Eyin omo ogbomosho a da fun yin o, ilu ogbomosho ko ni tuka o, ilu ogbomosho ko ni daru o e kare po omo oko ni yin e duro tan, eyin musulumi tooto eyin omo iya dada ninu musulumi e ku aduro ti Oba Gandi alujona ni ti yin ooo.
True and sensible Muslims in Ogbomoso, I salute you all. Bi elete ko ba te, ara re kii ro. Ole nfa ole mora, won nfi esin boju fun ise ibi won. Won fe fi tipa-tipa je gaba lori eyin ojulowo musulumi alaafia. Won fe so yin di alakatakiti ati terrorists bii tiwon. Won sebi mumu ni gbogbo musulumi Ogbomoso ati ile yoruba ati Nigeria. Bebi ti seju. Awon eru Alimi afipa gbale fun Fulani. Won fe jise eleje ti won ti gbowo re lati saudi bii Judasi. Enikeni to ba fe gbale Yoruba fun Fulani tabi ti o fe da ogun sile laarin wa, esinkesin ti o ba ti wa, ori ara re ni yoo fi gbee. Oju tie, self-acclaimed, local and unrecognized Mufuti toogi.
Wow! God bless you Sir..... ❤️❤️❤️🌹❤️❤️❤️ I'm happy that you are not relegated your King. Longlive OBA GHANDI, Longlive Ogbomosho.
Good response to senseless Mufti TAHUN Iwo who’s his mouth 👄 had been disconnected from his brain 🧠
Mufti fe ki ilu Ogbomosho daru. Olorun yo doju ti.
Thank you Baba,you are the best
omo oko ogbomoso ni yin sir. nice one
Eyin omo ogbomosho a da fun yin o, ilu ogbomosho ko ni tuka o, ilu ogbomosho ko ni daru o e kare po omo oko ni yin e duro tan, eyin musulumi tooto eyin omo iya dada ninu musulumi e ku aduro ti Oba Gandi alujona ni ti yin ooo.
True and sensible Muslims in Ogbomoso, I salute you all. Bi elete ko ba te, ara re kii ro. Ole nfa ole mora, won nfi esin boju fun ise ibi won. Won fe fi tipa-tipa je gaba lori eyin ojulowo musulumi alaafia. Won fe so yin di alakatakiti ati terrorists bii tiwon. Won sebi mumu ni gbogbo musulumi Ogbomoso ati ile yoruba ati Nigeria. Bebi ti seju. Awon eru Alimi afipa gbale fun Fulani. Won fe jise eleje ti won ti gbowo re lati saudi bii Judasi. Enikeni to ba fe gbale Yoruba fun Fulani tabi ti o fe da ogun sile laarin wa, esinkesin ti o ba ti wa, ori ara re ni yoo fi gbee. Oju tie, self-acclaimed, local and unrecognized Mufuti toogi.
This one is too much ooo. May Allah make peace reign in Ogbomoso, and all Yoruba land and in Nigeria as a whole.
Omo oko Ogbomosho ni baba may your years be long
Oloriburuku ni mufty iwo yen, ati wipe gbogbo eyin ti e n ta Ogbomoso sita, eyin alabosi,eyin nu Olorun nu.
Eje mufti iwo ni won ma fi se etutu fun ilu ogbomosho.
Good we bless you sir true talk sir
Kaare! Omo Oko Ogbomosho ❤
Good reply 👍
Plan imam ogbomoso ATI mufutau iwo ni wipe won fe ki oba ogbomoso na je ti musulumi nikan ki soun na Le ma se Ori sile biti Rasheed iwo
Ogbomosho people are intelligent . Well done sir
Well said thanks you sir
Ki iru yen ma soro si soun ile Ogbomoso
Bismillah
Omo oko kan, ko ni wu iwa omo ale.