Hummmm 😊😊😊😊 Oni agbara oooooo Oloriburuku eranko,eranko ni now Toba pa gbogbo omo ilu e tan o de ma joba lori awon eranko ati koriko Gbogbo eyin alabosi,elenini,eletanu,ninu Aye,mo fi bu lagbara olorun, orun bayin wi lase baba ati omo ati olorun emi mimo,
E n fi ejo ika sunka ni Gbogbo awon ti e n pe yii ti won je alagbara ni orilede Nigeria yii na ni odale,o ni wa buruku,a pomo lomo lekun jaye,awon naa ni won wa nidi corruption orilede Nigeria abi ki olorun gba wa lowo awon alagbara Aye Aye
Oba digbolugi leleyi,awon Alale lo fedi ibi ti o nse sita, awon were to duro ti nse Amin,o ye ki won fi Olopa ko gbogbo awon to duro ti, gbogbo Omo Yoruba atata,e dude si Oro yi💪💪💪💪
This is one of the wicked Obas in Yoruba Land. This Kabiyesi must be dethroned ASAP and his touts must be arrested and prosecuted. This is wickedness now!
YEYE DARA EYI NBE ENI KOSI NKAN OBA WE EGUN WE EPE MA KO IWO BABA YI YO ATO OMO ATAYA ATI IWO BABA EPE YI KONI SISE LORI EYIN ATI EBI YIN NI ASE EDUMARE AMIN YORUBA NATION NO GOING BACK
Yeye dara e ku ise opolo loruko jesu e o ma mo se loju gbogbo araye Amin Amin Amin loruko jesu yoruba nation no going back ire o ire ka un ka fun emi ati eyin naa
Eyin Olopa Nigeria kabiyesi so pe owo ohun ni gbogbo yin wa e ba wa gbe isi se lori Kabiyesi yi ni kiakia oju ko ni ti eyin agbofinro Gomina Dapo Abiodun o do wo yin lo ri oro Kabiyesi yi ko gbodo lo bee Kabiyesi so pe ohun yo paa ohun a si gbe sin, odidi oba ilu, o ga ooo. Gbogbo epe to se iwo Kabiyesi ori re ni gbogbo re ma da le ni ase Edumare.
This so kabiyesi needs to be investigated by the government and brought to book, so that it will serve as a deterrent to other Oba. He's nothing but a local champion.
Haaaaa,.oma wa ga ooo. Kabiyesi ayé iwọ ti gbagbe kabiyesi ọba awọn ọba, Ọba to ju gbogbo ọba ayé lọ. Ọba tó pa sanni abasha lai lo kondo tàbí kumọn. Ọba tí kìí leni koto mú ni, oduro de ọ lẹsẹ ogbeji.
Awon oba digbolugi, awon oba thug, awon oba bii Rashidi oluwo abeseekubiojo. Eleyi naan nhuwa bi eniti o ti mun nkan. Aamope ijoba ti n hire awon olopa lati odo oba ifo o. Eyin olopa ogun state e bawa dasi o.
We need to have background checking before selecting people into positions in Ogun State and Nigeria …. This is disturbing and children all over the world are afraid coming back to Nigeria.
The respect and the recognition that we accord the Obas and the Kabiyesis is making them equate themselves with God. This Oba that publicly dehumanized his subject deserves an in-depth investigation to curb future abuses. On the social media platform, he claimed to have the entire Nigeria Police force at his command. This assertion is very scary in that he can use any division of the law enforcement agencies to achieve the darkest of his intentions. Any subject, be it this victim or any other person, would disappear without a trace. How many had been victims before? Besides, he acknowledged that he installed a king in the middle of the night without the knowledge of the Chairman of the Local Government or the Governor. Who granted this king with animalistic tendencies so much power to become such an untameable terror? Human Rights organizations should stand up for this victim to conduct an investigation so as to curb future abuses and oppression. It's not going to be over until we say it's over.
