IṢẸ́ L'ÓÒGÙN ÌṢẸ̀Ẹ́ 1) Mú'rá sí iṣẹ́ ẹ̀ rẸ́, ọ̀rẹ́ ẹ̀ mí Iṣẹ́ ní ns'ọ́'ní d'Ẹ́ní gígá Bí á kò bá r'Ẹ́ní fẹ̀hìn tì Bí ọ̀lẹ́ l'àárí Bí á kò r'Ẹ́ní gbẹ́kẹ̀lé Á tẹ́'rá mọ́' ṣẹ́ ẹ́ Ẹ́ní Ìyá à rẹ́ lè l'ówó l'ọ̀wọ́ Bàbá à rẹ́ ṣì lè l'eṣín l'Èèkàn (L'ẹ́ṣín l'Éèkàn- has horses in the stable) Bí Ó bá gb'ójú lé Nwọ́n Ó tẹ́ tán ní mó sọ́ fún Ọ́! Ṣ' óhún tí á kò bá j'ìyà fún ún Iyẹ́n kì í t'ọ́jọ́ Ọ̀hún tí Á bá f'árá ṣ'íṣẹ́ fún Ní npẹ́ l' lọ́wọ́ Ẹ́ní Apá l'árá, igúnpá n' Íyèèkàn (íyèèkàǹ- relative) Bí Aiyé bá fẹ́ Ọ́ l'ónì í Bí Ó bá l'ówó l'ọ́wọ́, nwọ́n á tún fẹ́ Ọ́ l'ọ́lá Tábí kí Ó wà n'ípó àtàtà, Aiyé a yẹ́ Ọ́ sí t'ẹ̀rín-t'ẹ̀rín Jẹ́ kí Ó d'Ẹ̀ní tí nráágó Kí Ó wá wó bí nwọ́n yíó tí má á yín'mú sí Ọ́ Ẹ̀kọ́ ọ́ sì nsọ́'ní d' Ọ̀gá á Yáá'rá kí Ó kọ́ ọ́ dárá-dárá Bí Ó sì rí ọ̀pọ̀ èníà Tí ń fi ẹ̀kọ́ ṣ' ẹ̀rín rín Dá'kún, má f' árá wé nwọ́n Ìyá mbẹ́ f'ọ́mọ́ tí kò gbọ́n Ẹkún mbẹ́, f'ọ́mọ́ tí ń sá kírí Má f'òwúrọ́ ṣ'éré Ọ̀rẹ́ ẹ́ mí Mú'rá s' íṣẹ́, ọ́jọ́ nlọ́ 2) Já itánnà t'ó ntàn T'ó tútù t'ó sì dárá Má dùró d'ọ́jọ́ ọ̀lá Àkókó ńsáré tété
Ise logun Ise
IṢẸ́ L'ÓÒGÙN ÌṢẸ̀Ẹ́
1) Mú'rá sí iṣẹ́ ẹ̀ rẸ́, ọ̀rẹ́ ẹ̀ mí
Iṣẹ́ ní ns'ọ́'ní d'Ẹ́ní gígá
Bí á kò bá r'Ẹ́ní fẹ̀hìn tì
Bí ọ̀lẹ́ l'àárí
Bí á kò r'Ẹ́ní gbẹ́kẹ̀lé
Á tẹ́'rá mọ́' ṣẹ́ ẹ́ Ẹ́ní
Ìyá à rẹ́ lè l'ówó l'ọ̀wọ́
Bàbá à rẹ́ ṣì lè l'eṣín l'Èèkàn (L'ẹ́ṣín l'Éèkàn- has horses in the stable)
Bí Ó bá gb'ójú lé Nwọ́n
Ó tẹ́ tán ní mó sọ́ fún Ọ́!
Ṣ' óhún tí á kò bá j'ìyà fún ún
Iyẹ́n kì í t'ọ́jọ́
Ọ̀hún tí Á bá f'árá ṣ'íṣẹ́ fún
Ní npẹ́ l' lọ́wọ́ Ẹ́ní
Apá l'árá, igúnpá n' Íyèèkàn (íyèèkàǹ- relative)
Bí Aiyé bá fẹ́ Ọ́ l'ónì í
Bí Ó bá l'ówó l'ọ́wọ́, nwọ́n á tún fẹ́ Ọ́ l'ọ́lá
Tábí kí Ó wà n'ípó àtàtà,
Aiyé a yẹ́ Ọ́ sí t'ẹ̀rín-t'ẹ̀rín
Jẹ́ kí Ó d'Ẹ̀ní tí nráágó
Kí Ó wá wó bí nwọ́n yíó tí má á yín'mú sí Ọ́
Ẹ̀kọ́ ọ́ sì nsọ́'ní d' Ọ̀gá á
Yáá'rá kí Ó kọ́ ọ́ dárá-dárá
Bí Ó sì rí ọ̀pọ̀ èníà
Tí ń fi ẹ̀kọ́ ṣ' ẹ̀rín rín
Dá'kún, má f' árá wé nwọ́n
Ìyá mbẹ́ f'ọ́mọ́ tí kò gbọ́n
Ẹkún mbẹ́, f'ọ́mọ́ tí ń sá kírí
Má f'òwúrọ́ ṣ'éré Ọ̀rẹ́ ẹ́ mí
Mú'rá s' íṣẹ́, ọ́jọ́ nlọ́
2) Já itánnà t'ó ntàn
T'ó tútù t'ó sì dárá
Má dùró d'ọ́jọ́ ọ̀lá
Àkókó ńsáré tété