E PADE OLUDANI NIMONRAN (IKAANU)

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 29 лис 2024

КОМЕНТАРІ • 23

  • @afeezyahaya9850
    @afeezyahaya9850 27 днів тому

    Eku ise opolo olotu.., ki baba pe Omore ki oba so oro olohun pe agbara re ko ni ogbede ibeti ode loni, ki oko awon aburore monra ki osi fi orijin iyawon ❤❤

  • @wumiodubiyi7262
    @wumiodubiyi7262 24 дні тому

    Imoran temi fun baba yen nipe ki won gbo nkan ti omo won so yen ooo ti won ko ba fe ki Omo yen ko ma gbe ago ti won na mo nipa ti awon omo iyawo ki won so fun iyawo won ko wa aye lati be omo yen dada ki omo yen le yonu si awon Omo e e seun pupo olugbani nimoran lakaye yin koni pare lase olohun

  • @ajokeakeem5834
    @ajokeakeem5834 24 дні тому

    E dakun oludani nimoran wa, iyawo ore won yi ni kojoko, gbogbo ara nimo fimo,elekeji,ki Baba yi pe omo yi kiwon ba soro dada pe ara awon ni awon omo yi ti jade gege bi ibi ti ohun na gba wa saye,pelu ase olohun o ma gbo si Baba ee lenu

  • @christianaomoleyemudasiru5982
    @christianaomoleyemudasiru5982 26 днів тому

    Ko ti le ye ki iyawo baba yi mura lati joko si aye iya omo rara. Baba lo ye ki o fi oro Olorun ba omo re soro lori awon aburo re. Ki omobinrin yi fi ohun gbogbo mo Olorun. Ko ma se gba esan rara.

  • @ajokeakeem5834
    @ajokeakeem5834 24 дні тому

    Eseun gan ni fun oro olowo iyebiye teso yi,eko nla re o,opolo yin koni baje bijjah Rosullullahi (SAW)

  • @alimatonashokun8497
    @alimatonashokun8497 27 днів тому

    Ese Olotu oro ti wo wa lati ibere ovale fun omo yi ki oni ife obakan e Tori ikan ti Iya won fi oju e ri .

  • @HdjdjdjHxjxjjx
    @HdjdjdjHxjxjjx 26 днів тому +1

    Hmmm eku ise olotu kosi asegbe laye asepamo lowa ki baba omo yen ran iyawo re leti gbogbo bose wu iwa si omo yen ni igba togbe ni odo won fun idi eyi koso fun iyawo re omo kofaramo kojo gege bi iya ohun latari iwa toti wusi ki iyawo ore resi joko gege bi iya re nipa tawon aburo re owo iya awon omo yen ni iyen kusi ki iya awon omo gan ba omo yen soro kosi toro aforigin lowo re pelu iwa toti wusi ni kekere

  • @YoussoufYoussouf-m1x
    @YoussoufYoussouf-m1x 26 днів тому

    Bonjour que dieu vous guide beaucoup pour (la femme celui qui tue pas l'épée mort par l épée ) que son père lui dire que on ne rendre pas le Mal pas le Mal

  • @deaconesseshtodeleye7620
    @deaconesseshtodeleye7620 24 дні тому

    Enito ba to Omo ni iya Eni, e je ki iyawo ore baba Omo joko iya e, elekeji ni ti awon aburo re, baba yen ni ise gidi lati SE, o gbodo tu arin yen to, idi niyen ti ko fi dara ki enia ma huwa Ika, ki won so fun stepmom ko lo duro de asiko awon Omo ti e

  • @bolariwayessoufoualaoadeko7095
    @bolariwayessoufoualaoadeko7095 26 днів тому

    Beeni olotu oneto nitori inase naba iwa nawu nakan nipa ti awon aburo ki baba won ma pa arowa pèle pèle nitori toba to assiko iye ré yo nipa alajobi

  • @margaretlewis4833
    @margaretlewis4833 26 днів тому

    Eniti o ba Toni ohun ni iya Tabitha baba ,Oluwa ti koya fun omo na ,ti o ba to asiko ,adariji omo baba re, e fi omo sile ko se ife in re.

