Ìsétò/prostati Oníje je re - ohun tí ó ye kí a mò
Вставка
- Опубліковано 8 лют 2025
- Kazeem Abdul - Osise wadi ni ile ise iwadi ijnle ni kikun nipa arun jejere ti Herbert Irving - (Herbert Irving Comprehensive Cancer), ṣalaye nipa apo iseto prositati, pelu bi ati lese ayewo arun jejere prositati, ati igba to o yẹ ki a ba dokita onisegun oyinbo wa sọrọ nipa sise ayewo finifini lori arun jejere iseto/prositati wa.
CORRECT THANKS YOU SIR GOD CONTINUED BLESSED YOU INCLUDING YOUR FAMILY
Thanks for the information sir.
Eko yi dara pupo. E seun fun ise opolo ati iwadi. Owo yin a tun bo ma lo soke.