"Jehovah Jire-Oluwa yio pesè" - Gen. 22:14 1. OLUWA yio pesè Fun gbogbo àíni wa Ẹ ni ko bi a bi Ẹ ni bi a tún la. Egbe: Pesè wa fun awon ẹiyẹ Ma k'ọ̀ọmínú, ma kọ̀ọmínú yio pesè. 2. Oluwa yio pesè lṣẹ rére fún wa Ìgbà rere yio de Ọjà wa yio si tà. Egbe: Pesè wa fun àwọn ẹiyẹ ... 3. Oluwa yio pese Ọ̀pọ̀ ọjà yio de Ẹni nra yio si ri Ẹni nta yio ri ta. Egbe: Pèse wa fun àwọn ẹiyẹ. .. 4. Oluwa yio pesè Àlàáfíà ara Aláìsàn yio dide Ẹni ń ku lọ yio sàn . Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ... 5. Oluwa yio pesè Ẹ̀mi gígùn fún wa Angeli yio sọ wa A ko ni r’ágbakò. Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ... 6. Oluwa yio pesè Tabi, ṣùgbọ́n ko si F'ẹ̀ni to ba gbagbọ . Gbagbọ tọkàntọkàn. Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ... 7. Oluwa yio Pèse Awa maridi ni Ju gbogbo wọ̀nyí lọ Awa yio ba goke. Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ... 8. Oluwa yio Pèse Gbògbo wa yio rirán Aini ko ni si mọ Kedere l'a o mọ́. Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ Ma kọ̀minú, ma kọ̀minú yio pesè. Amin
Thank you Lord
I love this song
Thanks. Super grateful to listen to this again.
Thank you sir for doing this great Yoruba Hymn in a contemporary music style, I love it. The Lord will not cease to amaze you in good ways.
Nice one
Amen
"Jehovah Jire-Oluwa yio pesè"
- Gen. 22:14
1. OLUWA yio pesè
Fun gbogbo àíni wa
Ẹ ni ko bi a bi
Ẹ ni bi a tún la.
Egbe: Pesè wa fun awon ẹiyẹ
Ma k'ọ̀ọmínú, ma kọ̀ọmínú
yio pesè.
2. Oluwa yio pesè
lṣẹ rére fún wa
Ìgbà rere yio de
Ọjà wa yio si tà.
Egbe: Pesè wa fun àwọn ẹiyẹ ...
3. Oluwa yio pese
Ọ̀pọ̀ ọjà yio de
Ẹni nra yio si ri
Ẹni nta yio ri ta.
Egbe: Pèse wa fun àwọn ẹiyẹ. ..
4. Oluwa yio pesè
Àlàáfíà ara
Aláìsàn yio dide
Ẹni ń ku lọ yio sàn .
Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ...
5. Oluwa yio pesè
Ẹ̀mi gígùn fún wa
Angeli yio sọ wa
A ko ni r’ágbakò.
Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ...
6. Oluwa yio pesè
Tabi, ṣùgbọ́n ko si
F'ẹ̀ni to ba gbagbọ .
Gbagbọ tọkàntọkàn.
Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ...
7. Oluwa yio Pèse
Awa maridi ni
Ju gbogbo wọ̀nyí lọ
Awa yio ba goke.
Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ ...
8. Oluwa yio Pèse
Gbògbo wa yio rirán
Aini ko ni si mọ
Kedere l'a o mọ́.
Egbe: Pèse wa fún àwọn ẹiyẹ
Ma kọ̀minú, ma kọ̀minú
yio pesè. Amin
It will be nice to have the lyrics. Yoruba and English