SI GBOGBO OBA NILE YORUBA, ONIBITIKOYE KA BA AWON OBA ILE YORUBA, NIPA IRINSI, NIPA ORO ENU SISO, NIPA IWA ATI ISE. GBOGBO EYI NI OBA SEMIU OLAWALE OGUNJOBI OBA ORILE IFO , OGUN-STATE YI SAFOJUDI SI
The government should take steps, please,on this issue. This is a bully. So annoying no matter what, the king should be patient enough, you ve your own family too. May d Lord forgive you. You're not a good leader to emulate from. Awon lobaloba ko yin si , abiyamo o ki sepe. Kilode. Ogun state government pls we call for justice before this man killed the whole pple of ifo. God bless 🙌
Iru eranko yi ko ye Latin enia .Gbogbo Epe yi ori ara re lomafi gbe loruko Jesu.Ki ogbeni yen sunmo Olorun re dada Sebi Ifon owo ni ki is Ogun state Esu ni Obama yen. Ejowo eran okunrin yen lowo oooo oyè ki Ijoba lo ye kabiyesi yio
Lati ilewa ni mo ti soro lori gbogbo awon kabiyesi wa,wipe aso lo bo were awon,awon ti o duro ti were oba yi,gbogbo won lo ye lati fi oju ba ile ejo.ire o
Shishe shishe tóba ewurè to fin gun iya é ti ba Oba alaye bajè yii, governor Ogun state does not like this kind of behaviour because our governor is also a Prince
I AM SORRY FOR THE MISTAKE....IT'S IFO AFTER SANGO- OTA....NOT IFON ...THANKS
Yes oropo ni , ti oro ba ti kanilara
Hummmm 😊😊😊😊
Oni agbara oooooo
Oloriburuku eranko,eranko ni now
Toba pa gbogbo omo ilu e tan o de ma joba lori awon eranko ati koriko
Gbogbo eyin alabosi,elenini,eletanu,ninu Aye,mo fi bu lagbara olorun, orun bayin wi lase baba ati omo ati olorun emi mimo,
E n fi ejo ika sunka ni
Gbogbo awon ti e n pe yii ti won je alagbara ni orilede Nigeria yii na ni odale,o ni wa buruku,a pomo lomo lekun jaye,awon naa ni won wa nidi corruption orilede Nigeria abi ki olorun gba wa lowo awon alagbara Aye Aye
Oba digbolugi leleyi,awon Alale lo fedi ibi ti o nse sita, awon were to duro ti nse Amin,o ye ki won fi Olopa ko gbogbo awon to duro ti, gbogbo Omo Yoruba atata,e dude si Oro yi💪💪💪💪
This is one of the wicked Obas in Yoruba Land.
This Kabiyesi must be dethroned ASAP and his touts must be arrested and prosecuted. This is wickedness now!
Ogun state govt shd detrone him immediately
The police shd also arrest him because he said he owns Nigeria police
All the curses will go back to the kabiyesi and his children even up to the fourth generation, in 100% in the mighty name of Jesus Christ, Amen 🙏🙏🙏🙏🙏
Amin asentedumare
Amen 🙏 ijn
Amen IJMN
The curses hv bn fighting him
YEYE DARA EYI NBE ENI KOSI NKAN OBA WE EGUN WE EPE MA KO IWO BABA YI YO ATO OMO ATAYA ATI IWO BABA EPE YI KONI SISE LORI EYIN ATI EBI YIN NI ASE EDUMARE AMIN YORUBA NATION NO GOING BACK
Baale oloru, a'm hearing this for the first time in my entire life 💔 that's illegal now
Yeyedara , the dogged freedom fighter, I love and respect you.
Yeye dara e ku ise opolo loruko jesu e o ma mo se loju gbogbo araye Amin Amin Amin loruko jesu yoruba nation no going back ire o ire ka un ka fun emi ati eyin naa
Eyin Olopa Nigeria kabiyesi so pe owo ohun ni gbogbo yin wa e ba wa gbe isi se lori Kabiyesi yi ni kiakia oju ko ni ti eyin agbofinro
Gomina Dapo Abiodun o do wo yin lo ri oro Kabiyesi yi ko gbodo lo bee
Kabiyesi so pe ohun yo paa ohun a si gbe sin, odidi oba ilu, o ga ooo.
Gbogbo epe to se iwo Kabiyesi ori re ni gbogbo re ma da le ni ase Edumare.
He said he owns Naija police, this is so shameful
Oloribu oba elepe gbogbo epe toshe komon jetiee amen
Okay IFO awon OBA yahoo mujemuje olorun OBA oke ma mu yin ooo
We want our nation yoruba nation lafe kiakia
They should dethrone oba radarada yi
This Oba needs to be arrested for verbal harassment and physical assault. He shouldn’t go unpunished.
Not ifon but ifo, oloriburuku oba were.
Yeye Dara , that’s the best title for that Kabiasi. ❤👍
This so kabiyesi needs to be investigated by the government and brought to book, so that it will serve as a deterrent to other Oba. He's nothing but a local champion.
Oba ofo oba adanu oba yeye oba radarada Omo ale Fulani ni
Epe yi po ju ooo
Kini arakunrin yi le se ti kabiyesi fi sepe kabitikabiti yi fun u???
