Ko si afipase ninu esin.

  • @AjuwonOluwafemi
    @AjuwonOluwafemi 20 годин тому +1

    Oluwo o ni lakaye kankan

  • @OlamipoLaw
    @OlamipoLaw 22 години тому

    Thank you my mentor for this update

  • @olatunjibanwo5161
    @olatunjibanwo5161 3 години тому

    Mumulizim😂😂😂😂😂

  • @josephmaito213
    @josephmaito213 22 години тому +1

    Oponu gidi ni oluwo

  • @olufemifawole8499
    @olufemifawole8499 21 годину тому +2

    elenu sukete

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 21 годину тому +2

    Infact, Opolo Rashidi Akanbi (Oba Iwo) ti daru patapata. Elenu petepete.
    Rashidi Akanbi OLEEEEE ! ! Nitori Owo Saudi o fe ba Ile Yoruba je

  • @adebajolanu7755
    @adebajolanu7755 22 години тому

    Mr lecturer ❤

  • @KehindeKareem-b1j
    @KehindeKareem-b1j 3 години тому

    Oluwo is crazy

  • @yomibabalola5277
    @yomibabalola5277 20 годин тому

    RASHID ERU ARABIA, OLE O TI LO GBO OWO LOWO ARABU

  • @olufemifawole8499
    @olufemifawole8499 21 годину тому +1

    A Dara fun e iyami

  • @ola001234
    @ola001234 21 годину тому +1

    ORO RASIDI LE KAKUN
    SE ELEYAN MO NKAN TO NSO LENU

  • @yomibabalola5277
    @yomibabalola5277 20 годин тому +1

    TANI O FI OLORIBURUKU A MU GBO YI JOBA ?

  • @SikirulahiAdeshina
    @SikirulahiAdeshina 21 годину тому

    Arabinrin yi mo ki e pe oku ise , mode fi o salaye Eni today Omi ti an lo mosi Fe ki o selaye Eni to da aye ATI orun then nibo ni atubotan gbogbo awon Eni to kooko Bo orisa , nkan ti ele fi se Omi yatto si Omi Inu ile ATI Omi ojo edakun e salaye ,fun wa ,e Mase fi olorun ododo we Eni kankan

  • @WesternUnion-v7d
    @WesternUnion-v7d 22 години тому +3

    This boy supposed to be Alfa not king 🎉

    • @james_smith9
      @james_smith9 20 годин тому

      Excakly, he aint fit for a King, he's Alsunnah fanatics

  • @danielrasaki9135
    @danielrasaki9135 11 годин тому

    KOSI ILU TI WON KI TI BORISA, SUGBON JU GBOGBO RE LO EJEKI OLUKULUKU SIN OHUN TI O BA GBAGBO, E DAKE IYAN JAJA.

  • @SanyaoluDavidSunday
    @SanyaoluDavidSunday 21 годину тому

    Dummy king ,ororele fun olorun .

  • @abiodunolawoyin9774
    @abiodunolawoyin9774 5 годин тому

    Orisa ile yoruba,is not good,but oju obo obirin tie lo fi ori bale fun ni meka yin ni olorun yin.,,ori yin ti ba je,eyin eranko.,,eru aiye oju obo ti Muhammad gba waye lo gba lo,oloburiku adobolorun omo aleee,bowo le ru se je si olorun.,,,omo alade lo mo Olodumare.

  • @YemiOdejobi
    @YemiOdejobi 19 годин тому +2

    Pls leave Christianity out of this keep them out ur mouth Rashidi magbe Christians mora, nitori a mope iro lonpa.

  • @yankeeebony5149
    @yankeeebony5149 8 годин тому

    Onisese is just making them scared. Oun ja wọn laya bii ẹrù. If not, they would have invaded rue yoruba land a long time ago. That shows that something powerful is behind the isese worshipers. This Olu Ìwó is the last weapon that the Tayuun terrorists are left with. Otherwise they are nothing. He is doing left and right, not stable as water. Trying to appease the Yorubas, and yet deceive them by trying to support yoruba culture in some way and debunk their tradition. Mufti said, this guy gave the goahead for the fulani terrorists from Sokoto, kwara combined to wipe out an entire yoruba village. He is an imposter, because the monet the Yorubas drop their tradition, these people will attack them like anything, and will have no defensive means.

  • @samuelakingbade9717
    @samuelakingbade9717 17 годин тому

    Obonun ni oluwo ati awon to ntele, oluwo is a fraud