Glory be to God . This is a significant change and development in preparation for our Yoruba Nation. God wants everything to be set before declaring the new Nation. Omo oko Yoruba atata adura wa ti ngba ki a ma dupe lowo Olorun ati Eng , Seyi Makinde fun gbogbo akitiyan won lati tun ipile Oyo se . Awon Alale yoo ba wa se laseyori amin
Ole kan na ni e, bi ti makinde, ona ko dara, ko si ina, ko si ile iwe fun awon odo, ile ise kan kosi fun awon ara ilu, olee ojelu, fe fi papa ofurufu ko owo ilu si inu apo re.. Alaroye ayelujara, owo ti won fun e ma to tan...
Ofo ni e ma shee, gbogbo enikeni ti o ba npe ile yoruba mo ile Nigeria, nitoripe gbogbo yin e emo wipe ile yoruba ti jade kuro ni inun Nigeria. Orile ede tiwa tiwa DEMOCRATIC REPUBLIC OF YORUBA ko ni inkan kan shee pelu Nigeria..
Glory be to God . This is a significant change and development in preparation for our Yoruba Nation.
God wants everything to be set before declaring the new Nation.
Omo oko Yoruba atata adura wa ti ngba ki a ma dupe lowo Olorun ati Eng , Seyi Makinde fun gbogbo akitiyan won lati tun ipile Oyo se .
Awon Alale yoo ba wa se laseyori amin
Aku ori ire ooo
Allhamdulilah
God bless My president.
Alhamdulilaahi robilliaallamin
That's good news 🎉
Ope ooooo
Akuorire ooo
Adupe ooo fun olohun
Yoruba nation we move 🎉🎉🎉
IROHIN AYO LETI WA O MA GBO TITI LAILAI. PRESIDENT TINUBU, GOMINA MAKINDE, A KU ORIRE, ARA RE LA O FI JE IGBADUN RE O! AMIN 🙏 🙏 🙏
A ku oriire ooooo
Misplaced priorities, pls fix the roads, electricity, and necessary amenities for the people of Oyo.
Sele n tan yin owo Yoruba naa ni e maa nan si be fun wa
Oluwa seun o ,a ku orire oooooooo
Ìròyìn ayọ gbáà ni, kìíse f'ọmọ Ibadan nikan sugbon gbogbo ilẹ yoruba lápapò
Iroyin iya ti o ma je yin de oju ami niyen fun yin, E ma fi owo ti o dunyin si abe aso.
@@alabaadejumo535 ọwọ wo lodun yín o
That is a great idea God bless odudua
Ole kan na ni e, bi ti makinde, ona ko dara, ko si ina, ko si ile iwe fun awon odo, ile ise kan kosi fun awon ara ilu, olee ojelu, fe fi papa ofurufu ko owo ilu si inu apo re.. Alaroye ayelujara, owo ti won fun e ma to tan...
Titi ilu ko dara papako ofurufu lo kan Ebi ni npa Aja asinwin ku
Ofo ni e ma shee, gbogbo enikeni ti o ba npe ile yoruba mo ile Nigeria, nitoripe gbogbo yin e emo wipe ile yoruba ti jade kuro ni inun Nigeria. Orile ede tiwa tiwa DEMOCRATIC REPUBLIC OF YORUBA ko ni inkan kan shee pelu Nigeria..
Katikati, kinni Airport fe se fun economy Oyo State.
Seyi sa Kan nwa ona tiyofi maa ji owo ntie ni. Eseun.