YeyeDara eku eto,ifo,orile ifo ni ki ise ifo
This Kabiyesi must be dethroned immediately.Ogun state Governor must take action on him.
Haaaaa,.oma wa ga ooo. Kabiyesi ayé iwọ ti gbagbe kabiyesi ọba awọn ọba, Ọba to ju gbogbo ọba ayé lọ. Ọba tó pa sanni abasha lai lo kondo tàbí kumọn. Ọba tí kìí leni koto mú ni, oduro de ọ lẹsẹ ogbeji.
Is oba to ju oba lo that expose him
Yeye Dara up to you keep on doing the good job.
Awon oba tog, oba ton bora nonsense.
Awon political Obas ta ma get rid of niyi. These Oba should be dethroned.
Yeyedara kowe ko ko ko ❤❤❤❤❤❤❤
Awon oba digbolugi, awon oba thug, awon oba bii Rashidi oluwo abeseekubiojo. Eleyi naan nhuwa bi eniti o ti mun nkan. Aamope ijoba ti n hire awon olopa lati odo oba ifo o. Eyin olopa ogun state e bawa dasi o.
Yoruba Nation no going back, Ẹku iṣẹ takuntakun Yeye Dara
Olori Buruku Oba le leyi oooooo,Oba eleyi ti mu Colorado
Oba of Ifo not Ifon. Ifon is in Ondo State while Ifo is in Ogun State.
Adedoyin family. Sio!!!
This wicked Oba must be dethroned and arrested, including all the touts that he is using to perpetrate his evil acts.
Supported
Iru awọn Ọba to ntà ara ilu wọn sì oko ẹrú fún àwọn òyìnbó nìyẹn. Iru Ọba to ngba owo abẹtẹlẹ lọwọ Satani Sokoto niyi lati da Sharia sí ilẹ Yoruba.
We need to have background checking before selecting people into positions in Ogun State and Nigeria …. This is disturbing and children all over the world are afraid coming back to Nigeria.
The respect and the recognition that we accord the Obas and the Kabiyesis is making them equate themselves with God. This Oba that publicly dehumanized his subject deserves an in-depth investigation to curb future abuses. On the social media platform, he claimed to have the entire Nigeria Police force at his command. This assertion is very scary in that he can use any division of the law enforcement agencies to achieve the darkest of his intentions. Any subject, be it this victim or any other person, would disappear without a trace. How many had been victims before? Besides, he acknowledged that he installed a king in the middle of the night without the knowledge of the Chairman of the Local Government or the Governor. Who granted this king with animalistic tendencies so much power to become such an untameable terror? Human Rights organizations should stand up for this victim to conduct an investigation so as to curb future abuses and oppression. It's not going to be over until we say it's over.
Kabiyesi ika, ti ko ni rori, awon ti won ba ile Yoruba je niwon yi. Olorun Oba a gba wa lowo awon onika.
Emi Olorun da Ninu oba yi hahaha
Oye ki won dana sun ori ibi tonjoko si tofinpe ara re ni oba, Ota omo yoruba ni eleyi oo Ki se oba rara
The Ogun state public prosecutor should take up this matter.
ỌLỌRUN OLÙGBÀLÀ BUKÚN ORILE-EDE YORÙBÁ EMI ATI ÌDÍLÉ MI PRINCE 1 ÀṢẸ EDUMARÉ ❤❤❤
Awon oba were ti o ye ki won le laafin niyi, o sepe fun Omo ilu ni gbangba,
Oba adanu ofoni obayen mase
OLORIBUKU OBA, OLOPA NIGERIA MAA TO MUE TIMOLE, AWON OMO E MA YIYA E, ESAN MAA KE
If this Oba and his kinds in Yoruba land should have unfettered power, may our land not be doomed. This is an eye opener
Yoruba Nation nikan soso lona abayo fun gbogbo wahala yi oooo Yeyedara KOWEEE TV. Ki Olorun ELEDUMARE bawa gba ile wa fun wa oooo.
OBA elepe apayan haaa oro yii ni agbara ooo
Walaai kose Kabiesi gidi Rara atipe Eleyi o Kise Oba Rara
Obakoba wo niyen
Oba ifo ni ogun state
Awon Fulanis ni Oba awon Kabiyesi yi, oro awon Oba yi sun mi o
Walai kabiesi nkan nkan oni asè lenu ta ni jè kabiesi n'iwaju Allah
Oba di olorun oba ni ohun ko gbebe.gbogbo epe ti oba yen se ori re ni o malo otunna baba yen oba yen ma sofo pelu iya tio fije okunrin yen.