  • @momohabdulrasheed8889
    @momohabdulrasheed8889 26 днів тому +1

    The man should tell his wife to stay away from the high table and let her know the reason. He should pray and rely on God alone. She may want to do evil against the child. The woman should seek forgiveness from the child and talk to her children to unite with her. The man should talk to the child to forgive her siblings, what goes around comes around. Do good to everyone not because they deserve it but because God is watching and love those that are doing good.
    Thank you sir, may Allah continue to strengthen you.

  • @SafeSeniors5
    @SafeSeniors5 26 днів тому

    Ki baba ba fe bi oti fe ko sa ni ko to si agba ko ra aso ojo kan iyawo ti ati ore iyawo orere ti awon omo atun se ye owo baba lo ku si ohun ki ma ba omo e agba so oro to iya awon aburo gbin oro ègbon won ninu

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 27 днів тому

    Hmmm
    Eku Eto sir
    Olohun yio ma se alekun ogbon Ati imo yin
    Haaaa eleyi gbenu tan oo
    Iyawo ore lama ni Iya Lotito
    Emio
    Se awon ebi Iya re ma wipe o wa laye tele ni?
    Ki won tu Toba sini o hun kogba kogba niyen
    Ki Iyawo ore baba re joko gegebi ojuse Iya

  • @SafeSeniors5
    @SafeSeniors5 26 днів тому

    Imoran temi si yin wipe ako da oro ko da bi adagbeyi se owo ika ti iyawo baba fi lyawo ore baba re bo bamu omo ye so d la ti baba mo juto ki o le ni ojo ola

  • @monsurat.anikeikumapayi3452
    @monsurat.anikeikumapayi3452 26 днів тому +1

    The girl has the right to be happy on her day. Her wicked step mother should stay away from the high table.
    Regarding her half siblings,she should not pay back evil with evil. The man is too weak to control his wife. He should tell the wife to apologise to her

  • @bolatitooke
    @bolatitooke 25 днів тому

    This case is straightforward issues.
    The father should inform the stepmother to stay away from the high table she should respect the lady wishes.
    E ni to ba toju omo lon jere omo.
    As for her stepbrother, they're not here responsibility, but she can support his father's (,,just to worship God from their life) Ko ti ara won sin Olorun. God already blessed her up

  • @adesolaestherogunbodede6754
    @adesolaestherogunbodede6754 26 днів тому

    Eku ogbon ati oye sir . Imoran mi Baba omo yen ni wipe , ki o gba imoran omo re pupopupo nitori ara ita ni o ba to. Ati wipe ko gbodo gba iyawo re yi lati wa ni high table ni ojo na rara nitori wipe oni ewu. Imoran ni wipe baba yi ki o gbadura gidigidi kan lori omo na . Awon omo baba re yi ni ewu nitori iya awon omo na . Oluwa ma wa pelu wa . Thank you sir

  • @jamiuabayomi7957
    @jamiuabayomi7957 27 днів тому

    The father should inform the step mother to stay away from the high table. The father should be prayerful and also lobby the girl to accept her siblings they are innocent.

  • @AbdelMAZU
    @AbdelMAZU 23 дні тому

    Hello everyone. Thanks for the program. I really like it and enjoy it. I’m living in Brussels and i want to contact you about how can i choose the right wife for me.

    • @GOPROMMEDIA
      @GOPROMMEDIA  22 дні тому

      Call or message 08052175314 on Whatsapp thanks

  • @Compa834
    @Compa834 25 днів тому

    The mother’s friend supposed to sit as the mother on the wedding day unless she volunteer not to for peace to reign. But if someone deserves prayer and they were cursing her, the curse will not come upon her, but if she deserves curse and they were praying for her the prayer will not manifest in her life. God knows who to be praised. If I’m in the position of the mother’s friend I will voluntarily release myself standing in gap as the mother unless there will be two mothers on that day for peace to reign and everyone have to sit together and have a solid conversation and agreement before the wedding day.

  • @Compa834
    @Compa834 25 днів тому

    The mother’s friend supposed to sit as the mother on the wedding day unless she volunteer not to for peace to reign. But if someone deserves prayer and they were cursing her, the curse will not come upon her, but if she deserves curse and they were praying for her the prayer will not manifest in her life. God knows who to be praised. If I’m in the position of the mother’s friend I will voluntarily release myself standing in gap as the mother unless there will be two mothers on that day for peace to reign and everyone have to sit together and have a solid conversation and agreement before the wedding day.