ROGBODIYAN ILẸ HAUSA: WỌN NI WỌN FẸẸ FI ṢỌJA LE TINUBU LỌ NI O

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 10 вер 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

КОМЕНТАРІ • 44

  • @adebayophilip6011
    @adebayophilip6011 27 днів тому +7

    I love Nigeria more than anybody , I love Yoruba lands, I love peace. Let's the president wakeup and brake the price down..
    People are hungry

  • @user-ev3yd7wh3j
    @user-ev3yd7wh3j 27 днів тому +5

    omo Buruku wo ni omo Eni
    ti o nfi Ebi npawa

  • @user-vv3cy4jg4w
    @user-vv3cy4jg4w 27 днів тому +1

    Ti soja bama gba ijoba ti gbogbo Inkan mafi rorun ki soja gba ooo

  • @aladjimoustaphaiguewassiou9576
    @aladjimoustaphaiguewassiou9576 27 днів тому +3

    Ki Tinubu yáa tete pin Naijiria kia

  • @ElishaOlasomi-fx3wx
    @ElishaOlasomi-fx3wx 27 днів тому +2

    Awon Hausa-Fulani le ro wipe awon nikan ni awon ni Nigeria. Ki a pin orileede yi.lo dara.

  • @helenadegoke6922
    @helenadegoke6922 27 днів тому +1

    Omoyin ko sedi bebere loma yo yin, sentimente yen loma yo yin. Ebi niipa monnamonnaku.

  • @FasoroTemitayo
    @FasoroTemitayo 27 днів тому

    ijoba tinubu ijoba ole onimo taara Eni nikan. Olorun yio pa ijoba tinubu run lase eledumare. Amin

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 28 днів тому +5

    Esan ni Tinubu gba pelu iwode
    Tinubu Se be fun awon Kan ri
    Ki Tinubu tete Support Yoruba Nation
    Koje first president ni Ile Yoruba
    Iro ni wipe Soja Fe gba Ijoba
    Sebi awon Omo Yoruba lowa Ni Ile Ise ologun
    Se won o wa gba Ijoba lowo Iran re

    • @banirefatiualao9249
      @banirefatiualao9249 27 днів тому +1

      @@imamabdulrasaq401 iyen gan-an lo fa ti ko se rorun fun awon araabi.
      Egbinyan ki e ma wo oye oro

    • @imamabdulrasaq401
      @imamabdulrasaq401 27 днів тому

      @@banirefatiualao9249
      Olohun ase ni irorun bee

  • @mustaphaodeshina5111
    @mustaphaodeshina5111 27 днів тому

    Kudos to Jọkẹ Amọri and excellent narration by the best news caster . Is amazing how some sets of people can always think about their self. Nigeria belong to all of us!! The tide is turning and changing.

  • @abdulraheemkamilu6555
    @abdulraheemkamilu6555 27 днів тому +1

    Bi iwo ba se daada, Ara Ki yaa ya o, eru ni nba baba onidi bebere

  • @JhonePellon-gx7pk
    @JhonePellon-gx7pk 27 днів тому

    Yes nah
    Ki soja gba ijoba
    Abi
    Ebi apaa fee ku yi po
    Emi gan omo yooba ni mi

  • @omoshewayinka2581
    @omoshewayinka2581 27 днів тому

    Oşuwon!!! Ikan to şe lo gba o .. ki Tinubu da owo èpo pada si iye to wa tęlę abi ki won fi ipo president silę 😢

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 27 днів тому +2

    Tinubu should do the needful things are too hard nothing is working in this time APC government

  • @banirefatiualao9249
    @banirefatiualao9249 27 днів тому +2

    Igbayii laaro yin. Sio yin alaroye

    • @loantha2996
      @loantha2996 27 днів тому

      Fake news needs to work on Yoruba fluently

  • @RamatBukola-iw2oh
    @RamatBukola-iw2oh 27 днів тому

    Dey play

  • @user-ns7ot7cw9c
    @user-ns7ot7cw9c 24 дні тому

    Ki won fi le

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 28 днів тому +1

    Alaroye e gbadun rara

  • @princegabriel.975
    @princegabriel.975 26 днів тому

    Unfortunately his days are numbered!!😭😭😜

  • @fatalkehinderaheemat1513
    @fatalkehinderaheemat1513 28 днів тому +1

    Lori iro what my own about that what I want is to do Nigeria battle life wahala ti gbogbo won ni ye

