god you are the king 👑👑👑 of king so there is another King like king Nebuchadnezzar huuun I pray that god will take absolute control of ifo ogun state😢😢😢
O ye ki a mo irohin leerefe any time ti honourable, speaker, governor, chairman local government ati president ba ti ngba idajo won. Nitoripe ko gbodo si eniti o koja tabi ju ofin ni ile wa.
Man yii ti se opolopo eniyan o🤔 asiko esan gbogbo ise owo e lo to, very wicked soul 🤔😏 Ahhhh kini ki awon Oba first class wa se nigbati oun oba etile n huwa bayii 😮
Ita nikan ko lori ade maa sun ori ade ma sun ewo yio sunnu ibgo pelu. Ika obayeje oloriburuku. Talofe bail ika? Is not the only one using veto power on other people is time they remove them
Two wrongs will never make a right. I plead the Ogun Obas bail him for correction, second life to correct those with same spirit. Armed Robbers have become Evangelist in Nigeria and their performance have become standard to turn to God. Too complex issue and a way to know God for many !!
God will bless you in your work Amen
Oba ofo very good o ma darugbo si nu ewon ni oloriburuku somebody 😅😅😅😅 oba elewon 😅😅😅
Oba elewon of ewon Ilaro.😅😅😅😅😅
Awon Oba ti won fi ote ati ipa joba, gbogbo won lo maa sesin agbàye, kudos to you and the prophecies.
Iwa re ko dara rara, that's why he didn't see surety to bail him 👌 oni jaginnijagan eeyan buruku...a yonda ki won gbe Ade fun ninu ewon😂😂😂😂
B'Olorun Oba se mama fi won se eleya niyan, gbogbo awon alagbara to nfi agbara won gba alailagbara gbaragbara l'ase Edumare Amin.
Oloribu oba ofoo,tounte oju awon agbalagbaa molee
Olu of Ogbaewon!! 😜😜😁😁😁😁
😂😂😂😂Nigeria moi country
god you are the king 👑👑👑 of king so there is another King like king Nebuchadnezzar huuun I pray that god will take absolute control of ifo ogun state😢😢😢
Elese ko ni lo laijiya. Iru won ni awon oba ljoko, Olorun ma fi lya je awon na..
EWON LOMA GBO SI LOLA OLOHUN ATI LEYIN ANABI WA MUNMADU SAW SAW AMEEN KUN FAYA KUNMU
😂😂😂😂😂😂no one can stand bail for him bcus he may escape
So, he will go and become Oba in the prison. 😅😅😅😊
That is to say, o bo lati inu ògo bo si inu ògo, alade ògo maa wolè. 😂😊😅
Semiu se eleya ninu ogba ewon,asepamo ni o wa,ko si asegbe.
Who is the next Oba in Yoruba land going to prison soonest?
I think Is in osun state
Olu Iwo is the next Oba that will go to prison next
ATI awon oloribu aladanwo OLORI oni ojajaa naa ,oye katigbo nipa OLORI Mariam ATI OLORI tobi kawon na tilo maje OLORI fun awon ELEWON na
Esin yi is too much..ha!! Oga ju
Kabiyesi OO,Obatonfoba jee,Oba tonro oba loye,oba semiu GBA gbe wipe Obanla waloke ton wo ise oun,Iran farao
Iwa tani o ma mu mi ko dara rara . OLORUN OBA Kotida eniti Ko Le Mu , Asilo agbara biti pharaoh ko dara rara.
REVELATIONS : 22 vs 12.
O ye ki a mo irohin leerefe any time ti honourable, speaker, governor, chairman local government ati president ba ti ngba idajo won. Nitoripe ko gbodo si eniti o koja tabi ju ofin ni ile wa.
Won po dada awon were yi. Oba matanmi ati oba ljoko ti fi aye su awon ara ljoko na. Olorun a mu awon na sise.
Man yii ti se opolopo eniyan o🤔 asiko esan gbogbo ise owo e lo to, very wicked soul 🤔😏 Ahhhh kini ki awon Oba first class wa se nigbati oun oba etile n huwa bayii 😮
AMIN OOO
😂😂😂😂😂esin yi po faaa
Ita nikan ko lori ade maa sun ori ade ma sun ewo yio sunnu ibgo pelu. Ika obayeje oloriburuku. Talofe bail ika? Is not the only one using veto power on other people is time they remove them
Awon oni dethroned e. So awon ma fi je Oba iku ewon. Loo baa tan. Iba awon eleewon.
Oba Nebukadnasari
🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣
Abdulsemiu janduku. Ori ade Semiu ti sun ewon ni ilaro.
Two wrongs will never make a right. I plead the Ogun Obas bail him for correction, second life to correct those with same spirit. Armed Robbers have become Evangelist in Nigeria and their performance have become standard to turn to God. Too complex issue and a way to know God for many !!
Who's this again blogging is not for everyone