Yeye Dara ese gan ni eku ise
Ifo ni oruko ilu ye kii se Ifon
Eleyi jomi loju gidi ni ❤❤
Awon oba ofo, oba eleribu.
Awon oba ofo awon oba adan olorun ti gba agbara lowo oba eleyi
God of merciful. God is great and our God is slow to anger. Hummmm O ga o
Oba radarada epeyen mapada sodoreni
E ku eto o 💗💗💓
Yeye e ku ise ilu ❤kudos
oju ti ni ...too bad. Oba onrin leba titi
Yeye dara otise tipe oni kosi ohun ti olopa ilu yi se fun oooo
SI GBOGBO OBA NILE YORUBA, ONIBITIKOYE KA BA AWON OBA ILE YORUBA, NIPA IRINSI, NIPA ORO ENU SISO, NIPA IWA ATI ISE. GBOGBO EYI NI OBA SEMIU OLAWALE OGUNJOBI OBA ORILE IFO , OGUN-STATE YI SAFOJUDI SI
God have mercy on us in Yoruba land is to much
This is appalling, God's judgement upon everyone of them behaving this way. They forgot there's a God above. These all Al curseless curses
Oba ofo Oba adanu iwo nu olohun nu
kiwon roloye gbogbo epetose ori omo re loma dale
Tori e ni inu mi mo ndun ti Fulani ba NSE won mase Fulani ni oko won awon oba radarada agba osi😊
Which King is this
Madan justice hear from him first pls sometimes all this baba under kabiyesi are kings enemy...fro.Swiss
Nibo latun jasi bayio ki olorun sanu
Yeye dara e ku eto ilu ifo new Sango
The government should take steps, please,on this issue. This is a bully. So annoying no matter what, the king should be patient enough, you ve your own family too. May d Lord forgive you. You're not a good leader to emulate from. Awon lobaloba ko yin si , abiyamo o ki sepe. Kilode.
Ogun state government pls we call for justice before this man killed the whole pple of ifo. God bless 🙌
This is barbaric and unjustified. Very wicked nonsense kabiyesi
Oba amugbo,taout,king, gbogbo epe yin je tire ati irandiran
IFO NI KI SE IFON O IFO NINLONA ABEOKUTA
oyeki awon oba man uwabi eranko.tori oloselu lounfi won joba.boseye korinu
Okuta ti won ba so lu ope na ni ope m so pada ,oba na ti fori ara re gbe epe to nse , se Olorun ni
Oba were
Amin ase
Oba ifo and no ifon
Iru eranko yi ko ye Latin enia .Gbogbo Epe yi ori ara re lomafi gbe loruko Jesu.Ki ogbeni yen sunmo Olorun re dada Sebi Ifon owo ni ki is Ogun state Esu ni Obama yen. Ejowo eran okunrin yen lowo oooo oyè ki Ijoba lo ye kabiyesi yio
Lati ilewa ni mo ti soro lori gbogbo awon kabiyesi wa,wipe aso lo bo were awon,awon ti o duro ti were oba yi,gbogbo won lo ye lati fi oju ba ile ejo.ire o
They should arrest the mad guy that slapped him.
Eni fe ran eniyan enikan lewon,ki gbogbo omo Yoruba ran ohun naa ni ewon ko to peju
Is IFO in Ogun state not far from Sango Ota not Ifon.
Haaa kaaa biesi eyi póó eje ebure oo esebi awan Babà seunse oo emaje ota ile Yoruba oo omo Yoruba ni eunse epe fun ye now
Oloshi lawuje oba
Oruko Oba were yi ni "Oba Semiu Ogunjobi" the Oloorile of Orile Ifo. Ogun State
His name is adewale semiu ogunjobi
Yeye Dara....IFO not IFON....IFO Ogun state ni ilu yen wa.
Shishe shishe tóba ewurè to fin gun iya é ti ba Oba alaye bajè yii, governor Ogun state does not like this kind of behaviour because our governor is also a Prince
Awon elei iku won ni Olorun won pelu ikeke iya to ko sorun
Awon eranko onijekuje to ko sodo no ngbe oba iya won leyin
Not Ifon is Ifo
Alale abere lowo won
oloriburuku oba osinwin eniyan
Irufe Oba eleyi je onigberaga. Oba lasan ni eyi. Government ni lati se igbese Lori Oba yi. Eniyan buburu ni. Iwa aburu po lowo re.