Baba wa e se o te ba tun ile yoruba se o won fe ta wa so ko eru nitori o da oja sile o fe fi yen ma command ile yoruba se oun ni ijoba ni aya ko o mbu awon baba wa nitori esin arinfin gba a
Sallam Alaikum Alfa Abdul Akim,Sheria ti won Fe gbe WA lasi ko yi kise fun alafia Yoruba agenda Fulani lati fi da ija sile larin Yoruba,kia sora o Maha sallam
Alfa you’re addressing the matter in a very respectful manner don’t allow people to make you insult the King.What you are saying make sense and the king also hold his Opinion.But don’t cross the redline with insult,Religion is delicate issues in Nigeria,Let God judge everyone.Nigeria will great again.
Ki awon yoruba dide si okunrin yi gale gale tl npoju Muslim ni baba mi Christian ni iya mi baba mi npa era ileya to ba Di christmas a je turkey ko si wahala a gbe igbe alafia pelu baba wa kilowatt ti mufty o wa da family ru
Kole da ogun kankan sile, from where nh! ... to where. Do you people think something will just happen? How ? Think of it now, since all the years of Islamic fundermentalis in yoruba land, then ; what is the joy, instead of expanding is diminishing. Everybody should think now. Oga o
Lati keeper wa a ni Muslim nile wa a ni Christian ani isese won de ja ri gbogbo family ni metatarsal wa a Jo nse ileya ni a Jo nse Christmas ni isese ngbadura ti won a o ja ri o wa ni oun na awon baba wa nitori esin ki ijoba pe baba yi fun ikilo
Gbogbo yin oni ise nitorina le SE fe ku si esin elesin gbogbo Oro jatijati ti eyin Alfa so wonyi kinni o da fun eniti ebi npa, SE oro oshi te so gbe ounje sori table abi Ede elede te so yi ki lo da fun eniti ebi npa.
Allah bless you.
Thank you sir e ku lakaye e wi re ❤❤❤ UK
May Allah bless you alfa akeem, awa o se sharia law nile Yoruba, ete ati ogbon lati le so Iran Yoruba deru fulani ni
Ododo oro!
Se Ouran ni won fi se ogun yen abi kini. Eyin apayan yi.
Pelepele fun mufty kan te jeje ti o b fe te ko le ma bu awon baba wa loju wa won a dide si
More wisdom sir.
Baba wa e se o te ba tun ile yoruba se o won fe ta wa so ko eru nitori o da oja sile o fe fi yen ma command ile yoruba se oun ni ijoba ni aya ko o mbu awon baba wa nitori esin arinfin gba a
Sallam Alaikum Alfa Abdul Akim,Sheria ti won Fe gbe WA lasi ko yi kise fun alafia Yoruba agenda Fulani lati fi da ija sile larin Yoruba,kia sora o Maha sallam
Ni Lagos state about nse ileya ati christmas ni a o ya ara wa soto ko ma da ile yoruba ru
Mopatewo fun yin sir e ri mi so
Alfa you’re addressing the matter in a very respectful manner don’t allow people to make you insult the King.What you are saying make sense and the king also hold his Opinion.But don’t cross the redline with insult,Religion is delicate issues in Nigeria,Let God judge everyone.Nigeria will great again.
O ndoju ti yoruba gidi awon baba wa o ni gba fun
Se awon ni won nse ijoba ni abi killed ti galegale po to yi
Olrorun o ran enikankan nose se esin ti e ko si nkan to kan e pelu esin elesin ko ni kaduna se ti e
Omo odun melo ni mufti iwo naa ri, tosinja kaakiri bayan lorisirisi lati ojo yi. Kolo so ewe agbeje mowo kia. Ile Ootu kiise egbe re ooo
Ki awon yoruba dide si okunrin yi gale gale tl npoju Muslim ni baba mi Christian ni iya mi baba mi npa era ileya to ba Di christmas a je turkey ko si wahala a gbe igbe alafia pelu baba wa kilowatt ti mufty o wa da family ru
Kole da ogun kankan sile, from where nh! ... to where. Do you people think something will just happen? How ? Think of it now, since all the years of Islamic fundermentalis in yoruba land, then ; what is the joy, instead of expanding is diminishing. Everybody should think now. Oga o
O to ni a ri video omobinrin yen ni London o surprise wa
That man call himself mufty Iwo is not resemble Muslim look at his face just like something else.
Lati keeper wa a ni Muslim nile wa a ni Christian ani isese won de ja ri gbogbo family ni metatarsal wa a Jo nse ileya ni a Jo nse Christmas ni isese ngbadura ti won a o ja ri o wa ni oun na awon baba wa nitori esin ki ijoba pe baba yi fun ikilo
Gbogbo yin oni ise nitorina le SE fe ku si esin elesin gbogbo Oro jatijati ti eyin Alfa so wonyi kinni o da fun eniti ebi npa, SE oro oshi te so gbe ounje sori table abi Ede elede te so yi ki lo da fun eniti ebi npa.
You’re indirectly propagating the sharia idea