  • @OlarewajuJuliana-u8w
    @OlarewajuJuliana-u8w 27 днів тому

    Let Nigeria divide ➗ into three

  • @user-ns7ot7cw9c
    @user-ns7ot7cw9c 24 дні тому

    Tinubu ika

  • @IfayinkaJohnson-eo7xr
    @IfayinkaJohnson-eo7xr 27 днів тому

    Ebi nipawa se odi igba ti aba ku ton ki atunse to bere oda oo

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii 27 днів тому

    Omo eni should get his just reward.

  • @adecrown4413
    @adecrown4413 27 днів тому

    Alaroye papa elemu meji
    Odale.

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 28 днів тому +2

    Kosi ohun to kan wa pelu Tinubu, ika ni Tinubu, apaniyan,akotileta, arungun, odaju ni Tinubu. Lori iro ni,eni ti ebi npa ko gbo fe,ebi ki won ki oro miran wo. DSS is working for politicians. Gbogbo eni to ba ndamu Mekunnu ni Olorun ma fiya je tomotomo.

  • @anifaloge1166
    @anifaloge1166 26 днів тому

    Orilẹ ede Russia si da ju orilẹ ede amẹrika, UK, France lọ nínu aiye

  • @imoleadini
    @imoleadini 27 днів тому

    Edakun.tawa.omo nijeria.mofi.irobo otito.mole bayi.emimope.biro balo.logun odun.ododo yoba.lesekese.mosimope kangun kangun bikanna.loma.kangunsi.kisoja.nakuku wagba.joba gan.obetter.ju gbogbo.wahalayi.adinku.kosowo.kosi isinmiawon.odaju.lafi.solori bayi.odaju.ole aladanikan je.seradarada.tiwonnseyinada awon.alailanu.emimope yoleyin nitori.animoba bayilo.kolorun.mafebi.pawa o

  • @user-vx2py3yy6z
    @user-vx2py3yy6z 27 днів тому

    Iro lasan ni iroyin yi. Se ilu logbo ni?

  • @fredirckoladapo8057
    @fredirckoladapo8057 27 днів тому +2

    Tinubu those not care about Yoruba

  • @loantha2996
    @loantha2996 27 днів тому

    Iro po

  • @OlasunkanmiFasasi
    @OlasunkanmiFasasi 27 днів тому

    E je tete fa leti ki omi ma teyin wo igbin re leun bo ti le je pe oun to wa o ti ri. Oro epo yen lo fi ba ijoba yen je fun ra rae o ti oju su mio.

  • @oluremiehalaiye2499
    @oluremiehalaiye2499 28 днів тому

    Lori iro ni iriyin o .sugbon oju yin maa ja .se e ko mo pe pharaoh ni tinubu .eyin oloriburuku omo ale yoruba maacto mo pe tinubu lo kan lati pari aye gbogbo yin sewon ati febi run aye yin .

  • @kemoblunsky3794
    @kemoblunsky3794 28 днів тому

    Tell bola to do the needful, awon omo yoruba gan ko gbadun bola, bola Tinubu should take care of his own just like buhari then, yoruba na ma dide si awon to fe le danu, bibeko?....awo lo ni yen, SMH

  • @topeadeyemo576
    @topeadeyemo576 27 днів тому

    Alaroye opuro no yin o. Jawo kuro ninu iro pipa. Ba ❤tinubu soro ki o se ijoba daadaa. Empty propaganda

  • @fredirckoladapo8057
    @fredirckoladapo8057 27 днів тому +1

    This agbagba are lier

  • @adesinawasiu7993
    @adesinawasiu7993 27 днів тому +1

    Russia is good country very good Putin

    • @adecrown4413
      @adecrown4413 27 днів тому +1

      When are you going to Russia or how many of your family are currently living there?