AWON FULANI ADARANJE TUN TI SE AKOLU SI AWON ARA ILU YI

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 8 вер 2024
  • A O GBODO MA BA LO BAYI O

КОМЕНТАРІ • 36

  • @debbyakinleye5024
    @debbyakinleye5024 2 місяці тому +1

    ARole, kilode ti awon Agbe o le fin oko won , se baby ni awon Agbe wa.

  • @ceciliabola1650
    @ceciliabola1650 2 місяці тому

    Baba arole won ti fe inkan si ategun fun omo Yoruba ejo yi saaaa ni e ri to ni o sa pamo o wa n fi malu je oko aruwo to sa ni o Ma se oooooooo o gaa

  • @florencedairo3888
    @florencedairo3888 2 місяці тому

    E lo ran ARA si won ko sin pa won, asiko Ojo ni yi. E ran Ara si won, Eni to pa Fulani marun to pe o je Oko won , adajo Osun ni ki wo lo ye ki mo awon Yoruba. Ojo ti Fulani ti n pa Awon agbe loko,Ojo melo ni won ni ki lo ye ki mo Fulani, Olorun ase da Jo fun adajo ye laiye lai jina, Yoruba nation no going back

  • @omoyorubaedide9697
    @omoyorubaedide9697 2 місяці тому +3

    WON TI FI ESIN AJOJI BA AYE WA JE NI ILE YORUBA, AROLE KO SI UNTI ARAKUNRIN YEN LE SE , TI O BA GBAS IYANJU LATI FI IGI LASAN LU OKAN NINU AWON MAALU YEN ,MO LE FI DA YIN LOJU PE OKU E NI WON MA GBE KURO NINU IGBO YEN NITORI ESIN AJOJI

  • @isaacstrongtower-ws9qm
    @isaacstrongtower-ws9qm 2 місяці тому +2

    THE GOVERNORS ARE HAPPY ABOUT IT otherwise they will act accordingly.

  • @iyabolawal9520
    @iyabolawal9520 2 місяці тому

    Iyeenn loyeeh keeh maa se iso nunn eeeh kuu Awoon noooo nwa maa munn mooraa nii teeh baa paa bii maa runn moo raa

  • @sanitempleprayer472
    @sanitempleprayer472 2 місяці тому

    Won ti fi àdua de gbogbo omo yoruba atunse ku si owo olodumare o

  • @jamesitaronbi3889
    @jamesitaronbi3889 2 місяці тому

    AROLE BABA 10 10 EKU ETO DIE LOKU MA TO YE GBOGBO YORUBA

  • @hungboanthony7770
    @hungboanthony7770 2 місяці тому

    Be nio won nmo 15:33 mo se gbogbo Ise ibi yii. It is time for FIRE for FIRE.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому

    Awon Oba ile Yoruba ati governors ile Yoruba ati awon oloselu ni won gba awon fulani wonyi laiye nkan ti won nse nitori gbogbo won ni malu lowo Fulani

  • @patrickakinbola4052
    @patrickakinbola4052 2 місяці тому

    Yoruba warriors! Keep up the great job you’re doing! 🦾

  • @user-bd3ih2en3o
    @user-bd3ih2en3o 2 місяці тому

    Aroleeee.Esin igbagbo lo sowa Di omugo ,dindinrin,ni île wa oo,Ti kii ba se beeni,agbara awon baba wa po de biipe,ara nbe,agbon nbe,ejo nbe,oyin nbe,igbona nbe,awon ebora nbe,ore oogun nbe,aluwo nbe,to jepe tiaba nawo re jade ni gbogbo île wa,fun ra ara won ni won maa salo patapata Kuro ni ilewa,ATI egbe boko Haram,won o le duro mon lailai.

  • @DareJoseph-mx1zn
    @DareJoseph-mx1zn 2 місяці тому

    Arole eeku ise Latipa fulani koni isoro awayoruba latiboasiri awan topa fulani nikoko arawa na lomatu asiri fun awan agbofinro

  • @Sayitasebe
    @Sayitasebe 2 місяці тому

    Se awon were yen o le le maaluu funra won ni

  • @helenahmed9189
    @helenahmed9189 2 місяці тому

    Traditional rulers should stand up and have security system for all the farm in their locality. Farmers should have their own association in the area and have have ode, hunters, to watch the farmland. Can a watch tower be built by the help of local government to have surveillance of the area farms? When a Fulani herd is sported, hunters can be contacted if they cannot be employed by farmers association to watch the farms in the area.

