LATEST & TRENDING NEWS FOR THE DAY...IROYIN AKOJOPO AGBEYEWO LORI YBN..NIGERIA & YORUBA NATION NEWS

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 15 вер 2024
  • LATEST & TRENDING NEWS FOR THE DAY...IROYIN AKOJOPO AGBEYEWO LORI YBN..NIGERIA & YORUBA NATION NEWS
    #trendingnews
    VIDEO LINK: • LATEST & TRENDING NEWS...
    FOR MORE VIDEOS: / yorubabroadcastingnetwork
    SUBSCRIBE TO OUR CHANNEL: / yorubabroadcastingnetwork
    #trendingnews YBN

КОМЕНТАРІ • 20

  • @sikiruoluwasegun6804
    @sikiruoluwasegun6804 9 днів тому +1

    Yoruba nation no going back

  • @princegabriel.975
    @princegabriel.975 10 днів тому +2

    Yoruba Nation is the only Solution

  • @bellomodo3184
    @bellomodo3184 10 днів тому +3

    Esee éku eetoo

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому +1

    Eyin Olopa ilu Nigeria eku ise nla naa o!!!! Inu mi dun bi e seri awon oloriburuku apayan yii mu....💯👏

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому

    Oga olopa muyinwa eku ise o💯👏

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому +1

    Ilese YBN lroyin kakiri Agbaye 👍👍👍💯

  • @Mummytiobad
    @Mummytiobad 9 днів тому +3

    O se nilaanu pe government Nigeria ko se olooto pelu awon omo Nigeria

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому

    Eku irole sir! Mr Seyi lpadeola

  • @AlkasimMuhammadBello-x5s
    @AlkasimMuhammadBello-x5s 9 днів тому +1

    Mr president is merciless

  • @AlkasimMuhammadBello-x5s
    @AlkasimMuhammadBello-x5s 9 днів тому +1

    President Tinubu won laanu

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 10 днів тому +1

    Iyen ya yin lara ewo ojo ti won ti ji dokita Ganiyat gbe ti ijoba Ko se nkan kan si se bi ao se ma ba lo ni yi ti ajinigbe mama ji awon eyan gbe titi gbogbo ilu ma fi di ahoro

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому +1

    Sebi eyin eyan yii gangan, le fi owo ara yin dibo fun Tinubu 🤓 pe kowa fi iya wa....

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому +1

    Eku ilu Nigeria tan ti biwa wadi eru jeje fun wa bayi o..... Ka male sun ninu ile, Ka tun jade lo sise tun Di Wahala fun wa.... Nitori awon ajinigbe. 🤔🤔🤔🤔

  • @ADEXAdeade
    @ADEXAdeade 9 днів тому

    Eku ise ilu sir edumare ama funyin seooo

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому

    Oloriburuku lomo kunrin yio! Omokekere ji eyan gbe!!!! Ibanuje toma pa awon obi pelu awon Omo iya pata ...

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому

    Oloriburuku ni gbogbo awon oselu wa ni ilu Nigeria pata!!!! E wo bi won se pa awon Omo Ologo loju yii , Awon Ajinigbe eri kankan se sin...

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 10 днів тому

    Sebi ijoba so pe Ki won ma San owo itusile fun awon ajinigbe mo kin ni won se si oro na won kan ma paro fun ara ilu

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 9 днів тому

    Awon oloriburuku ole, apayan tan ti da e joo iku e pa won danu....

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 10 днів тому

    Igbese wo ni baba se nigba to wa nbe e meji Sa ni o lo se ijoba lorile ede yi

    • @ADEXAdeade
      @ADEXAdeade 9 днів тому

      But u can't compare his tenure with this president one lailai