EMI NI MI O JẸ KI ABACHA PA ỌBASANJỌ, EYI LOHUN TI MO ṢE-GOWON

Поділитися
Вставка
  • Опубліковано 11 гру 2024

КОМЕНТАРІ • 19

  • @labakeowolabi2828
    @labakeowolabi2828 8 днів тому +1

    Òun sì lajú sílè ó jẹ́kí wọ́n pa Bola Ige... Thanks to general Gowon.

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 8 днів тому

    You have done well

  • @BEAUTIFULQUEEN-n3l
    @BEAUTIFULQUEEN-n3l 9 днів тому

    ORUKO RERE SAN JU , WURA ATI FADAKA
    OGAGUN GOWON KI OLODUMARE KO FUN NI EMI GUNGUN SI AMIN 🙏

  • @victoriaadebayo6446
    @victoriaadebayo6446 8 днів тому

    E seun Gowon ti e bawa ran OBJ leti bi iku se ye lori re. E jowo kini gbogbo yin nse bayi lori bi se npa iran ti e ti se ijoba le lori lati da itaje sile duro. Se e mo iye emi to ti sofo danu ni ipinle ti e ti nse ayeye yi, opolopo idile lo ti wa 😢ninu ibanuje ayeraye ni ipinle yen ati gbogbo orilede yi ni apapo. Idajo mbe.

  • @sundayemmanuel703
    @sundayemmanuel703 9 днів тому

    THANKS

  • @ayenia2736
    @ayenia2736 9 днів тому

    Olorun ni ko pa Obasanjo. And the north thought he was going to be under their control should he got back in power

  • @OmidijiOdunayo
    @OmidijiOdunayo 9 днів тому +1

    @ Emimimo Lo Lo Gowon, Dajudaju Iwa Odaju Po Ni Orile Ede Nigeria, Ki Obj Sa Ma Dupe Fun Eleda Re, Ota Po Larin Ore.. Idajo Eleda Ku Si Dede.. Abacha Ti Ku Eleda Gbe Obj Ga.. Gbogbo Asiri Ikoko Abacha Lo Pada Untu Sita Bayi Sotan Abi Kotan?

    • @oyewole5530
      @oyewole5530 9 днів тому +1

      It wasn't because of Gowon. I remember very well that Obasanjo's late wife Stella put in so much effort by visiting so many emirs to secure her husband's release and wrote so many letters complaining and pleading about the condition in the prison she even expressed concern that he was gradually losing his sight, so I wonder why Gowon should be giving a wrong impression.

  • @abiolabasirutajudeen2407
    @abiolabasirutajudeen2407 9 днів тому

    Why?

  • @haynehifanny8006
    @haynehifanny8006 9 днів тому

    Onirọ npa irọ mọ oku.

  • @goldenroyal7351
    @goldenroyal7351 8 днів тому

    Ara e ni yi tafi gbodo jade ninun NIGERIA kole rowa lorun yoruba nation Now is the best answer Awusa nation Biafra nation now ejo Alaroye sir omo yoruba melo loti ti olori onipo Awusa mon ile ogba ewan tabi totun wa da ejo iku fun Awusa mun Awusa gba sile ejo se oree niye bee awan agba yi gan ikan na ni wan wa fifi ko idamun ba omo yoruba lati fiya buruku je gbogbo wa lapere, ewo baba wa 1 dada Babatunde Idiagban inkan ti babaungida se fun 2 ewo Mko Abiola babaungida yi kan na 3 Muhamed Lawal kwara togbe igbese ire fun iran re ilu ile eya omo yoruba awan Awusa yi na ni 4 ewo Abasha inkan tose fun Obasanjo bikiku yiye 5 baba wa Bola ige 6 etun wo Buhari lori pe ki awa omo yoruba di ero eyin lasoko re kan na wan pe Tolulope arotile 7 wantun fegba emi BABA wa Baunji Akintoye ki Olorun Edumare toko wan yo wan tufe gba emi omo Adeyemon igboho atayese of yoruba land Dr Oloye sunday igboho osha ki Olorun Edumare toko wan yo sibe wangba emi aimonye ni ile yoruba ejo kini aun durose pelu Awan ota wa koye nio sir

  • @AkinlolujohnAyodeji
    @AkinlolujohnAyodeji 7 днів тому

    Lied, if not the death of abacha he would have killed him. Is God not you Gowon.

  • @banirefatiualao9249
    @banirefatiualao9249 9 днів тому

    Ti won o ba ti kuku pa were danu leekan sebi kii ba ti ma wa ma dayeru bayii

    • @kemoblunsky3794
      @kemoblunsky3794 9 днів тому +1

      Kinni iku e da fun e, se oun ni buhari tabi tinubu to n da seria fun yin lowo lowo, during OBASANJO regime, no one went hungry, not innocent but not this bad.

    • @banirefatiualao9249
      @banirefatiualao9249 9 днів тому +1

      @kemoblunsky3794 bi oye se ye yin mo niyen.
      Amukun eru re wo,
      o ni,oke le n wo e wo isale

    • @elizabetholanrewaju6921
      @elizabetholanrewaju6921 9 днів тому

      Aridin nie

    • @banirefatiualao9249
      @banirefatiualao9249 9 днів тому

      @elizabetholanrewaju6921 dakun, je ki a fimo bayii.o seun