  • @mathewolusoladiekola1765
    @mathewolusoladiekola1765 2 місяці тому

    Eru lonbawon pe tawon base nkankan fawon malu yen, Fulani Mafi ibon pawon sinu oko nibe

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt 2 місяці тому

    Yoruba nation no going back ekale sir ooo baba mi arole baba 10 10 eku ise takun takun sir ooo abo olorun ama ba Yin GBE tie bi ti ara yin na ooo

  • @hungboanthony7770
    @hungboanthony7770 2 місяці тому

    AROLE Baba 10 10 gbogbo wa lati ri lasi ti gbo gbogbo ariwo te enpa. Awon eniyan wa ya eleti kunkun Awon eniyan wa ya alai gboran. Odigba ti onikaluku ba pada si isedale wa lati lo ro Ara wa ni Agbara. Lai se yen akole koju si Awon Fulani yii.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 місяці тому

    o di lgbati awa omo Yoruba ba dide ogun si awon oba ati governors ati oloselu bi ti Kenya ibi kan lo ti ma bere ni nigeria kio to kari gbogbo orile ede Nigeria yen

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt 2 місяці тому +2

    OGA ooo AFi kia TE TE Fi Owosowopo ni gbogbo Ile Yoruba patapata ni tori awon FULANI radarada tio WA ni gbogbo Ile Yoruba patapata Yi ooo

  • @iyabolawal9520
    @iyabolawal9520 2 місяці тому

    Kilee lese siiruu eyii baayii eehh jee koonn moonn eeleyii kobo raraa inkoonn tee baa mooonn

  • @user-yw3iy7iu6w
    @user-yw3iy7iu6w 2 місяці тому

    Arole , gbogbo theory yen kole work .
    Temi nipe awa Omo Yoruba SI nse drama lowo ni . Toba ti yawa , ATI Le Fulani kogbawa ni osu kan soso pere . Iba omo Adeyemo , iba Banji Akintoye ATI awon agbagba to won moye - moran .
    Iba opolopo oponu tiwon nfi Oro aigbon bati Iran Yoruba je , sugbon tiwon npe Ara won ni sorosoro ajijangbara Ile- Yoruba .
    Arole ti Ile- bamo , gbogbo wa ma rira wa kedere .

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 2 місяці тому

    E ku ise takuntakun

  • @SodipoAkinwale
    @SodipoAkinwale 2 місяці тому

    God safe us from Fulani

  • @helenahmed9189
    @helenahmed9189 2 місяці тому

    People feel powerless because the Fulanis have ammunition but they have no one to help them. Can the traditional rulers in Yoruba land know in their locality and have ode to know who are the Fulani herders in their area.
    If the Fulani herders cannot obey the law of the land, they should be driven out of Yoruba land. Let Yorubas start their own ranches and boycott Fulani cows

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt 2 місяці тому

    Koyen kia si ma ri gbogbo nkan radarada Yi mo ni gbogbo Ile Yoruba patapata ba Yi ooo

  • @adeyemiolufadeju2254
    @adeyemiolufadeju2254 2 місяці тому

    Kini awon Governor ati awon Oba nse?

  • @helenadegoke6922
    @helenadegoke6922 2 місяці тому

    Ani omo go eni koma ku kini npa omo ju ago lo?

  • @iyabolawal9520
    @iyabolawal9520 2 місяці тому

    Woonn sera Awoonn nii is Aa woonn kaanwoon eyaan waa nooon maa soo woonn do you an doo
    Miin

  • @user-bd3ih2en3o
    @user-bd3ih2en3o 2 місяці тому

    Iwa were buruku ni awon eniyan wa nhu sée,kinni vidéo ti won maa nse gan ri,A nsope ki e maa pawon labenu niooooo.

  • @olusolaayindefakeye4426
    @olusolaayindefakeye4426 2 місяці тому

    Ko ye kiiru video yi si wa titi di akoko yi.

  • @sikiruoluwasegun6804
    @sikiruoluwasegun6804 2 місяці тому

    Yoruba nation is the only way.Yoruba nation no going back.we won't freedom in Yoruba land 1999 constusion is a scammer

  • @debbyakinleye5024
    @debbyakinleye5024 2 місяці тому

    Ko ye ka si Mari iru video yi mo, ki lo se Oloko, ki lo se ti won ko fin oko yi.

  • @ahmedadeleke1722
    @ahmedadeleke1722 2 місяці тому

    You are in South Africa and you are advising them to kill the Fulani hardmen using their cows to eat farm produce? Do you want to say you don't know what will follow next?

  • @adeyemiolufadeju2254
    @adeyemiolufadeju2254 2 місяці тому

    Please don't share this man's video, this program is against the Church. Eeranko