EMI AWON ANOBI OLOHUN - Sheikh Abubakri Issah Olayinka Saiful Qudiriyah (Baba Ote)
Вставка
- Опубліковано 10 лют 2025
- Subscribe for more updates from My Naija TV.
EMI AWON ANOBI OLOHUN - Sheikh Abubakri Issah Olayinka Saiful Qudiriyah (Baba Ote)
#mynaijatv #babaote #anobi
Olohun ko se alekun ike ati anu fun gbogbo awon agbalagba ti won tilo, ki o se alekun emi gigun, alafia, anu fun awon obi ati Alfa wa ti won wa laye, Aamin.
Ki Olohun wo ola awon Alfa ati Obi wa, ki o se alekun emi gigun, alafia, IMO, ogbon, oye, anu , gbigba adua, ati iyonu Olohun fun Alfa Issa Abubakri Otte.
Aamin
We are all proud of you ( faari gbogbo awa odo ati omo Ilorin )
Baba, ote inu mi dun pupo toripe mo (complane) si last video yin , e si ti (rectify) re, emiyin agun, ninu alafia ati owo, insha allahu, amin. its (me)....